Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,227,778 members, 8,071,637 topics. Date: Thursday, 06 February 2025 at 08:09 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1854082 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (73) (74) (75) (76) (77) (78) (79) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by estateallen: 2:39am On May 06, 2016 |
Ara iwaju iba o!!! ejor shey a le jo ewe ogun papo lori electric cooker? |
Re: .. by jophins(m): 10:43am On May 06, 2016 |
Ifankaleluya no ki yin sir eku ishe E jowo no Send mail kan si yin ejowo sir E dakun mon reti esi Ayo. |
Re: .. by jophins(m): 10:47am On May 06, 2016 |
@estateallen o funny die sugbon emi naa to she iru e ri daada sugbon Orun at I efi ma gba inu ile koda gan o tun ya sugbon e je ji a she bi ti awon Baba wa tin manshe ki o ba ri bitin ri ka ma fi aye Olaju bo lo Aroo eledu tabi Stove tabi Igi |
Re: .. by sanjayzaman(m): 10:18pm On May 06, 2016 |
walexy30:se ale lo ebu yii fun opo eniyan abi ori Kan Loma loo toba je ori Kan Loma loo se ekan Lao lo gbogbo ebu yii tan abi diedie ni ao ma lo ese pupo olohun atunbo ma ran yin lowo ewe ATI egbo yio ma je? |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:57pm On May 07, 2016 |
flightz: E se suuru baba..! 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:58pm On May 07, 2016 |
jophins: E dakun kin ni e-mail yin yen na? |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:04pm On May 07, 2016 |
OGUN KI A MA BA LU MAGUN Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa. Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:11pm On May 07, 2016 |
AJEGUN ABALAYE Owo-osi elegbede, ewe-ina pupa, ewe-esisi, odidi atare kan, etu ibon. Owo-osi elegbede yi ni ao koko jo papo mo awon ewe-ida yoku, ti o ba jo tan ti a so kale, ao wa je ko tutu, ao wa da etu-ibon yen si, ao lo po dada, ao fi sin gbere yi orun owo mejeji ka, ao po iyoku mo ose, ao ma fi fo owo. Ela-boru, Ela-boye, Ela-bosise. 2 Likes |
Re: .. by zenith329: 8:04am On May 08, 2016 |
[quote author=Ifankaleluya post=45414089]OGUN KI A MA BA LU MAGUN Panumo, ewe seyo, ao lo papo mo oko-atare kan, ao fi sin gbere yika isale ikun wa. Baba ifankehaleluya, e ma binu, se ewe sayo le fe ko? |
Re: .. by Lero70: 12:47pm On May 08, 2016 |
Ifankaleluya:, baba awo Ifankaleluya, edakun orisi panumo meji lowa, panumo abo ni abi panumo abafe? Eseepupo ewe amaaje o. 2 Likes 1 Share |
Re: .. by consato009: 10:52pm On May 08, 2016 |
E joo baba efun nise yi tan nitori mo need e gan ni, gbogbo Awon babalawo timo ma nlo sodore tiwon ba dafa lo tiwon dafa bo won ani ogun Awon agbalagba ni kinma tera mo lati loo, e tori olorun efi iseyi saanu mi... |
Re: .. by Faiga84: 8:10am On May 09, 2016 |
Nil |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:18pm On May 09, 2016 |
Lero70: Panumo Abo ni baba..! 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 7:23pm On May 09, 2016 |
consato009: Se eti se awon etutu ti won ni ki e se? Ati wipe, se awon babalawo yen o se ifa awon agbalagba fun yin ni? Ifa awon agbalagba po dada, melo ni e se?....sugbon ko ba wu mi lati mo ODU-IFA e da last. |
Re: .. by fbabs(m): 9:01am On May 10, 2016 |
Ifankaleluya:e seun baba mo ti ri owo yin. E pe fun wa mo ti kan si yin pada |
Re: .. by estateallen: 10:21pm On May 10, 2016 |
Ejor shey mo le ri eni to nbo wa si ilu oyinbo (UK) laipe ni bibayi ? Ese o |
Re: .. by Ifankaleluya: 10:23pm On May 11, 2016 |
Ifa ni; Tipa-tipa ni Babalawo fi fewure bo-ifa Agbe eeti ni maro Aluko kii ti ni ibu kosun Odidere kii ti ni ibu tepo Ojulumo e je ki ahun o sun gbe Alo, alo, alo ese lori alabahun jafa Ora loni kin ma rahun owo Ihoho-dodo lagbado roko To ba dajodun a do nigba ire gbogbo Sinkinminni mi de Afaimoni ko ni mora Iyere-osun loni ki ire-aje temi o ma sun na Eji-ogbe, a gbe la ni ko gbe mi. Eledumare ko ni je ki gbogbo wa o rahun ire gbogbo. Ase! Aboru, Aboye, Abo-sise..! 1 Like |
Re: .. by auggswell: 12:08am On May 12, 2016 |
[quote author=Legendbaba1 post=44872377]BABA KEPE EJO WO TI ENIYAN BANI AYISAN Staphylococcus KINI ENIYAN LELO FUN ARUN YI MAY U LIVE LONG AMIN [ aarun buruku ni staph, oogun wa ti e ma lo amo yi o gba yin ni time, at leas OSU meta, o wa le kuro Lara yin laarin OSU kan oo amo OSU meta ni ki e ma fi okan le. toripe e le lo se test ki won ni won o ri nlankan ti o de si wa nibe. aasi ma fa aisan orisirisi si yin lara. torina Bi e ba se n lo oogun ni e o ma se ayewo leekan tabi emeji losu |
Re: .. by Ifankaleluya: 9:14pm On May 12, 2016 |
Ifa ni; Bikun ba jẹ loju oloko, Eku ẹ sagada lẹhin ebe A difa fun Ogbe eyi ti o gbe apo iwa ko Iwori ọmọ iya rẹ lọrun. O ni ọjọ ta a ri Iwori la rahun aje mọ. A rira, mama jẹ ki a rahun a rira. Ojọ ta ri Iwori la rahun owo mọ. Ojo ta ri Iwori la rahun ire gbogbo mo. A rira, Ifa mama je ki a rahun, a rira. Eledumare ko ni je ki a rahun ire-gbogbo nile aye...Ase! 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 5:57pm On May 13, 2016 |
Ifa ni; Aronipin(re re re re) eniyan ni funni lagbondo adie je, A dia fun Orunmila Baba n fomije sungbere aya Won ni o sa ki imonle ebo elenini ni ko se, O gbebo nbe o si sebo, Nje elenini ile e wa gba, Eyin aronipin eniyan, e wa gba, Odere ile yi e wa gba, Asake ile yi e wa gba, Iya kere ile yi e wa gba, Eyin aronipin eniyan e wa gba. Gbogbo ota to ni ti e ko ba de ile oun e o ni se rere, Pelu ogo-olorun, lowo yin ni won ti mo wa gba. To abala esu. Aboru, Aboye, Abo-sise. 1 Like |
Re: .. by shogzy12: 6:32pm On May 13, 2016 |
Bi e ba fe dara po mo wa lori whatsapp, e fi number yin ranse si e-mail yi binaryteck@gmail.com, ao fi yin sori whasapp wa. Ao da whatsapp group sile fun awon ibeere sugbon eni to ba fe ibeere lori asiri, yio kan si wa ni idakonko.(private). |
Re: .. by shogzy12: 6:38pm On May 13, 2016 |
E jo sir (gmail) te fun wa o lo lati aro ni mo ti gbiyanju lati add re, e Jo boya ke ranmilowo ke add mi, aolamide25@gmail.com e seun gan sir modupe |
Re: .. by misspricy(f): 9:59am On May 14, 2016 |
orunmila76:. E jowo sir, se body cream ni lofinda abi perfume. |
Re: .. by wale259(m): 10:56pm On May 14, 2016 |
Amin Ase baba mi ifankaleluya. Ifankaleluya: |
Re: .. by ALIUDAVID: 11:04pm On May 14, 2016 |
Ifankaleluya: Baba ifakaleluya moti send mail si email yin ma ma reti esi yin email mi ni yii (aliudavidodunayo@gmail.com) eseun iba agbagba, iba eyin to laye. |
Re: .. by ademotech: 2:55am On May 15, 2016 |
eejo molala pe moru irin mosi sokale SI ebute kini itun mo re |
Re: .. by Tevez83839: 7:45am On May 15, 2016 |
Edakun eyin babawa monife arabinrin kan ni mosi fee fe sile sugbon oni ohun ko le femi edakun mo mo oruko re ati ti baba re .ko ki se omo timo le fun ni afunje .,sugbon iru ise wo nimole sasi |
Re: .. by Hadeyeancah(m): 12:26pm On May 15, 2016 |
Ara iwaju iba o!!! E Jo sir, kini awon agba npe ni ogun asiri owo ati ogun asiri bibo. Iyato wo lo wa larin won ati wi pe kinni implications ati disadvantages won.. E se sir, ewe a ma je ooo |
Re: .. by fbabs(m): 1:57pm On May 15, 2016 |
misspricy: lofinda = perfume , body cream = ipara |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:28pm On May 15, 2016 |
Tevez83839: Imonran temi ni wipe ki e koko lo wadi boya iyawo yin ni na. Lotito Ife se fi agbara wa, sugbon ko dara to nitori ojo-iwaju. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 2:37pm On May 15, 2016 |
Hadeyeancah: Iyato wa dara-dara larin awon nkan ti e daruko yen. Ati wipe orisi-risi re lo wa. Asiri-Owo da bi Ako-Osole, Nigbati a si le pe Asiri-bibo ni Awure. Nipa disadvantages won, Awon nkan ti won ba fi se ni yio so iru alebu to wa nibe. Kiiise. Gbogbo iru-ogun bayen na ni o ni alebu, o wa lowo Babalawo ti o ba se fun yin. Idi niyi to fi je wipe eniyan o kan le sa dede ma se awon ogun kan to ka ninu iwe kan, bi kose. Ko to awon to ni imo(knowledge) nipa Ogun lo. 1 Like |
Re: .. by Ifankaleluya: 3:00pm On May 15, 2016 |
IFA NI, Iji ti mo ji mo ba agbe lori igbago Iji ti mo ji mo ba akalamagbo lori imo Iji ti mo ji mo ba toro momo lori ope Toro gege ni iya orunmile nje Awon olode e mo le binu igun-nu-gun lai-lai Olorisa kii binu sefun-sefun Enikan kii binu akan lodo Aigbori odo pete odo Aigbaja ka gbimonran ika laja Enikan kii gun iyan koko ko pode ilu jo Ojiji enikan ke di mo ni Ifa o to gege, ma je ki omo araye o le binu mi. Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes |
(1) (2) (3) ... (73) (74) (75) (76) (77) (78) (79) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 55 |