Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,173,526 members, 7,888,684 topics. Date: Saturday, 13 July 2024 at 12:45 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán (3192 Views)
Àwọn Èso Ati Irúgbìn Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Awòrán / Transportation In Yoruba Land (àwọn Ọ̀nà Tí À Ń Gbà Rin Ìrìn Àjò) / Ònkà - The ABC Of Yorùbá Numerals (2) (3) (4)
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply) (Go Down)
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 9:57pm On Nov 09, 2023 |
Adìyẹ Odò — Kiwi 2 Likes 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 10:04pm On Nov 09, 2023 |
Agánrán — Senegal parrot, Green parrot Popular Proverb : 1. Agánrán tó bímọ sílẹ̀ tí kò ní ìkà, ọmọ tirẹ̀ kọ́, ọmọ ẹlòmíràn ni. 3 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 10:18pm On Nov 09, 2023 |
Ìkóódẹ — African Grey parrot 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 7:46am On Nov 10, 2023 |
Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀ — Bulbul Popular saying: 1. O ùn sọ òyìnbó bi Ti Ọ̀pẹ́ẹ̀rẹ̀ 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:25am On Nov 10, 2023 |
Ẹiyẹ Omi — Flamingo
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:25am On Nov 10, 2023 |
Reserved |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:29am On Nov 10, 2023 |
Still reserved |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:30am On Nov 10, 2023 |
Reserved for birds |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:37am On Nov 10, 2023 |
Reserved- |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 8:42am On Nov 10, 2023 |
Reserved |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:06pm On Nov 10, 2023 |
Ìrẹ̀ — Cricket 3 Likes 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:23pm On Nov 10, 2023 |
Ẹ̀fọn/Yànmù-yánmú — Mosquito 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:24pm On Nov 10, 2023 |
Ẹ̀ka/Àkányín — Black Ant 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:25pm On Nov 10, 2023 |
Ìjàlọ — Soldier Ant 1 Like 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:37pm On Nov 10, 2023 |
Èèrà — 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 4:44pm On Nov 10, 2023 |
Kòkòrò Sugar — Well I don't know the precise name for this in Yoruba, I'm trying to make some research if it has a name in Yoruba, and If it doesn't, I'll give it a name! But for now, Let's call it "Kòkòrò Sugar" 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:03pm On Nov 10, 2023 |
Ìdun — Bedbugs 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 5:05pm On Nov 10, 2023 |
Èkùọ́ — Beans weavil Popular Saying: 1. Èkùọ́ L'alábàkú Ẹ̀wà 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 11:48am On Nov 13, 2023 |
Ikán — Termite. Òkìtì Ọ̀gán — Termite Mound I don't know why my post keep getting removed by the Bots, I haven't done anything wrong, Lalasticlala, Myndd44 Seun pleas do something! 1 Like 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by caye(m): 9:05am On Nov 14, 2023 |
Raydos: Ikun n j'ọgẹdẹ, / ikun is eating a banana Ikun n re'di, / Ikun shakes her behind joyfully Ikun o mọ wípé / ikun doesn't know that oun to dun/ what sweetens one nii n pa ni / could end up killing oneself |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by dominique(f): 11:25am On Nov 14, 2023 |
Your hidden posts are now visible, stop spamming front-page topics please 2 Likes |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:32pm On Nov 14, 2023 |
Iná-Orí — Lice
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:48pm On Nov 14, 2023 |
Esunsun/Ilé Esun — Flying termite 1 Like 1 Share
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 12:49pm On Nov 14, 2023 |
Eṣinṣin — Housefly 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Zimri(m): 1:06pm On Nov 14, 2023 |
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:09pm On Nov 14, 2023 |
Agbọ́n — Wasp 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:10pm On Nov 14, 2023 |
Oyin — Bee 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:12pm On Nov 14, 2023 |
Alábọ̀nbọ̀n/Lábọ̀nbọ̀n — Bumblebee 2 Likes
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:21pm On Nov 14, 2023 |
Aáyán — Cockroach 1 Like
|
Re: Àwọn Ẹranko Li Èdè Yorùbá Pẹ̀lú Àwòrán by Raydos: 1:22pm On Nov 14, 2023 |
Labalábá — Butterfly 1 Like
|
(1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (Reply)
13-year-old Girl Stoned To Death / The Concept Of Igbo Kwenu In Igbo Culture / How Do You Think You Can Eradicate Tribalism In African Societies
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 18 |