Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,206,876 members, 7,997,101 topics. Date: Thursday, 07 November 2024 at 10:44 PM

Fxopen's Posts

Nairaland Forum / Fxopen's Profile / Fxopen's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by fxopen(m): 4:45pm On Apr 06, 2016
Ifankaleluya:


fifo bawo....Ika-owo ni a ma fi lu ose yen ooo.
e seun sir, e jowo ti won ba so pe eeyan maa sefa (m m) ki lo tunmosi sir,
Culture / Re: .. by fxopen(m): 5:04pm On Apr 05, 2016
[quote author=Ifankaleluya post=43914838]OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI

Ewe-laali

Eyin adire ororo(do do do) merin

Oga aaye kan

Owo-titun (#500 or 1000)

Igba-olomori

Ose

Oyin

Lofinda bintu meji.

Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(d o do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na.

Pelu Ogo-Olohun yio si ri be.

NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo.

e jowo baba nigbati a ba lu ose yen ni Aarin nje igba naa ko ni fo? bawo ni a o se see
Culture / Re: .. by fxopen(m): 12:14pm On Mar 22, 2016
alhajialhaji:
Ifankaleluya, E jo e fun mi ni ise yi pe ooooo... 070529055775...Alhaji [img][/img]Taofeeq.

e jowo e fun mi ni ise yii pe ooo..oluwolelove@gmail.com
Culture / Re: .. by fxopen(m): 7:19pm On Mar 21, 2016
kadunasouth:

Aseta todaju

Igbin to pinu 3 ewe kasan eru alamo odidi atare kan ao jo papo ao rosibi kan tiaba felo ao bu die nibe ao te ifa obara eka si ao wa pe ofore si ao fi omi gbigbona lo tabi eko gbigbona

Kowe leye aye agbigbo leye ode orun ton bari hihihi amako awon agbagba sanko sanko losode orun, ese oba taye lape obara eka, obara eka bamika Awon otami lese losi ode orun, owo mowo ibiwon lewon lori eru maru ibiwon da siwon lara , ti igbin ba fa ikarahun re atele, gbogbo aburu ti awon ota baro simi komon tele won leyin

e jowo, ofo yen ko ye mi daadaa, koowe l'eye aye agbigbo l'eye ode orun...next word ko ye mi ...TON BARI HIHIHI AMAKO AWON AGBAAGBA SANKO LOSODE ORUN, ESE OBA TAYE LAPE ...... awon to seku ye mi E JOWO KINNI AWON ORO TI MO KO NI LETA GADAGBA NINU APAKAN OFO YII , E JOWO KOO KO YE MI ....THANKS

1 Like

Culture / Re: .. by fxopen(m): 9:39pm On Mar 20, 2016
Ifankaleluya:



@fxopen..!

R u a forex-trader? If you're one, what are d indicators you're using?

Concerning wht you asked. Asiri bibo keekeke ni awon yen now,so ko ni eewo or whteva kankan.

Awon alujon-nu ti n wa owo(money) fun awon eeyan po lode(mi re).

So.....Oloju awon-asiri bibo to le sise(re mi).

Emi kan n woran ni....Nigbati mo ri awon kan ti won post oso-owo olojo-meje to gbona pe ke lo fi isu dandan je.

Kosi wahala kankan ore mi(my 5rnd)!

E seun, ewe a maa je oo, emi o ki n se ferex trader oo, mo kan lo oruko yen gegebi inagije lati wole sori ikanni yii ni, mo moriri idahun yin..
Culture / Re: .. by fxopen(m): 12:34pm On Mar 18, 2016
[quote author=wale259 post=43838886]Baba ifankaleluya,E jo lori ise Asiri bibo yi,mo ni ibere, E JOWO SE KO NI LABURU KANKAN ati wipe se ko ni eewo tabi nkan teeyan yoo maa se losu tabi lodun bii keeyan pa nkan eleje...e jowo daun
Culture / Re: .. by fxopen(m): 12:27pm On Mar 18, 2016
E jowo mo fe beere oro nipa ASEJE OSOLE YII, ewe onitikuti to lale wu,ata ijosi pelu eja Aro. e jowo se osole yii ko ni etutu tabi nkankan teeyan yoo maa se loorekoore, osu tabi odun e jowo mo n fe alaye e seun

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 23
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.