Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,200,695 members, 7,975,692 topics. Date: Tuesday, 15 October 2024 at 10:38 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843467 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (36) (37) (38) (39) (40) (41) (42) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Nobody: 3:55pm On Dec 06, 2015 |
WiLdFLame: Ise yi ki se ise eyo kan...o si sowon pupo...e kan si mi lori e-mail...ao le fi ise yi sita lofe rara. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 3:57pm On Dec 06, 2015 |
Aluqman: orisirisi inkan lo le fa...Sugbon, e lo ma lo ise Ebe Agba, lehin re, ke lo se Ajeegun to gara. |
Re: .. by Nobody: 3:59pm On Dec 06, 2015 |
Ifadamilola30: Ewe laa yato si lapalapa...ti n ri picture re, ma post re later. |
Re: .. by OPCNAIRALAND: 4:12pm On Dec 06, 2015 |
healthFirst: Lmao! Esee Alagba, eku oye. Ehhn, emi na a fi se oro so nijo waju. Igba ti mo bari sisi akowe ti o wo kaba to fo s'oke ti gbogbo awe ibadi n'gb afefe.... Ng' o ran leti ihoho omoluabi! Kee pe fun wa o! Ewe a je! |
Re: .. by Lukerz: 4:20pm On Dec 06, 2015 |
Ejowo baba. Agba yin adale. Efun wa ni ogun amudo to daju |
Re: .. by Nobody: 5:05pm On Dec 06, 2015 |
OPCNAIRALAND: Alawada kerikeri ni arakunrin yi o. |
Re: .. by omoalade144(m): 5:47pm On Dec 06, 2015 |
Ese lopolopo, e o ni seku.ejoo se amin oke ni egbo udi yen ni abi amin isale. Ese lopolopo. |
Re: .. by KolaBELIEVE: 6:53pm On Dec 06, 2015 |
kadunasouth:ejowo monile ogun lati ri ise gidi pelu certificate mi. Eranmilowo. Moti laya moti bimo. @ kadunasouth ama juyin se ooooo! |
Re: .. by Nobody: 7:42pm On Dec 06, 2015 |
omoalade144: Ami oke ati isale ...Udi(Re Mi) |
Re: .. by omoalade144(m): 9:01pm On Dec 06, 2015 |
Egbayi baba,yio dara fun yin. |
Re: .. by omoalade144(m): 9:04pm On Dec 06, 2015 |
Egbayi baba!!.Ese modupe. |
Re: .. by Aluqman(m): 9:07pm On Dec 06, 2015 |
healthFirst: eku asale o baba, mo n fe alaye lori egbogi yi daa daa mo fun eni mi kan kosi ri ise re. Mo lero wipe ko se ise na daadaa ni. Iru oruka wo ni ale lo se oruka irin ni abi eyikeyi, ti eyin adie na ba fo nigba ti aba fe yo jade leyin ojo meje se ko bawi. A ma ri yin ba o. |
Re: .. by omoalade144(m): 9:17pm On Dec 06, 2015 |
Emi OMOALADE144 gege bi member lori aaye yi fi asiko yi ki olorii aaye yi ati gbogbo omo egbe patapata lapapo pe aku imurasile odun tuntun, yio ba walayo ati alafia, amin aseeee. 1 Like |
Re: .. by Aluqman(m): 9:20pm On Dec 06, 2015 |
Ekale o baba health first ati baba kadunasouth. E seun wa lopolopo ajinde ara ama je o, ewe asi ma je pelu. Mo ni lo Ogun ti ale fi ta nkan bi dukia ti ani lo re mo ti osi dara gege bi oko, okada, ati bebe lo. Agbe si ita asi gbe FOR SALE le Lori amoo won na in ina ku na. Kini ale se si baba ti won o fi ra daadaa. Eseun o. |
Re: .. by Nobody: 10:17pm On Dec 06, 2015 |
healthFirst: Mo ti email yin sir |
Re: .. by Nobody: 10:48pm On Dec 06, 2015 |
Aluqman: E so fun eni na ko se Eyonu Agba, ko de se Ajeegun...lehin na ko tun Oogun yi se...nitori O daju daada. |
Re: .. by Nobody: 10:49pm On Dec 06, 2015 |
omoalade144: Ami Ase...E seun o. |
Re: .. by aone4(m): 9:13am On Dec 07, 2015 |
kadunasouth:Eseun baba Kaduna alaye ise yi ti yemi, ema binu fun ibere ti moko bere. Ajinde Ara amaje o. |
Re: .. by Nobody: 10:53am On Dec 07, 2015 |
x 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Nobody: 10:57am On Dec 07, 2015 |
x 2 Likes |
Re: .. by Nobody: 10:59am On Dec 07, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by Nobody: 11:12am On Dec 07, 2015 |
x 4 Likes 2 Shares |
Re: .. by Nobody: 11:56am On Dec 07, 2015 |
x 1 Like |
Re: .. by systembayo: 1:14pm On Dec 07, 2015 |
eka son oo ejo eyin awo mo need Ogun ti alantakun ba ko eniyan loju. 1 Like |
Re: .. by Nobody: 2:13pm On Dec 07, 2015 |
systembayo: E lo se Ebe Agba No 105 yen. 2 Likes |
Re: .. by Shomar: 8:05pm On Dec 07, 2015 |
[color=#990000][/color]moseba awon to laye o. Iba baba, iba yeye. Eyin baba wa mejeeji, Baba health ati Baba kaduna. Ko ni su yin, beeni ko ni reyin. E jor sir. Efi EYONUN OLUGBARE tawa lore. Ti eniyan ba wa ni ibi ise ti won fe pin post kan ti yio fi je teyan. E sanu wa. |
Re: .. by Youceemeri: 8:35pm On Dec 07, 2015 |
healthFirst: E FI ESI RANSE SI MI PADA E JOWO |
Re: .. by systembayo: 8:41pm On Dec 07, 2015 |
e seun ooo ewe ama jeoooo |
Re: .. by keyguy59(m): 9:43pm On Dec 07, 2015 |
e jo...eni to ba ni ogun ti omo yahoo fi gbowo lowo client e todaju....orisa oke agbe wa ooo |
Re: .. by jomilojupeace: 10:15pm On Dec 07, 2015 |
hmmm |
Re: .. by Nobody: 10:23pm On Dec 07, 2015 |
x 1 Like 1 Share |
Re: .. by omoalade144(m): 10:34pm On Dec 07, 2015 |
ejoo nibo ni a o gbe ipese na lo,atipe sebi woni ti eyan ban je okete,awon agbalagba yio ma ri ifun re,yio si rorun funwon lati baja??.Koni baje o |
(1) (2) (3) ... (36) (37) (38) (39) (40) (41) (42) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 25 |