Stats: 3,227,772 members, 8,071,620 topics. Date: Thursday, 06 February 2025 at 07:42 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1854079 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (68) (69) (70) (71) (72) (73) (74) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by Zenlife: 1:26am On Apr 02, 2016 |
dominicson: what is osumare? And how or when is it found? In lagos, what river may one locate it? How does one know for sure it is osumare upon locating it? What precisely is required for the ritual and how is it done? How much is to be paid to osumare? And how does one make said payment? How much should be taken out of the said payment and given to wife? Upon doing these afore-mentioned, what will result, how soon, and is this method proven? I am thankful for the directive sir, and earnestly await your response. |
Re: .. by Lero70: 8:39am On Apr 02, 2016 |
@Dominicson Ekaaro Alagba, esisehun pupo fun iranlowo tense fun gbogbo wa, Olorun konii kunyin nipa, eesiniidaamu lagbara oga-ogo, ewe o maaje funyin o. Ase. Moti da esipada sori email yin, mositun nreti esi lati odo yin. Oro yin konii su Olodumare. 1 Like 1 Share |
Re: .. by Zenlife: 1:15pm On Apr 03, 2016 |
Zenlife: Please am still awaiting your reply sir. |
Re: .. by Zenlife: 1:18pm On Apr 03, 2016 |
Zenlife: Please am still awaiting your reply sir. Thank you. |
Re: .. by swiss98: 3:28pm On Apr 03, 2016 |
[color=#000099][/color] Okigbe igo todaju kini ewo re |
Re: .. by swiss98: 3:28pm On Apr 03, 2016 |
[color=#000099][/color] Okigbe igo todaju kin I ewo re |
Re: .. by Nobody: 5:37pm On Apr 03, 2016 |
dominicson: ![]() |
Re: .. by Djbless: 11:51am On Apr 04, 2016 |
ejo efun wa ni ogun Agbeti todaju |
Re: .. by Rokeeb75: 3:27pm On Apr 05, 2016 |
EJOWO MO NI LO MAYEHUN TI A FI LE GBA NKAN NI OWO ENIYAN LATI ORI ERO IBARAENISORO... |
Re: .. by fxopen(m): 5:04pm On Apr 05, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=43914838]OSO KEKE KAN TO GBONA NIYI Ewe-laali Eyin adire ororo(do do do) merin Oga aaye kan Owo-titun (#500 or 1000) Igba-olomori Ose Oyin Lofinda bintu meji. Ao gun ewe-lali yen daadaa, ao gun awon eyin yen mo, ao gun ose yen papo mo, ao fi oyin po ose yen, leyin na ao tun po pelu lofinda bintu kan, ao fi owo(money) yen tele(mi do) igba, ao fi Oga yen le owo yen lori ki o gba awo(d o do) owo yen, ao gbe ose yen le lori, ao wa lu ose yen laarin ti yio fi kan Oga yen lara, ao wa tun bintu kan to ku yen si. ao de igba yen pa fun ojo-merindinlogun(16days) ki a to ma we ose na. Pelu Ogo-Olohun yio si ri be. NOTE; Akii fi omi si oso yen ti a ba n se lowo oo. e jowo baba nigbati a ba lu ose yen ni Aarin nje igba naa ko ni fo? bawo ni a o se see |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:14pm On Apr 05, 2016 |
Ose iyonu awon agba imi-ewure, imi-agutan, ewe-eko ti won sonu, ewe-orijin pupo. Ao gun po mo ose..ao ma fi we. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:15pm On Apr 05, 2016 |
[quote author=fxopen post=44432917][/quote] fifo bawo....Ika-owo ni a ma fi lu ose yen ooo. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 8:20pm On Apr 05, 2016 |
Aworo Itaja Era aladi Awo-eta Ao fi owo(re mi) fon ina si Ose Ao gun papo ati ose yen,ao wa pe gbolohun re si, ao ma fi we. Gbolohun re; Afi atewo fon ina kii duro, ina loni ki e fi owo(re mi) owo(hand) yin ba mi na, era loni ki e fi owo owo(re mi) yin ba mi ra, eta ni koko ta ki omo-eranko miran to ta. Ao so oun ti a fe, ao fi we. 2 Likes |
Re: .. by fxopen(m): 4:45pm On Apr 06, 2016 |
Ifankaleluya:e seun sir, e jowo ti won ba so pe eeyan maa sefa (m m) ki lo tunmosi sir, |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:33pm On Apr 07, 2016 |
fxopen: Ifa sise tumo si wipe eniyan ma da ifa re ni, yio si ma ba soro nigbakigba ti o ba wu eniyan. Eniyan le gba ifa ko gbe si odo(do do) Baba-awo re, a sile gbe si odo(do do) fun ra wa. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:40pm On Apr 07, 2016 |
Ifa ni; Ewure(re mi mi) lo fi ori sile Lo pa(mi) lorunkun(mi mi mi) Adifa fun Orunmila Nijo ti wa n tori baba kewu Ti won tori baba pe egede(do do do) Ti won n tori baba pe aasan Ti won tori baba sa ogungun(do do do) Orunmila ni, e ba tori mi kewu oo E ba tori mi pe egede E ba tori mi pa aasan E ba tori mi sa ogungun E ba tori mi tan abela(do mi do) Ti owo mi ba ba(re) ikin(re re) Ma si sete(mi do) igba(do do) ti owo mi ba Ikin Mo si sete. Aboru, Aboye, Abo-sise! 1 Like |
Re: .. by Ifatoki16: 6:44am On Apr 08, 2016 |
Baba mi agbalagba Ifankaleluya,e jowo mo fi Orunmila beyin kie fun mi ni ise imule awon agba ti won fi nyo si wa loju orun fi ogun aye wa han wa yen kio pe.O fi tie sile gbo teni eleni, Olorun yio gbo tiyin na ooo.Ase. number mi 09053297971 @Ifatoki16 |
Re: .. by Tevez83839: 7:23am On Apr 09, 2016 |
Baba edakun.ise ayaworan ni mo yan-an laayo. Sugbon ni shop mi oja ko yaa daada oorun ni mo n sun edakun kini ogun ti mo le ri mo inu shop bi aworo todaju ti customer fi maa wa pupo...boya eyi ti eyan ma gbe ile fun Atipe se ise yi daju ( ao gbe ile sinu shop ,ao da iyo sibe ,aote ni eji ogbe ao wa fi pandoro si inu ile yii .ao da iyo lee lori to maa bo pandoro yii ,ao wa da aso funfun boo lori ao wa ro iyepe lee lori ) se odaju tabi afikun .tabi ki e fun mi ni ominra aje biidan .edakun |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:20am On Apr 09, 2016 |
Ifa ni; Owonrin-wese(do mi) wese A dia fun Abi-ose Ti s'omo Ose-lawe(re do re do) Nijo ti n be larin iponju Ebo won ni kose Ogb'ebo nibe o si sebo Ogb'atuka esu o si tu Nje ero-ipo, ero-offa E wa wo ifa awo ki bi ti n se. Mo gbadura ki Eledumare o ba onikaluku wa we ise(do mi) aye wa nu. Ase! Aboru, Aboye! 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:24am On Apr 09, 2016 |
Ifatoki16: Omo baba-awo ifatoki, Imule awon agbalagba to tun lagbara ju iyen lo si wa. A ko mo ifa ni...Orunmila ni oko-oso ati Aje, so boya ka soro labe aso. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:32am On Apr 09, 2016 |
Tevez83839: Ore wa, n ko ise ti e bere nipa re yen. Eleyi ti emi mo to jo mo nipe ao ko tewe-tegbo kun-kun(mi mi) le odu ti a fi iyo te yen lori ni. Ao si tun fi awon ewe-ifa kan kun. Nko mo bi shop yin yen se tobi to ni...Oso-afaro wa toje wipe laarin 21days shop yin yen a ti di Oja(market). Sugbon kiise oun ti e le da se, ati wipe ti shop yin yen ba kere, ko dara to. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:02am On Apr 09, 2016 |
Ifa isegun ota o ni Obara-ika to daju. Ao lo wa epo igi-iroko, ao lo kunna daadaa, ao sa gbe, ao fi te Obara-ika sinu awo-amo dudu. Ao pa obi-meji fun, ao je die ninu obi na ni ao fi pe ifa re Ogun ni be mo lori omo-okege Iroko alu ji ni deru ba agba Opelope obara-ika Ngba tomo araiye yo ida Ti won ni awon o pa mi se bi akaniku,Orunmila lekun Aja ki ja mo lehin ekun paje Oso ile to ba nperi mi nibi Obara-ika o,ka oluwa re sorun Aje-ile, okunrin, obinrin ti ba n peri mi nibi, Obara-ika, ko ka Oluwa re sorun. Ao da obi yen fun, ti obi yen ba ti yan, ao bu epo pupa si, ao la ti a ba fe sun lale. Aboru, Aboye. 2 Likes |
Re: .. by Tevez83839: 11:48am On Apr 09, 2016 |
Edakun shop yen fee die .e koo fun mi boya mo le see. Tabi ejowo e add me 08162736520.EDAKUN OJA KO WA |
Re: .. by Tevez83839: 11:50am On Apr 09, 2016 |
[color=#770077][/color .ejowo e add me ni whatsapp .ejowo..ki ale baa maa soro daada 08162736520 |
Re: .. by wale259(m): 11:25am On Apr 10, 2016 |
Sir,bawo la se ma wa se obi yen to ba ti yan?obi yen ma je mejo(eight pieces) Ifankaleluya: |
Re: .. by wale259(m): 11:26am On Apr 10, 2016 |
Ase!!! Ifankaleluya: |
Re: .. by Ifatoki16: 3:54pm On Apr 10, 2016 |
Baba Ifankaleluya,eku atunse ati agbaale wa lori ikanni yi.Ejoo emi Ifatoki16 bere fun imule awon aje ti won fi nfi ami igba si aya wa tie fi sita ti ko pe.mo bere ni ori email yin,sugbon e ko dami lohun lati igba na.tabi e nbinu simi ni.email mi ni eyi llcatz@yahoo.com |
Re: .. by Ifankaleluya: 3:58pm On Apr 10, 2016 |
Apete ti a ma n fi sara to sise ibon, Ada, Okuta, Apola or whatever, Ti a ba se Apete yi tan, ti o ba wa lara wa, ti won ba yin ibon(gun) mo wa, eni ti o yin ibon yen yio si di Aka(re mi)(Adete) lesekese. Ao lo re wa ewe-ina pupa, ewe-esisi, Ahun, ewe-airagba, Aso-aka. Oruka ti ko wo omi iyekiye. E je kin da enu duro nibi tori awon oni-ise ibi. |
Re: .. by Ifankaleluya: 3:59pm On Apr 10, 2016 |
Ifa ni; Idin Ran nnn Babalawo Oyin lo ki ifa ojo kan fun oyin Nijo ti n ti ikole orun-bowa aye Ebo won ni kose Ogb'ebo nbe o si sebo Ogb'atuka esu o si tu Nje morann-morann lawiran oyin Awidun lawiran iyo Morann-morann lawiran oyin. Pelu ogo Eledumare, tomode-tagba yio ma soro wa si rere. Ase! Aboru, Aboye. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 4:02pm On Apr 10, 2016 |
wale259: Jije ni obi yen. |
(1) (2) (3) ... (68) (69) (70) (71) (72) (73) (74) ... (99) (Reply)
Viewing this topic: 3 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 47 |