Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,211,415 members, 8,011,650 topics. Date: Sunday, 24 November 2024 at 10:40 AM

.. - Culture (30) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1847225 Views)

"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (99) (Reply) (Go Down)

Re: .. by kadunasouth(m): 1:11pm On Nov 01, 2015
Ogbe-fun

2 Likes

Re: .. by kadunasouth(m): 1:14pm On Nov 01, 2015
Ifa re ni lokeyi

Bostilo:
Modupe lopolopo sir. E jowo baba ogberi ni mi mio mo biwon se te ifa. Ejowo esanu mi sir. Kini mole se bayi toriwipe ogun promise and fail yi bami ja gidigan ni o

1 Like

Re: .. by Bostilo: 2:27pm On Nov 01, 2015
kadunasouth:

Ifa re ni lokeyi


Ogberi nimi koye mi raara. Esanu mi
Re: .. by omoalade144(m): 8:04pm On Nov 01, 2015
akaale o baba, ejoo kilo nje ajesi adie, atipe kini won pe ni ikobere
Re: .. by omoalade144(m): 8:10pm On Nov 01, 2015
Ewe amaje sir o, ejoo ki lonje ajesi adie,atipe kini onje ikobere.eseun agba yin adale
Re: .. by Nobody: 10:35pm On Nov 01, 2015
Ifa ni;

Mo yó kèsèkèsè
Mo gbàdè borì
Mo yòlè-yòlè
Mo f`èjigbàrà ìlèkè òun okùn borún
Emi ò mó`kan
Emi ò mó`kan
Mo gorí ìlé Olójà
Èsò ilè –Ifè wòn rí mi
Wón n yanso ò ró
Àgbáágbá Ifé wón ri mi
Won n láwúú borún
Òbíbí má bí mí lu igún
Jé kí n gbó
Bí igún tíí gbó
Obibi mà bi mi lu Ákála
Jé kí n dágbá
Gègè bí Ákála
Àgbáágbá wón kíì ró gbáá
Bì ilèkún áásé
Ifá wáá se mí ní Babáláwo
Nitorí bí babáíáwo bá di Babáláwo tán
Wón s ni baárù niwájú ilé
Ifá wáá se mí ní Babáláwo
Nitorí bí babáíáwo bá di Babáláwo tán
Wón à lèsin kúùrù lèyinkúnlé
Ifá wáá se mi ní Babáláwo
Bi Bábáláwo bá di Bábáláwo tán
Wón à Iètalélégbèje aya werewere nílé
Ifá wáá se mi ní Bábáláwo
Bi Bábáláwo bá di Bábáláwo tán
Wón à Iètalélégbèje omo werewere sayè
Ifá jé ki n tó bábá a wón se
Àlóófohún oko
Iwo ni bábá ewera
Ifá je ki n to baba a won se
Òdúsó nìì solojà lawujo Ikín
Ifá je ki n to baba a won se
Àlóófohún oko
Iwo ni baba ewera
Ifá je ki n to baba a won se

4 Likes

Re: .. by Lionhearted: 6:19am On Nov 02, 2015
kadunasouth:
Ifa re ni lokeyi
Mi o ri esi email ti mo fi ranse siyin.
Re: .. by keyguy59(m): 11:35am On Nov 02, 2015
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin
gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan
Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon
tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao
ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji
po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku
mole lorita laro yen otan
MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe
ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe
pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki
opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin
e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese
re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI
OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN
Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe
rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo
ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun
wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso
aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju
ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o
ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere
lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati
ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo
lopolopo
OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari
aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti
obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki
tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja
loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan
ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection
AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko
atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori.
OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo,
odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la.
TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN.
Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao
lopo gbere 11 lori.
ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(coolni
dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o
wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu
igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi
etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa
yibon si wo.
ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti
aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko
ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran
de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona
OGUN ORUKA ANO SUBU.
Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a
ba fi oruka yi na yio subu lese kan na.
Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara
kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko
oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri
si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo
keje ao to ju re.
Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu.
OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji
meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori
eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die,
ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o
ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a
o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi.
OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and
OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi
toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso
funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo
kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao
ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi
we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga
ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki
lagbaja ma sun loni o . ODAJU
Ogun Asma
Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar
oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio
gbadun pelu ogo oloun

3 Likes 1 Share

Re: .. by keyguy59(m): 1:24pm On Nov 02, 2015
bawo bari awo,,,,awo asoro awo....bo gberi bari ogberi ,,,ogberi asoro ogberi......dide mode emi owa subu awo....dide mode emi o wa subu ogberi......to ri bi ado ba wo nu ado,,,ado mejeji arinu ara won......ogberi ko gbodo ri omije lo ju awo....e jo mo fe mo phone number healthfirst.....ewe a ma je ooo
Re: .. by Ousmaf(m): 5:58pm On Nov 02, 2015
keyguy59:
AFOSE ase oka ati odindi atare kan ao Jo papo ao fi sin
gbenre kan si isale ete ao ma fi ahon kan
Okigbe ida ogbe pada sodo eni sawa)ao wa agbon
tobo sile funrare ao da lu lori ao lo efun ati osun po ao
ro sinu agbon yen ao gbe sile di aro kutu ojo keji aoji
po ao gbemu laiti soro si eni keni ao lo la agbon toku
mole lorita laro yen otan
MALU-opolo odidi kan ao fi okun di ese re ao wa ewe
ina esinsin ewe airagba ewe oyin ewe sawerepepe
pelu iyo ao lopo ao fi kun eyin opolo yen ao maki
opolo yen pe "se ofe kuni? maiku, ori unfo e? Edo unrin
e?, aragbigbona ni? Tio ba ti wa ku ao wa tu okun ese
re ao jopo mon ijakariwo ati odidi atare kan ao fi se igbadi tabi tira ti won ba luwa mon ao sowipe "OJO TI
OPOLO BATI KUN OSUN SAWEREPEPE OJO NA NI RORUN
Amudo: imi ewure oriso,imi aguntan oriso,ewe
rekureku. Eso agunmona ao gunpo aofi awo ojiji di mo
ara aba irin ni owo mejeji aofi owu dudu ati funfun
wepo o4 ibiti ewure abaso ewure si ni susi. Ibiti abaso
aguntan si ni susi .rekureku kifo koja oju
ona.agunmona kiraye gun igi re jake ao daruko obirin nasi ao kan mo ara igi abo odaju gan o
ASEJE OWO NLA TODAJU- ewe tanapowo 50, iyere
lopolopo, ao fi se akuku adie je, lepo niyo, ao ge ori ati
ese adie naa ao ri mole ao se aseje naa, ao ri owo
lopolopo
OWO-ao te ifa ejiogbe sile ao pe ofo yi si lori-Oludari
aye loruko ti anpe ifa,ina kaan loruko ti anpe etu,ojo ti
obinrin bati di aya oba ojo naa ni won fi owo tire wo,ki
tomode tagba ma fi owo wo emi lagbaja omo lagbaja
loni,ao koju seyin fi ese osi ta yepe naa.(A le ra nkan
ni owo eniyan ki won ma gba owo,eri daju pe efun won ni owo won)use it for your own protection
AGBELEPOTA: Ori ako alangba1, ao fi osun pa, ao ko
atare9 si lenu,ao jopo ao fi sin gbere mesan si arin ori.
OGUN EYONU AIYE: Odidi ladaripon1, Ewe ewuro oojo,
odidi atare1. aojopo, ao da sinu epo pupa ao ma la.
TI AKIFI RANTI SA OGUN SENIYAN.
Ewe igbagbe eyo atare 7 fun obinrin 9 fun okunrin ao
lopo gbere 11 lori.
ORUKA AYETA:ao ge igi atori mejo(coolni
dogbandogba,oruka irin dudu mejo,awo{skin}o
wawa,odindi atare kan,ao jopo ao ko gbogbore sinu
igo kan ao fi etu die foko mu ao ki oruka kan bowo.Efi
etu die si adie lenu kie ki oruka kan bo lese ki wa
yibon si wo.
ogun ki ole ma wole;ao ge ora ara ewure die ti
aguntan die ati ti elede die sinu fitila kan,ao fi ewe ko
ti won pe ni idariko tabi modesina si ao fi fitila miran
de,ao we lowu dudu ati funfun a o gbeko enu ona
OGUN ORUKA ANO SUBU.
Bo wu ki enia ti tobi to tabi ki agbara re ju ti enikan ti a
ba fi oruka yi na yio subu lese kan na.
Ewe ina gbigbe ao lo pelu alahannahan ao pa bara
kan ni oko [parsa] ao ko egbogi ti alo yi si ao wa ko
oruka irin iye ti aba fe si ao wa osun ti won fi kun ibeji lara ao ko le oruka yi na ao de pa mo bara na ao lo ri
si idi ogede wewe gba ijo meje ao lo ko oruka yi ni ijo
keje ao to ju re.
Lilo re:- ao fi ikan bowo fi na enia yio subu.
OSOLE NLA TODAJU- odidi tagiri mejo a o ge wo si meji
meji ti yo wa je 16, a o ko won sinu isasun pelu ori
eiye akala, olongbo kan, iru woro ti ko ni iyo ko po die,
ati ewe orijin a o jo gbogbo re a o si lo kuna daada a o
ma bu ebu na die si owo osi wa a o si fi oyin gidi po a
o fi lo ni eekan losu o ti di dsame date ta lo la o tun lo ni d following month, odaju baba mi kan lo fun mi.
OTIDE OOOOOO, AMUDO AMUDO AMUDO, tested and
OKAY AMUDO... Ewe ogbo meta, ewe apada meta, odidi oga kan, omi
toromini, Áo jopo ao p month ose, ao ko sinu aso
funfun, ao so ko si ibikan ninu ile (house) ti kogbodo
kan ile, (ground). Tia abafe lo ao bu die ninu ose ye ao
ho si owo, ao daruko obinrin ti a fe lo fun sinu re, ao fi
we owo mejeji. OFO RE.... Ogbo loni kio gbo temi lonni, apada loni kio ma le pa oro mi da, aso alaso ni oga
ngba, ekuin ekekun ni toromini nji sun, ekun mi ni ki
lagbaja ma sun loni o . ODAJU
Ogun Asma
Ikarahun igbin ao lo dada yio kuna ao walo sugar
oni koro eyo meta mon ti yio kuna dada ao mala yio
gbadun pelu ogo oloun
ejoo sir se odindi OLONGBO abi ori re lao lo fun osole nla yen abi bao?

3 Likes 3 Shares

Re: .. by keyguy59(m): 7:57pm On Nov 02, 2015
odindin ologbo ni oooooo .....ko ba je gbigbe...ko sa ti je ologbo
Re: .. by keyguy59(m): 8:22pm On Nov 02, 2015
ikun aboyun to ga ekan si mi........08133500074

Re: .. by Nobody: 9:43pm On Nov 02, 2015
keyguy59:
ikun aboyun to ga ekan si mi........08133500074

ewe ama je funyin on
e jowo baba ogun wo lo le mu ki oko olomokurin to kere tobi?
Re: .. by Nobody: 12:25am On Nov 03, 2015
keyguy59:
ikun aboyun to ga ekan si mi........0813350074

Pls we do not allow phone numbers here. We do no also allow translation of Oogun to English language. Pls take note.

check my signature for my e-mail and e-mail me, i'll send my phone number. Thanks
Re: .. by keyguy59(m): 11:27am On Nov 03, 2015
e ma binu sir....emi ko mo wipe a ki fe number wa sori afefe ooooo........
Re: .. by opeey360(m): 9:22pm On Nov 03, 2015
Ago onile oo
Re: .. by mondaylyno(m): 11:31pm On Nov 03, 2015
Mo need ogun osole
Re: .. by Youceemeri: 11:32pm On Nov 03, 2015
kunleoosha:

ewe ama je funyin on
e jowo baba ogun wo lo le mu ki oko olomokurin to kere tobi?




cc: healthFirst,kadunasouth,keyguy59,
Re: .. by mondaylyno(m): 11:43pm On Nov 03, 2015
Aboru boye oo. mo need ogun egbo adajinaAboru boye oo. mo need ogun egbo adajinaAboru boye oo. mo need ogun egbo adajina
Re: .. by sammyjay76(m): 1:23pm On Nov 04, 2015
GBOGBO ILE NI MO KI O. EJOWO OGUN IBILE HERNIA TO DAJU E BA WA FI SITA .ATI OGUN IBA TYPHOID.
EWE A MA JE O.
Re: .. by hamykaz: 1:53pm On Nov 04, 2015
ewe a maa he o, ejowo kinni WO n pe ni, awure owo agboojo, nitoriwipe omo ile eko giga ni mi, a si to fe wole sugbon kosi agbara fun a won obi mi lati san owo ile iwe mi, ejowo mo ni lo Ogun ti alaanu fi n was eniyan ri, ipari OSU yii ni a maa wole, owo naa si din die ni egberun lona ogorun,#100,000
Re: .. by KolaBELIEVE: 2:45pm On Nov 04, 2015
kadunasouth:
Oshole Oni okan Malu(cow)
Odidi Okan Malu Oju iho meta lowa lara okan
Malu, Ao fi atare sikan,owo towu
wa sikan, Igbo mumu sikan, aowa jo gbogbo re
papo, ao lo ti yio kuna dada ao wa mafi miliki olope lo ebuna die die odaju
ejowo se lararo lama ma lo ni abi ale? Ejowo se koni pa awon omo teyan bi lara lojowaju?

1 Like

Re: .. by absoluteSuccess: 9:07pm On Nov 04, 2015
Mo ki mutumuwa o.

Yoruba bo wonni eti to ba gbo alo, dandan ni ko gbo abo.

Se mo so nipa alicin pride nijosi? Ah, nse ni egbogi naa ngeregejige si lojojumo.

Ori ti yoo dade, inu agogo ide ni tii wa. Ogoro awon tiwon ti lo egbogi mi ni won nkan sara si agbara Olorun to da ewe ati egbo fun kowa.

Arakunrin kan so pe ogun na pelu oun ti o wo ailoyun iyawo ore oun odun meta san, ekeji wipe nkan osu to se fun odun merin di atunri. Emi na dupe temi o, ati beebee lo.

Bayi, oruko egbogi na ti yipada. Marada ni oruko tuntun t'onje. Abija wara ni, kiise akerekoro.

Nkan eni kii di meji kinu bini, mo tun ni asiri kan fun iwulo pupo, o si je oun ti o le je ki eje po daradara ninu fanran isan ara.

Ayunlo ayunbo l'owo nyenu.
Re: .. by keyguy59(m): 11:08am On Nov 05, 2015
"OGUN TI OKO OKUNRIN BAKERE TI YIO FI YO JADE TI YIO
SI TOBI" ao
wa igbin nkan toba bonu, ao ju sinu
omi fun igba die, bi iseju mewa tabi marundogun,ao
yo igbin naa pada, ao
fi sile, tobati yo ori jade funrare, ao fi ada be ori re lekan, ao wa gun po mose dudu, ao mafi fo
gbogbo ara oko wa. oko wa yojade
ti yio si gun dada.

9 Likes 1 Share

Re: .. by Nobody: 4:55am On Nov 06, 2015
healthFirst:
1. OOGUN FUN GBOGBO KOKORO INU EJE

Bi eeyan ba we tan, ti gbogbo ara ba n ja je tabi ti ara ba n ja je ni gbogbo igba tabi ki kokoro wa lara wa gegebi kuruna tabi kokoro eyikeyi. iwadi ijinle awon agbalagba fi ye wa wipe kokoro inu eje lo n fa awon inkan wonyi. Otito Oogun re ni eleyi...

Ao wa Egbo Igi ti Yourba n pe ni Akogun, ao gun po ti yio kunna daada, ao da sinu igo tabi ike, ao da omi osan wewe to po die si.

Lilo Re: Ao ma mu niwon sibi imuko laaro ati lale leyin ounje. Eni ti o ba ni arun Ogbe inu(Ulcer) ko gbudo lo omi osan wewe, ki eni na lo omi lasan.
.
E jowo e ba wa fi ami si ori akogun yii

1 Like

Re: .. by Sobandemojisola: 8:32am On Nov 06, 2015
B
Re: .. by keyguy59(m): 12:49pm On Nov 06, 2015
Ori mi jowo ma je fi owo osi ju we ile baba to bi mi lomo......ta lo so wipe yoruba o ni science....ti gbogbo eniyan mo si ogun.......ti eyinbo ba soro ni pa science ti won pe ni imo ijile......ba kan na ni yoruba pe ti re ni ogun....ti definition je.......osuka oru eru agba....ologbon lo le gbe.....ki awon baba wa laye jowun ana to le pa ewe po wipe ise bayi ni o se....oye ke mo wipe owun na ni won pe ni imo ijinle..........iba olobinkin osanyin.......iba....iba orunmila baba agbonmirekun.....iba awon agbagba to gba ni waju ati ni eyin ti ko je ki oowo...iba ile aboko ye re.....iba agbede meji orun owun aye....mo se iba gunnugun ti jebo isalu aye......mo se ba akala ti je bo i sa lu orun.......bi omo ti tun ba de ileaye agbe ekun wa yin.....iba obo ti je ki ako,o ma da ti nu re sile..... Iba araba nilu remo.......iba ni mo se ema je ko pa mi lare oooo........OGUN WARAPA BO LONA TO DAJU
Re: .. by Youceemeri: 7:40pm On Nov 06, 2015
Aboru bo ye oo, e jowo o ti to osu merin ti iyawo ile me ti se unkan osu keyin lati ijo ti oyun to baje ni arare ni ko ti ri mo ejowo e sa nu mi ki ni mo le lo fun Gbogbo Aye oju o gbodo ti omo awo.



Baba KADUNASOUTH ati baba HEALTHFIRST EJOWO E DA SI IBERE MI
Re: .. by Nobody: 9:21pm On Nov 06, 2015
.
Re: .. by mondaylyno(m): 9:23pm On Nov 06, 2015
Aboru boye oo ejo mo need ogun egbo adajino to daju
Re: .. by ALIUDAVID: 10:01pm On Nov 06, 2015
Eku dede asiko yii, baba efun wa ni (ogun atupa aye) atupa wa ko ni ku o, ati (awo tabi digi aye) ti won fin woni.
mo se iba eyin agbagba ati eyin to ni ile aye.
Re: .. by ALIUDAVID: 6:07pm On Nov 07, 2015
ERO MAGUN (THUNDERBOOT)
Ifun aja, igba eyo atare(200), igba obi pupa(200), igba obi ifin(200).
A o gun po a o sa yio gbe, a o fi ran onde tabi igbadi si idi wa..

Ogun ti obirin ba nse isekuse..
Ewe ewura, ao fi nu oko nigbati a ba ba obinrin na lo po tan, ao wa odindin eko kan, ao gbo ewe ewura yen si omi to mo ti kopo ao yo omi re, ao fi foko mu ati obinrin yen...
Ti obirin yen bati ba okunrin mi lo po yi bi si okunrin yen lara.

1 Like

(1) (2) (3) ... (27) (28) (29) (30) (31) (32) (33) ... (99) (Reply)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 62
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.