Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,207,602 members, 7,999,618 topics. Date: Monday, 11 November 2024 at 10:50 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (703417 Views)
OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (384) (Reply) (Go Down)
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 10:06pm On Oct 30, 2015 |
razid:Hmmmmmmm oro na so si ni lenu otun bu iyo si |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 10:08pm On Oct 30, 2015 |
Modath ti wa si ori eto, Midolian, eyin na e wa bawa da si eto yi oo. Ogbeni razid, asiko lati ni oludari eto omo oodua ko ti i to nitori oro oro aje ile naijiriya.... Awon yoruba bo "won ni ebi ki pa inu ki oro mi i wo... ni iwon igba ti ilu o ba ti fararo mi o ni ireti pe a le ri eniyan ti a fa ara re sile lati ja fun eto omo oodua.. Ewo idibo to koja bi awon aladeluwa se di arepiba kale, awon egbe odua people's congress na gba owo, ni won bere isokuso..... |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:09pm On Oct 30, 2015 |
E maa n so Yoruba ni'gba ti n ba ti wa l'ori nl. Ko da o |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:09pm On Oct 30, 2015 |
razid: O ti pe tati n gbo nipa ele yi. eje ka so ooto fun ra wa.ipinle ogun o ni owo lati fi pari iru igbero yii |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:09pm On Oct 30, 2015 |
Laudate |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:10pm On Oct 30, 2015 |
Lol see them coming in after the match |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by delpee(f): 10:10pm On Oct 30, 2015 |
E Ku igbadun asiko yi. O dara pupo lati maa so ede abinibi wa. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:10pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo: Bawo lo se moh? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:11pm On Oct 30, 2015 |
Ilekeh:
|
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 10:13pm On Oct 30, 2015 |
Musiwa419:E seun e jana. Ipinya to waye lati ara egbe oselu won je lara nnkan ti yoo fa ti ise naa fi wole. Ti e ko ba gbagbe, Odun 2009 ni Mimiko gba ijoba lowo Agagu labe egbe Labour ti igbakeji re ni ipinle Ogun si n be ni PDP. Lati ara bi awon mejeeji kose si ni egbe oselu kanna, ko fee si ajose to dan moran laarin won. Nigba ti Gbenga Daniel kuro lori oye ni 2011 ti ijoba bo si owo Amosun labe asia ACN, aisedeede tun tesiwaju nitori wipe Mimiko ti n fa sehin nipa ibasepo re pelu awon gomina ilu Yoruba yo ku nitori aawo to sele laarin ohun ati Tinubu. Nnkan ti mo mo ni wipe nitori Mimiko ohun ni eto DAWN ko se ni aseyori nitori wipe kosi bi won se fe yo owo Ondo kuro lawo. 2 Likes |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:13pm On Oct 30, 2015 |
modath:Present! I no too hear yoruba o! I can see yoruba everywhere on this thread |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:14pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo: Ki Olorun dele fun awon eni ire. Ni gba ti awon agbagba Ile Yoruba bi Pa Abraham Adesanya fi owo le Amojuero Funsho William lejika lati gba fun Bola Tinubu ni aye AD, o se ni laanu wipe abamo lo gbehin oro naa. Eyin Omo Odua, oto akoko lati gbena woju awon jegudujera oloselu iwoyi. 2 Likes 2 Shares |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:14pm On Oct 30, 2015 |
I'm really dissapointed though.I was expecting to see a lot of people comment.I know they will come later to give excuses We have those who are also showing up after the match . |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 10:14pm On Oct 30, 2015 |
midolian: Ere abi awada? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:15pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo: Omo Ekiti n'iya mi. Omo Ekiti ati Ondo ni baba mi. Sugbon, Ekiti ni won ti bi mi ati pe, ibe ni mo dagba si. Mo ti so gbogbo eleyi fun e tele nau |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:15pm On Oct 30, 2015 |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:16pm On Oct 30, 2015 |
Firefire: Oro nla le so yi.ki olorun ko ko wa yo |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 10:17pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo:The only person suitable for this is the pillar of arts and culture in Africa but for his little shady side.He is sagacious if I may use that word.Almost like Awo if not for that little hmmm...I think he has repented.He has Yoruba's leader quality if I must say... |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:17pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo: You guys aren't arranging this properly. Mii moh igba ti e ma so Yoruba. Let's make it the same time everyday. Mo maa n wa lori computer lati code ni gbogbo igba ti n ba wa ni ile-iwe, maa le wa nibi nigba ti e ba ti n so ede Yoruba. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:17pm On Oct 30, 2015 |
Ilekeh: Oo so nkankanfun mi tele oo.mo sese n gbo ni sin ni ooo |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 10:19pm On Oct 30, 2015 |
Ilekeh: aunty, e ki i se Ekiti mo ni? ki lo tun sele bayi? tele, Hausa le pe ara yin, o tun ti da Ondo lakoko yi, e se kuku claim Eko? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by zimoni(f): 10:19pm On Oct 30, 2015 |
itstpia8: Rara. In the sentence, he was referring to a comment made by someone on a 'thread'. Ire ooooooo. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:20pm On Oct 30, 2015 |
Firefire:lol..I saw you viewing. I was expecting your mention. I am Nupe by tribe. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:20pm On Oct 30, 2015 |
Ilekeh: We already agreed its 9pm-10pm Nigerian time.You were probably viewing as a guest. stop lyyiiing
|
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by midolian(m): 10:21pm On Oct 30, 2015 |
modath:lol..I mean it o! I understand when you speak and write though..to an extent |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:21pm On Oct 30, 2015 |
Aareonakakanfo: lmaoooo...... rara, mo n sise lowo. Igba wo ni yen? Se o da oruko mi? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:22pm On Oct 30, 2015 |
zimoni: He actually meant " ready " hence I corrected him " se'tan or gbaradi " |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:23pm On Oct 30, 2015 |
Ritchiee: Exactly but that's not politics though, that's arts. Politics is a totally different ball game |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 10:25pm On Oct 30, 2015 |
bolabolakemi: This is true and this is why every well-meaning Yoruba person should invest in the Yoruba interest and any legal Yoruba business. We need to do all we can to lift the Yoruba nation up again! |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:25pm On Oct 30, 2015 |
Ilekeh: If i don't mention you, who else will i mention.In fact your name was the first or are you not ilekehd anymore? |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 10:25pm On Oct 30, 2015 |
bolabolakemi: well, they've said you folks should come and dredge/develop Imo river, but you prefer congregating here on this thread and yarning fables. |
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Firefire(m): 10:26pm On Oct 30, 2015 |
midolian: One Nigeria bro, nothing do you. 1 Like 2 Shares |
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (384) (Reply)
Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 56 |