Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,175,526 members, 7,895,193 topics. Date: Saturday, 20 July 2024 at 01:33 AM

E Pa Awon Irugbin Mo - Health - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Health / E Pa Awon Irugbin Mo (70 Views)

Bii Aa See Loo Awon Asiri Kankan / Ise Osole Awon Babami Ayee Igba Nii Tii Won Fii Jehun / Eleyi Ni Awon Asiri Ewe Ati Egbo (2) (3) (4)

(1) (Reply)

E Pa Awon Irugbin Mo by Akli09tunt: 8:33pm On Jun 20
E pa irugbin mo!

Daju daju, won ti koju ija si wa, ni pataki julo nipa ounje wa! Labele nan tin se tele, sugbon gbogbo e ti n tansan ni sinyi.

Imoran temi a gba olukuluku ni wonni:

1)E pa gbogbo irugbin tele pamo kiakia. E ma ra irugbin kankan o--kii soni na n ti koju ija si ogbin wa. Sugbon, e pa irugbin mo lati eyi to tikarare hu lehinkule yin. Eyi ti Oga Ogo Eledumare gangan gbin fun ara won nikan ni ke pamo. eyi to wa loja ko se gbekele!

Te ba ni ile lenkule tabi nibikan logba yin, e je ko hu! ewe ati egbo ma wan be! E je ki efinrin, ewuro, gure, ewedu ati bebelo, e je kan hu fun ra wo! Ke je die ni be, sugbon e ma gbagbe irugbin won--o se pataki pe ke pa won mo tan ba ti yo! Bayi ni e ma gbogun ti awon tan koju ija si yin pelu ounje, tori won mo pe eni ti ko ba je nkan to da, ko le koju aisan.

2) Enikeni to ba ni awon igi eso logba, e pa irugbin e mo! Irugbin agbon, mango, sour sup, pawpaw, moringa ati bebe lo. E pa irugbin won mo! Tori gbogbo nkan lagbaye ti fe di GMO. Asiko "Noa" la wa yi.

3) Te ba ra ounje loja, e ni lokan pe kii se ti Eleda--gbogbo e, ku die ni won ti yi pada. Nitorina, e sora yin fun wobia--e ma se jeun pipo mo! To ba je pe e ma b je abo ondindin LEKAN tele, e so di idameta tabi idamerin gan le kan--ke le fun ara yin aye lati koju ija si ohun buburu ti GMO nse sara

E pa irugbin mo ki e ma se jeun pipo mo!

(1) (Reply)

Make Una Save Natural Seeds! / Meditation Program: Innapeace-the Most Advanced Self-development Method. / Ayurheals Insights: Detailed Baidyanath Product List And Health Benefits

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 10
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.