Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,336 members, 7,978,073 topics. Date: Thursday, 17 October 2024 at 06:22 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843577 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (82) (83) (84) (85) (86) (87) (88) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by miich28: 11:01am On Sep 14, 2016 |
@:Baba #Kadunasouth ati Baba #Healthfirst...Mi o le paro nkan ti mo n se:Omo yahoo ni mi,,,,,Ejowo,,,Mo ni lo Oogun ti mo le fi GBA owo lowo awon Clients Mi Ewe a maa he fun yin @:Baba #Kadunasouth ati Baba #Healthfirst...Mi o le paro nkan ti mo n se:Omo yahoo ni mi,,,,,Ejowo,,,Mo ni lo Oogun ti mo le fi GBA owo lowo awon Clients Mi Ewe a maa he fun yin |
Re: .. by sirkzee: 1:39pm On Sep 18, 2016 |
ewe ama je ooo |
Re: .. by ENOWOH: 9:18pm On Sep 19, 2016 |
Baba ki ni a le lo fun omode ti o ni kokoro ni gbogbo ara re. kokoro naa ma lo a tun pade. |
Re: .. by dmangodwin(m): 9:38am On Sep 21, 2016 |
x |
Re: .. by Nobody: 10:57am On Sep 24, 2016 |
Hello all karoojire here, Pls, 1. How does "MAGUN" work? 2. Is it possible for someone who is not a legit husband( or anybody at all) to put it on someone else's legit wife (or on any female, married or not married)? 3. If a man places it on his wife, is he excempted from the magun spell? That is, can he mate SAFELY with his wife? 4. How to identify a female with magun 5. How to remove magun from a female with Magun 6. Is there Magun or equivalent done on males? 7. How is it prepared? Thanks |
Re: .. by olusegunakintol: 8:52pm On Sep 24, 2016 |
dominicson: dominicson: dominicson: gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo |
Re: .. by olusegunakintol: 8:55pm On Sep 24, 2016 |
dominicson: gbogbo isese E joo, ise contract ni mo n se,o de ti le lodun meta bayi ti mo ti di oga ara mi. Amo s e ni mo kan n joko ni office lasan ni mio ki n rise gba. Koda awon ore kan ma n wa ya irinse mi sise won ni. Isin(religion) mi ko faye gba ogun(charms),ayajo ati ofo(chants). Sugbon a nigbagbo ninu ewe ati egbo,agbo(herbs) ati ose(soaps) gege bi ase ti Olorun ti da mo won. E jowo e ran mi lowo ki n yee seru aye. Ki ona la femi naa. A maa ju yin se o gbogbo isese, e joo e ma wo mi niran. e ran mi lowo |
Re: .. by emmyjahzy: 11:28am On Sep 28, 2016 |
Mofi Olohun bura, owa daada sugbon awon yahoo won ki n moore 1 Like |
Re: .. by Nobody: 6:40pm On Sep 28, 2016 |
add me to the group 1 Like |
Re: .. by dominicson: 10:59pm On Sep 28, 2016 |
olusegunakintol: Join Isese L'agba! 1 Like |
Re: .. by elegushichilling: 1:36am On Sep 29, 2016 |
dominicson: our God Jehovah is alive, he is fighting for us and will continue to do same. Better give ur life to christ now, tomm may be too late. Iku lo'n keyin oungbo gbo. Kini yo je erere ti oba jere gbogbo aye yi, ti osi so emi renu. Ranti wipe aye loja, orun nile. Kilode toje wipe a'un gba owo iyebiye lowo ara wa, ki ato ran ira wa lowo pelu agbara, ipo ati oye wa. A'un tan ira waje wipe okan niwa, omo ile kaaro ojire. Sioo, Iwo ti oko, ti oko se ore, seranti wipe elomiran ni olorun yo lo lati se ore eyi ni ofe, ti oun olorun fe se. Iru eni na sini yoo gba iyi re fun ogo olorun ati imuse oro olorun. Olorun ki se eniyan ti yo fi puro, tabi omo eniyan ti yo fi yipada. Otiso, unje ko ni se, otiso oro, se koni muse. Fi igbagbo re le Oluwa eledumare, ki ogba laye, ki ose iyanu layere. Igbagbo lai si ise, oku ni. Ise pelu igbagbo, emi ni. Gba olorun laye ki odari re si ibi ti igbala re wa pelu ise igbagbo re ninu oruko Jesu. Emi, Ara Olodunmare. 2 Likes |
Re: .. by zenith329: 2:57pm On Sep 29, 2016 |
If you have it in abundant, kindly give him, he will surely appreciate it and be grateful to you, remember, this world is a small world |
Re: .. by Ola4ple: 5:27pm On Sep 29, 2016 |
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese (iri) |
Re: .. by jophins(m): 12:20am On Sep 30, 2016 |
mo ki gbogbo ile 08082988576 ero ibani soroo mi ni yi e add me si whatsapp group. |
Re: .. by dominicson: 11:45am On Sep 30, 2016 |
elegushichilling: K |
Re: .. by Zenlife: 12:42am On Oct 01, 2016 |
Re: .. by Zenlife: 12:45am On Oct 01, 2016 |
elegushichilling: Hmmmm.... Good Introspection. Food for thought. Well said. 1 Like |
Re: .. by Zenlife: 2:40am On Oct 01, 2016 |
For those who claim to be in the know on this thread and those with whatsapp group, the so called babas, Awos, etc , why are valid questions ignored, such as... Asked by 'nobody' above over a week ago... " Hello all karoojire here, Pls, 1. How does "MAGUN" work? 2. Is it possible for someone who is not a legit husband( or anybody at all) to put it on someone else's legit wife (or on any female, married or not married)? 3. If a man places it on his wife, is he excempted from the magun spell? That is, can he mate SAFELY with his wife? 4. How to identify a female with magun 5. How to remove magun from a female with Magun 6. Is there Magun or equivalent done on males? 7. How is it prepared? Thanks" Could it be because there's no potential monetary gains in these questions? If so, there's I guess no limit to your despicable hustle in the cloak of disguised assistance and that to me is so damn low exploitative, and apologetically dishonorable. Using Orunmila, the deities, for the primary reason to exploit users of this forum or thread for personal monetary gains is abhorrent, humanly and spiritually disappointing. Those who come under such umbrella should be perceived as scumbags, leaches and avoided as plagues. It shouldn't always be about money. On here, you give a little coomon candy as though you wanna assist, but all done with ulterior motives. When you get folks sucked in and pertinent questions asked, you give the flimsy excuse why it can't be publicly shared and asked to pm you or join your group. So I ask, those who pay you and you give these 'oogun" to, how do you know that they are worthy of it? Do you conduct a thorough background check? No you don't. Damn shameless hustlers. You all can go bury your head in the sand, fly a kite, or flush yourselves down the loo and kiss my black ass while at it. Despicable, nauseating charlatans!!! Rubbish! Oshi!! |
Re: .. by Ola4ple: 9:51am On Oct 01, 2016 |
Edakun Kilo Nje Iri Ti Eko Si Ibi Ogun Atayese I Mean D Meaning Of Iri |
Re: .. by dominicson: 5:01pm On Oct 01, 2016 |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:28am On Oct 05, 2016 |
ago'onile'o, fun eyin ti enbere ibeere nipa osu, tabi ti nta nso'oye, opolopo ntaso koseyin akose jaye, dida ara eni mo, iwadi nipa eto igbe aye wa, boba wa laye bi okoba da arare mo inira amawa ni igba kokan, tojepe bi oba se oogun gan koni sise, sugbon aje, oso, emere lama ndi lelori, bi akose jaye ba ndani laamun bi eyi tojepe eyan si aye wa ni, tori bore waju pabo ni, bore yin pabo ni, atotun atosi bi alai monse ni bi oro bari bai, owo Ori lati nbeere, tori ori eni lawure eni, ogun loni ojo iponju kafola fori tolojo gbogbo. fun iwo ti obafe lati wo akose jaye re onilati fi ojo ibi re ranse. ati paapa eyin Omo June 22 to July 23 ati 2/19to3/20 haa! Afiti ori won bagbe alawore kowon nitori hmm olagbara'o ajuwase'o Asitun nfi asikoyi sofun eyin aworo sasa todarare loju wipe anfani Ti si sile bai lati join egbe awon ojogbon Ti ape oruko'e Ni MAJEMU LAILAI on wasp. Kajolasepe'o |
Re: .. by olusegunakintol: 4:07pm On Oct 05, 2016 |
dominicson: add me to the group. my whatsapp number is 08182533557 |
Re: .. by skamoh74: 6:44am On Oct 09, 2016 |
08101646045atwp: . please add me 08085632313 thanks |
Re: .. by Lero70: 2:56am On Oct 11, 2016 |
dominicson:moki gbogbo eyin agbalagba ti Eledumare jogun ogbon fun ni abala yi, lagbara Eledua ogbon na konii dope, kosiniitan nibiti eti nmuu. Ejowo mose akiyesi pe eyin agba wonyi kofibee kobiara si abala yi mo, ISESE LAGBA GROUP lorii whatsapp ti boo mole patapata, mosifekeemope awa ti a nje anfaani abala yi, sugbon ti phone wa kogba whatsapp application sipo gan, nitorinaa ejowo ebawa fun abala yi ni ijelogun bii tateyinwa. Yio maa juu yin se o ase. |
Re: .. by Nostradamus: 7:37am On Oct 12, 2016 |
dominicson:edakun gbogbo ile mo ni ibeere ranpe kan,ti won salaye pe ki a gun ogun kan mo ose dudu,shey a le ko ose ati ogun na si ori olo(grinding stone)ki a lo papo?mo fe se ose ebe awon agba kan ni sugbon mi o ri aye si odo but olo wa niwaju mi bayi. |
Re: .. by emmyjahzy: 1:22pm On Oct 12, 2016 |
Beeni sugbon kodara to kia ma lo eyi ti awon iyawo wa fi nlo ata |
Re: .. by bolorunfem(f): 4:28pm On Oct 13, 2016 |
. |
Re: .. by dominicson: 11:56pm On Oct 13, 2016 |
Nostradamus: A ma n lo olo. Asi tun ma n lo odo. Nigba miran ohun ti a ba fe gun le kere ti o je wipe ti a ba lo odo, odo yoo ko je. Fun idi eyi, a ma lo olo. Nigba miran ewe, ohun ti a ba fe gun le po ju olo lo ti o je wipe odo la ma lo. Sugbon o, awon ise kan wa ti o je wipe o ma n pan dandan ki a lo ohun ti won ba ni ki a lo lati fi gun, boya odo tabi olo. Ohun ti o tun da bi re ni wipe, a koko ma n gun eroja kunna ki a to da ose abuwe si, ki a to wa gun papo. Ohun ti o fa sababi eleyi ni wipe ki o le ba rorun lati gun papo. Isese a gbe wa o! 1 Like |
Re: .. by dominicson: 12:07am On Oct 14, 2016 |
Lero70: O seun gan. Adura re yoo gba. Oju ko ni tie. Omo araye ko ni binu re. O o ni te oju ile mo'le. O o ni si oko ja je. Porogodo aye ko ni lu fun o jo. O wi're! Agbekale oro re fi han pe omoluhabi ni o. Oo ni je ibaje nigba kookan. Ba mi fi omi lo kekere yi: House arrest Iha, damonito, koleorogba, ose dudu, a o gun papo, ita gbangba nibiti elomiran ko le ti we ni a ti ma n we. Ko si igba ti a ko le we. Psalm: Damonito kan kii fi ito tie dola, warawara ni koleorogba n s'oje, gbogbo eniti ba n p'ori mi nibi, oso ni, aje ni, emere ni, kenimani, babalawo, pastor, ala-laafa,abbl, Iha lo ba mi ha won mole ki won ma le jade mo. Ki won ma a gbe yara pe omo alakara. 1 Like |
Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 6:13am On Oct 14, 2016 |
ekaro, eku oju mon, inu mi dun lati darapo mo eyin memba ti nairaland. eku ki asa ati ise yoruba ma pa run. motun fi asiko yi ki gbogbo agbalagba ati omode to wa ni nairalandi yi ajinde ara yo maje oo inu mi dun pupo lati tun mo eniyan si lori oro alagbeka (internet). |
Re: .. by HorlarhMheporzy(m): 6:19am On Oct 14, 2016 |
Ejo mo ni di ogun ti mofa ti ara eyan ati awon mo gbon lai ri inka iberu (scared thing) ta bi wa nibi ti oro posi (in public). so gbon mogbo pe aisan isan (vein fever) ni. eda kun mo nidi ogun yi gidi gidi gan ni. |
Re: .. by rubbyplus: 2:25pm On Oct 14, 2016 |
Mo ki gbogbo tomode tagba lori ikani yii. Mo je olufe ikanni yiii lati 2015. Inu mi lati join finally. Ewe a ma je oo. Ase |
(1) (2) (3) ... (82) (83) (84) (85) (86) (87) (88) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 72 |