Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,344 members, 7,978,104 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 07:02 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843592 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (19) (20) (21) (22) (23) (24) (25) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Ade231(m): 12:39pm On Sep 08, 2015 |
sammyjay76:ese pupo baba e ma pe fun wa lola eledua ase,gege bi omo yoruba ito ara wa dara fun iwosan ara,fun apere ale lo fun ti jankariwo ba n ko eyan ni oju ona ti aba fe ji to loru ao fi owo gbe ito wa ao fi boju lemeta ao si iyoku danu ese iba eyin agbalagba o. |
Re: .. by sammyjay76(m): 8:22am On Sep 09, 2015 |
Ejowo gbogbo ile e fun wa ni ogun ti a fi n wo egungun .... Eniti ko ti ju bi omo okandinlogoji 39 ti ko si ni aisan egungun tele, sugbon ti nkan na bere si se bayi, lehin ise die ki gbogbo egungun orikerike ara ma dun ni pe iwora egungun. ejowo eba ni so si. |
Re: .. by tundebadmus(m): 1:17pm On Sep 09, 2015 |
kadunasouth:ejowo baba monilo ogun yi ejowo se ele fun tan mio fise ika rara oo ejowo eyo dare fun mi tan ma kan siyin lori email yin ejowo ki e fun mi ni esi o aboru boye 1 Like |
Re: .. by enigstil(m): 2:51pm On Sep 09, 2015 |
Ejowo gbogbo Ile, iba won agba gba to wa lori ikanni yi, ejowo kini oruko ti wonn pe eiye kowe ni geesi |
Re: .. by oscartee: 11:36pm On Sep 09, 2015 |
aboru aboye sir, e ku agbaale gbogbo eniyan lowo arun gbogbo. e si ku itoni sona nipa sise afihan opolopo ogun lori eto yi. ibeere mi ni wipe bawo ni ao se lo ogun yi ? se lila ni tabi ao po mo ose fun wiwe tabi gbere?................OGUN TI OWU ALANTAKUN BA N KO ENIYAN LARA Oku opolo kan ao ki igi bo lati enu ti yoo wole dada ti yoo ha mon ninu dada ao wa mun ao ma fi ko gbogbo jankariwo inu ile titi afi ni leri ara opolo yen mo ti aba ti se bayen tan ao gbodo fi owo kan mon, ao fi ada ge igi yen mo ao wa fi igi gbe sinu agbada ao jo pelu odidi atare kan sugbon ako gbodo fi owo kan ti oba ti jo tan na... ao wa lo epo obo ti yio kuna daada bi atike, ao wa da mo igba yen ni a to le fowo kan. 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 12:27pm On Sep 10, 2015 |
tundebadmus: Ogun wo lenso koyemi molerepo moti dayin lohun ni |
Re: .. by kadunasouth(m): 1:00pm On Sep 10, 2015 |
Ebe ati Asina awon Agba Eye alapandede ao gun po ma ewe lapalapa funfun ao wa popo ma ose dudu ao wa igba olomori ao wa fi igbin kan si ao wa ko ose yi lelori ao ma buwe pelu kehin kehin tun tun odaju 4 Likes 3 Shares |
Re: .. by tundebadmus(m): 3:14pm On Sep 10, 2015 |
healthFirst:baba ejowo emabi un simi ogun yin gangan ni mofe je kefun mi tan olohun ni mofi beyin tori eyin na tise adeun fun wa pe eni ti obafe ogun yin wipe efun tan alale ni mofe beyin ejowo efun mi tan.moti kan siyin lori email yin eda milo un.ejowo ebami fisi ori email mi (tundebadmus38@yahoo.com)or(tundebadmus82@gmail.com) ma mo reti yio ese gan oluwa aduro ti o 2 Likes |
Re: .. by tundebadmus(m): 3:22pm On Sep 10, 2015 |
kadunasouth:baba moju bayin o mi ori agba fi o ejowo koda bi ese sewa mobere fun kan lowo yin lori email yin esi dami loun motun send mesg si yin etun dami milo un ejowo baba efun mi nikan ti mobere fun lowo yin ejowo |
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 4:59pm On Sep 10, 2015 |
E jowo baba,ti eeyan ba lo nkan aajo si ara ni aaro(morning), ti o ba wa ba iyawo re ni nkan ajosepo ni osan(afternoon),kini ewu ti o wa nibe. |
Re: .. by Nobody: 9:26am On Sep 12, 2015 |
omoaribaba1: E jawo ninu ika sise. Ko sunwon e yiwa pada. Ogun ti a se omo araye lanfani ni ki e mu ni pataki. Imoran ni, e se. |
Re: .. by tiphareth1: 12:32pm On Sep 12, 2015 |
Mo ki yin ninu yara yi o Awon awo so wipe ebo ya osi lagbara ju ogun lo. A nfi towotowo peyin ki e ba wa da si Yara Ebo ya ju ogun lo lori facebook lo wa o. Awon ojogbon awo ti wa nikale lati to wa sona. A tun pe eyin awo na lati wa polowo oja yin nipa titowa sona lori ebo at ipese. Gbogbo eni ti o ba je awo lo ni anfani latipolowo oja to ba wu ati lati fi numba won si ori gbogbo ebo ati ipese ti e ba post. Eyin awo e dakun e ran wa lowo o. orunmila yio ran gbogbo wa lowo o. Ase 1 Like |
Re: .. by Ousmaf(m): 3:57pm On Sep 13, 2015 |
Aboru boye o ise a ma je o e jowo kini ma fa to fi je wipe ti mba sise fun eyan a ma je ama ti mba se fun ara mi mi kii ri ami e joo e fun mi lesi re oluwa yio pelu wa ase |
Re: .. by Isholex1love: 12:44pm On Sep 14, 2015 |
healthFirst:e jo sir, bawo ni asema lo ogun tio wa ninu aso funfun 1 Like |
Re: .. by Davidifa(m): 11:44pm On Sep 15, 2015 |
E jo iyawo mi ti fi mi sile lo mo fe ko pada wa ba mi,ejo efun mi ni ogun ti mo lese si. A ma dun yise oooo |
Re: .. by Lionhearted: 10:29am On Sep 16, 2015 |
Davidifa: Emu ra si ise yin ki esi wa ojurere Olorun fun aseyori ati oro. Fun rara e ni yio pada wa. |
Re: .. by Davidifa(m): 12:48pm On Sep 16, 2015 |
Mo ti na owo mi fun ju, efum mi ni ogun ta fi pada |
Re: .. by scholes0(m): 1:18pm On Sep 16, 2015 |
walexy30: |
Re: .. by kadunasouth(m): 1:23pm On Sep 16, 2015 |
Ogun ta nfi pe obirin/okunrin to salo pada Adan 1 eye onbe 1 akeke 1 atare 1 ao jo papo pomo ose dudu kosinu igba olomori gbesi nu apo aso fun fun odi wiwe kia kia ni yio de Ofore adan kilori ade obe kilorun atokunbo akeke kinidi aga lagbaja omo lagbaja koma nidi aga komalesun komalewo koma sare pada bowa sodomi NB ise yi wafun obinrin tosalo tabi okunrin tosalo fun iyawo tabi okore tia ko ba jebire yio de larin ojo meje ti kobade ye arare wo iwo koloto odaju 3 Likes 3 Shares |
Re: .. by Davidifa(m): 7:07pm On Sep 16, 2015 |
E se pupo oooo |
Re: .. by Davidifa(m): 7:10pm On Sep 16, 2015 |
E jo ta loni afose ti ale lo fi ba maga soro ko fun mi 1 Like |
Re: .. by Mediji: 10:09pm On Sep 16, 2015 |
Eku Dede akoko yio.Ejowo gbogbo eyin agba'gba omo yoruba kini Ogun staphlococcus. |
Re: .. by Davidifa(m): 8:31pm On Sep 17, 2015 |
Ejo kilo je isu dandan ati kolobo kekere |
Re: .. by Nobody: 2:31am On Sep 19, 2015 |
Peki ni mo ko, Yaba ni mo ya, D'Ifa fun Agboniregun nijo ti baba nlo si ode Awo Olodumerindinlogun, Orita meta Oja-Ejigbomekun ni Baba ti gbe pade Arugbobinrin t'oun takisa lorun; Sebi ore Orunmila se Eleye ana lo so Barapetu di Olola ayeraye... Ifa dakun mo di mi loju pe Olore mi l'abinrun O, Ase. |
Re: .. by KEHINDE633(m): 10:57am On Sep 19, 2015 |
MAYEHUN TODAJU awon okete meje. irudi okete meje. ewe ogbo. ewe ogba. ewe abamoda. atare odidi kan jijopo fisin gbere meta isale enu wa OFORE= 2 Likes |
Re: .. by kadunasouth(m): 12:20pm On Sep 19, 2015 |
Ogun iwe ikorira iyere osun, osun pupa, ao gun mose dudu, ao pin sona meta wekan laro losan lale. Ankatif funfun meta lama fise kehin kehin ao lo dasi ori akitan tabati we meteta 2 Likes |
Re: .. by tundebadmus(m): 1:17pm On Sep 19, 2015 |
KEHINDE633:ofore da eje kamo alale ni mofi beyin |
Re: .. by kadunasouth(m): 1:26pm On Sep 19, 2015 |
ẸYỌNU AWỌN AGBA Ifunni ekete kan, egbo akerejupon , ati ewe ajẹọbale, ao jo papọ̀, ao po ma ọṣẹ dudu ao ko sinu igba olomori ao ma fiwẹ leralera. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 7:03pm On Sep 19, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 7:07pm On Sep 19, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 7:25pm On Sep 19, 2015 |
x 2 Likes 1 Share |
(1) (2) (3) ... (19) (20) (21) (22) (23) (24) (25) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 53 |