Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,208,291 members, 8,002,166 topics. Date: Thursday, 14 November 2024 at 05:43 AM

Yoruba Commonwealth and Politics - Politics (106) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (704071 Views)

OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (103) (104) (105) (106) (107) (108) (109) ... (384) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by YoruBanger: 9:02pm On Nov 01, 2015
Mo ki gbogbo yin o. E ku ale o. Yoruba mi ko conk to ti eyin Ogbologbo te wa ni'bi. grin Nitori eyi mo toro gafara. Mo kuku n'gbadun gbogbo awon orishirishi ara ti e'nda ni ori ti-re-di yi o. grin Olorun a wa pelu gbogbo wa o. cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:05pm On Nov 01, 2015
shizzy7:
Eleyi gidi gann ooo. Mi ó mo npa é, Sugbon mo ma gbiyanju..... Mo n wo Nigeria - Brazil. O dun bi oyin...

Ilekeh, oya kini itumo ni ede geesi... grin grin

lol omode yii, se emi lo n fi se yeye?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Shymm3x: 9:06pm On Nov 01, 2015
When I posted the Yoruba players in the NFL, I forgot to post this Yoruba son.

Johnson Bademosi



Johnson Bademosi (born July 23, 1990 in Washington, D.C.) is an American football safety and special teamer for the Cleveland Browns of the National Football League. He was signed by the Browns as an undrafted free agent in 2012. He was a member of the football, rugby, and track and field teams at Gonzaga College High School and went on to play college football for Stanford University.

Bademosi was a three-year starter at Cornerback for Stanford. He recorded his first career interception against Washington during the 2010 season. An All-Conference honorable mention at Stanford for his participation in track and field.

Bademosi received the Maurice "Maus" Collins Award for excellence and leadership on and off the football field while in high school. He was a history major while attending Stanford.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:06pm On Nov 01, 2015
Ekale o gbogbo eni to ka tiredi yi.

Se e rope ale se ju ba sen se ni isiyin lo ri oro agbe? Emi ro pe ikan nu ona ta le fi pese ise fun awon odo ipinle wa ni.

Ki le ro si?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:07pm On Nov 01, 2015
.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:07pm On Nov 01, 2015
shizzy7:
Eleyi gidi gann ooo. Mi ó mo npa é, Sugbon mo ma gbiyanju..... Mo n wo Nigeria - Brazil. O dun bi oyin...

Ilekeh, oya kini itumo ni ede geesi... grin grin
Kini a ma se nipa egbon shymex bayi?Won o mo yoruba ka rara ni?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Shymm3x: 9:08pm On Nov 01, 2015
Ritchiee:
Yea...AI is the future.It is highly technical,specialized and grossly divided into subfields which mostly fail to communicate with one another.My man,its field is quite interdisciplinary...

But the money/prospect in the field is crazy.

And everything is moving towards A.I now.

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:08pm On Nov 01, 2015
YoruBanger:
Mo ki gbogbo yin o. E ku ale o. Yoruba mi ko conk to ti eyin Ogbologbo te wa ni'bi. grin Nitori eyi mo toro gafara. Mo kuku n'gbadun gbogbo awon orishirishi ara ti e'nda ni ori ti-re-di yi o. grin Olorun a wa pelu gbogbo wa o. cheesy

E jo, tani olorun? Se eledumare ti awon omo Yoruba?

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:09pm On Nov 01, 2015
Whathaveidone:


Won tun ti da aareonakakanfo mi duro lehin igba to tu mii le.oro yi sumi.Afi ki ma wo yin loku bayii

Se won fe ko so ede yoruba ni?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by YoruBanger: 9:10pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:


E jo, tani olorun? Se eledumare ti awon omo Yoruba?


Ati Olorun, ati Eledunmare, ikokana ni awon mejeji. Nkan ti emi feelgrin niyen.

2 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:10pm On Nov 01, 2015
Shym3x, come and learn Yoruba. Don't run away during Yoruba hour.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:10pm On Nov 01, 2015
Whathaveidone:


Won tun ti da aareonakakanfo mi duro lehin igba to tu mii le.oro yi sumi.Afi ki ma wo yin loku bayii

Again? I am beginning to suspect foul play.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:13pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:

Yo, what should be on the poster?
Yoruba hours...... come and discuss Yoruba politics/development etc in Yoruba language?
Gimme something spicy.

E fun mi ni idahun fun ibeere yii?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Shymm3x: 9:15pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:
Shym3x, come and learn Yoruba. Don't run away during Yoruba hour.

Lol.

I'm learning.

I do learn with Yoruba Bible and I'm picking up a few things from this thread. grin

3 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:16pm On Nov 01, 2015
Mo ranti wipe nigba ti a wa ni ile eko alakobere ni odun gbonhun, ti won ba ti pe oruko wa, gbogbo wa ni a o maa dahun pe "mo wa sir". Nitori idi eyi, nigba ti won ti pe mi pe aago ti lu, emi naa dahun pe "MO WA SIR". E kaale o dede ile. A dara fun dede wa o. A ko ni sanku o. E gbere ke! grin grin grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:20pm On Nov 01, 2015
Shymm3x:


Lol.

I'm learning.

I do learn with Yoruba Bible and I'm picking up a few things from this thread. grin

Write a sentence in yoruba. Just try.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:20pm On Nov 01, 2015
Whathaveidone:

Won tun ti da aareonakakanfo mi duro lehin igba to tu mii le.oro yi sumi.Afi ki ma wo yin loku bayii
O ga o. Boya ki e ye kun oro yin loda mo. O see se ko je wipe nitori wipe e n lo "bold" lo fa. Nnkan ti mo mo nipa "antispam bot" ni wipe o maa n "filter" awon oro ni. O see se ko je wipe o ni awon oro kan ti e maa n lo ti ko te "antispam bot" naa lorun.

Abi ko je wipe e ti gba iyawo re ni. E je wo ko ba le je ki e r'ona lo. grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:22pm On Nov 01, 2015
razid:
Mo ranti wipe nigba ti a wa ni ile eko alakobere ni odun gbonhun, ti won ba ti pe oruko wa, gbogbo wa ni a o maa dahun pe "mo wa sir". Nitori idi eyi, nigba ti won ti pe mi pe aago ti lu, emi naa dahun pe "MO WA SIR". E kaale o dede ile. A dara fun dede wa o. A ko ni sanku o. E gbere ke! grin grin grin

Nile iwe, se won si maa n pe oluko won ni "anti" ati "uncle"?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:23pm On Nov 01, 2015
Aarekonkofo/CableAC/whathaveidone

Se o le gbe poster yen si oju iwe kan?

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:24pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:
.

Looks good wink
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:25pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:

Nile iwe, se won si maa n pe oluko won ni "anti" ati "uncle"?
Beeni. Sugbon l'aye ti wa "mummy" ati "daddy" ni a maa n pe awon oluko wa. Ojo ti pe. grin

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:26pm On Nov 01, 2015
N je a ri eni ti o mo bi a se le fi ami si ori awon oro wa lori ero alantakun?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:26pm On Nov 01, 2015
PrincessJaneDoe:


Looks good wink

l
E seun. E jo, e ba mi fi ila (tone marks) si.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:29pm On Nov 01, 2015
razid:

Beeni. Sugbon l'aye ti wa "mummy" ati "daddy" ni a maa n pe awon oluko wa. Ojo ti pe. grin

Gosh Mii fe ki awon omo mi maa pe oluko won ni daddy/mommy t'abi uncle/aunty.
Nigba ti mo wa ni kekere, nko feran lati maa gbe gbogbo eyan to ju mi lo ni "mommy" ati "daddy". Nitori e, mii ni je ki awon omo mi se iyen. Enikeni ti ko ba feran e, kan fi awon omo mi s'ile.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ilekeh(f): 9:31pm On Nov 01, 2015
Eyin omo Yoruba, ki le ro nipa ile ti won ko pelu biriki?

Kilode ti a le fi ko oru awon ile yii?


Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 9:31pm On Nov 01, 2015
PrincessJaneDoe:


i am the Asinwin of life!!! cheesy cheesy cheesy

hm, I responded to your post civilly, but you choose to reply with vile insults.

you must have had a great upbringing.

at least, you've impressed ileke and your cohorts here with that, not so?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by modath(f): 9:32pm On Nov 01, 2015
Iya aafin modat na ti wo le wa oo, awon omo keekeeke mi ni won dami duro ni iwon ba nitori aun se eto ile iwe ni ola..

Ki ni aun jiroro lelori ? Mi o yo ju lana nitori wipe , anti sp*m bot o joko le ori adape mi.

Anti ilekehd, e ku ise ooo.

Egbon aareonakakanfo , eku ise , iwaju iwaju ni awa yoruba ma ma a lo .. Awon Romanis won ma binu wa ko si osa gbeyin ni... cheesy

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Ritchiee: 9:34pm On Nov 01, 2015
Shymm3x:


But the money/prospect in the field is crazy.

And everything is moving towards A.I now.
E MA BINU O,EYING OMOLUABI.MI O FE KI AAYUN SE EGBON SHYMEX LESE NI O...lol.
It is really an old field but just gaining prominence now.It was founded in the summer of 1956.I am sure our yoruba guys are keying into the AI phenomenon.It is a matter of time....
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by razid: 9:35pm On Nov 01, 2015
Ilekeh:


Gosh Mii fe ki awon omo mi maa pe oluko won ni daddy/mommy t'abi uncle/aunty.
Nigba ti mo wa ni kekere, nko feran lati maa gbe gbogbo eyan to ju mi lo ni "mommy" ati "daddy". Nitori e, mii ni je ki awon omo mi se iyen. Enikeni ti ko ba feran e, kan fi awon omo mi s'ile.

Kilo n je be nigba ti wa? Omo naa yoo je egba oju awon obi re a yan. grin E je ki n ranti oluko kan ti o kan mi ni yara kefa Daddy Olusanya ni a pe won. Baba yii ti wa ni ile eko wa lati odun 1969. Nnkan ti o maa n so fun wa ni wipe oun pelu awon ti o ko awon obi wa. Nitori naa, omokomo ti o ba sesi pe ni Misita daran. grin

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by itstpia8: 9:36pm On Nov 01, 2015
Aareonakakanfo:
Finally they unban me,adupe folorun.maybe whathaveidone is what i will start using to call them grin cheesy

when using alternate ids, can you add your original id or whichever moniker is your favorite, to your comments, so others can know it's you.


if folks respond to your moniker without even knowing who it is, ileke and your other attack dogs will start getting worried and cranky because they"ll feel you're chatting with other people. Or you'll start developing wings because you feel someone is responding to your post.

so please add aok or something to your posts when you are not using that id, just for clarity.

thank you.

Not everybody automatically knows when you're posting under various user ids.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by scholes0(m): 9:37pm On Nov 01, 2015
Gbogbo yin, e jowo, e ki mi Kaabo si ori eto.

(1) (2) (3) ... (103) (104) (105) (106) (107) (108) (109) ... (384) (Reply)

Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 36
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.