Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,175,522 members, 7,895,191 topics. Date: Saturday, 20 July 2024 at 01:21 AM

Won Ti Kogun Ja Wa Labele - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Won Ti Kogun Ja Wa Labele (201 Views)

Roco Nnadiekwe Aka Ja Rule Shot Dead In Orlu, Imo State (Graphic Photos) / Please What Is The Meaning Of "Won Ti Nto Ara" ? / Nigerian Lawmakers, Police, Judges Most Corrupt, Says TI, N’assembly Kicks (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Won Ti Kogun Ja Wa Labele by Akli09tunt: 3:38am On Jun 12
Gbogbo awon asaju wa(Ile Gusu Naija) na ti pa ku!

Mo ni ase lati ko awon oran yi tori:
1) Akobi Eleda(Oba Oro Eledumare pa lase--Matt 10:26-27.
2) won ti bi mi ninu pelu oro ikilo ti won ko sori nairaland ( If You Are 35years You Should Have Realize These) lehin tan wa gege bi olopa eke si ile mi lojo 2024/6/3.
3) Mo ka lana pe awon fulani ba omo metala je ni ile Igbo, won si pa eniti o fe gba a la. Ibonu mi si hona gan. Mo mo pe won ti n se be--ju be lo gan ni Benue ati agbegbe, sugbon inu bibi mi ru lana tori Eleda na n ru okan mi si.

La koko, arakorin, arabinrin, mo n lati fi lele pe gbogbo rogbodiyan ati iponju to n kolu wa, ko dede wa, tabi tori a ko ni awon asaju rere(gbogbo won ti ku!)--oro Oga Ogo Eledumare ni n sele laye wa! Isele to sele ni ile Igbo(ti ibinu mi fi ru), je ara oro zech 14:2 ton wa si muse laye wa ni isinyi. Nitori na, eyin Ibo,Yoruba, ati eyin iyoku Onibukun, te n tele awon jew gogo, pe awon ni eni yiyan Eleda(tori won ti koro eke sinu bible), e sakiesi!

Emi ti mon soro, omo Egba ni mi, mo si je Eleri Oga Ogo Eledumare ati Akobi won! Awon oro to ti wa si imuse laye mi ni wonni:

1) Jer 30:6--2019 titi doni (ni 2019, 2024/1/15, ati awon mi)
2) Mark 3:21: 2021/7/15
3) Luke 21:12: 2021/6/3, 2022/12/16, 2022/12/18
4) Luke 21:15: 2022/12/16
5) Luke 21:16--2021/7/15, 2022/12/18, 2023/7/12, 2023/1/30 ati bebe lo
6) Micah 4:10,11--2019/1/17 titi doni(o sin lo)
7) Zech 12:2-3--2019 titi doni
cool Isa 29:1,2,3,4,6: iji--aimoye, sugbon: 2020/12/5, 2021/4/30 ati bebe lo;
Imi ile: 2021/5/31, 2021/6/2-4;
iji efufu: 2021/2/2;
iro nla: 2021/3/4; Ara nla: 2021/5/17 ati bebe lo

Omo Egba ni mi, mi o ki i se jew tabi oyinbo kankan, gbogbo awon oro yi (ati awon mi si ti sele)si n sele laye mi! Nitori na, eyin Ibo,Yoruba, ati eyin iyoku Onibukun, te n tele awon jew gogo, pe awon ni eni yiyan Eleda(tori won ti koro eke sinu bible), e sakiesi!

Oro ti mo fe so yi, ki i se ti boya--gbogbo awon asaju wa ti ku! Tinubu(wan ti pa nigba to lo france fun iwosan), gbogbo won ni National Assembly(ni won se se ofinkofin national anthem. Obasanjo, Oni ti Ife,awon gomina Osun, Eko, Ogun, ati bebe lo. Sunday Igboho na. O sa lo si Germany fun abo, sugbon won pa a ni be, won si fi ara won ropo e. Pastor Adeboye (added: 2024/6/20: 23:20) O da miloju pe Oshiomole na ti ku. Awon asaju ile Ibo na ti ku Peter obi, nnamdi kanu, alex otti (added: 2024/6/19: 23:53) -gbogbo asaju Gusu Naija. Awon ota wa na pa won, won si fi ara won ropo won lati se gbogbo ibi tan tin se si wa lati bi 2015. Kii se awon asaju wa nikan. Awon olopa na--won pa won, awon ota wa si lo afose ati juju fi yi awo won pada si awon olori wa, olopa ati gbogbo awon adari wa--baale ilu kekere gan, won ti ropo e!

Ki i se oni ni wan ti n se eyi! Bawo le ro boya won ko awon baba wa lo seru?! Juju ati afose! Won pa awon oba, fi ara won ropo won, se ofin ton so ijiya ese die di lilo si igbekun. Gbogbo awon oba tan sope won kopa ninu tita eru awon baba wa, won kii se awon oba wa! Awon oyinbo to ti lo juju yi ara po si aworan oba na lati fi je ki oja eru ma lore kore!

Lati bi 1440 ni won ti n lo eto yi lori wa! Awon portuguese na koko bere e!

Gbogbo pipa awon olori wa, oro Eze 21:12 lon wa si imuse nipa awon asaju wa, ati awa na.

Awon wo lawon ota wa(awa eni yiyan--Onibukun)loni tan koju ija si wa(zech 12:3b; zech 14:2)

1) Gbogbo awon caucasian( oyinbo)--Gbogbo iru won
2) Awon arab-- Gbogbo iru won
3) Awon mongoloid(chinese, korean, japanese ati bebe lo)--gbogbo iru won.
4) Awon indian --Gbogbo iru won
5) Awon hispanic/latina --Gbogbo iru won
6) Awon fulani --Gbogbo iru won
7) Awon Hausa --Gbogbo iru won
cool Awon Ethiopia ati gbogbo awon ti "iho afrika" --Gbogbo iru won
9) Awon kenya --Gbogbo iru won
10) Awon south africa --Gbogbo iru won
11) Awon senegambia ati awon sahel--Gbogbo iru won
Re: Won Ti Kogun Ja Wa Labele by Akli09tunt: 4:13am On Jun 12
Awon Oro to won to kole ni pa wa Lati Iran keje aye!

Re: Won Ti Kogun Ja Wa Labele by Akli09tunt: 4:16am On Jun 12
Awon Oro ati Iran keje aye!

Re: Won Ti Kogun Ja Wa Labele by helinues: 5:44am On Jun 12

(1) (Reply)

Why Is NLC Not Compelling Abia State To Pay The Old Minimum Wage? / Ondo Poll ‘24: Exodus Hits Ondo APC And SDP As Ajayi Welcomes Decampees To PDP / Kano Gov Orders Demolition Of Bayero’s Palace

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 34
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.