Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,201,399 members, 7,978,272 topics. Date: Friday, 18 October 2024 at 01:46 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / .. (1843628 Views)
"We The Ewe People Of Ghana Are The Same As Yoruba"- Yewe2011.ewe Guy From Ghana / How Do U Spell (weed) In Yoruba, Is It Igbo? Or Egbo? / Yoruba Idioms: Owe Yoruba, Itunmo Re Ati Lilo Re (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (99) (Reply) (Go Down)
Re: .. by 08101646045atwp(m): 9:55am On Dec 15, 2016 |
Moki gbogbo eyin Omo Iya wa Nile loko lona leyin oodi Wipe AKI'IMUNRA ODUN'OO!!! Mo se awon aki'esi Pataki kan Lori gbogbo eyin Omo iyawa Ti eje yioruba Ti Ewa Ni Ilu okeere tabi Ti eyi kuro Nile tipe... Opo awon call Ti moma ngba ati awon atejise to nwole lofun mi Ni akie si lopolopo Lori won wipe opo ninu won atun maarahun, elomiran tie le wipe ohun Fe pe sugbon Ko si owo card tori wipe owo Kekere Koto bawa soro, elomi ama sise sugbon bukaata tipoju, nipa bai elomi kotie ran to Ile mon nitori opo igba Ti obati ranti awon enyan re bai ironu Ni Ni gbogbo ijo na, oroyi Ni Moro Ti mofi fi awon oogun kan sile seyin iyen fun awon Ti won bale jawe tabi Sa oogun! Opo lositi lo oogun yala Ti ose fun arare tabi Ti won fi ranse sugbon pabo lotun njaasi Nitori Idi eyi nimose tun gbe ilana eto nipa wiwo akosejaye sile Sugbon bai motun Fe fi awon oogun sile fun eyin Ti enpe mi lati okeere tabi fun oniru'iru isoro Emaabawa kalo Ajuwase o |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:02am On Dec 15, 2016 |
Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:11am On Dec 15, 2016 |
Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan Ajuwase o |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:16am On Dec 15, 2016 |
HMMM eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. . N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ). |
Re: .. by seanjizzyayo: 10:20am On Dec 17, 2016 |
kadunasouth: kini itumo eran malu ekiri kan ,koyemi to ejowo elayemi 2 Likes |
Re: .. by seanjizzyayo: 1:58pm On Dec 17, 2016 |
ALIUDAVID: kini a o fi ran awo yii se awo ni tabi aso abi iru awo WO .ela yemi edakun ewe amaje ooo |
Re: .. by seanjizzyayo: 3:09pm On Dec 17, 2016 |
kadunasouth: Mo ki yin ooo, baba wa Kadunasouth ati Baba wa healthfirst, ewe ama je ooo. baba ejowo efumi ni ogun ti omo yahoo le Malo ti yo mari owo gba Dada lowo client, yala oruka tabi aseje tabi ose mo si tun nilo Ogun GBOGBO IGI TI ELEGBEDE BA FOWO BA DIDUN LON DUN ejowo esanu mi konibaje fun yin agba yin adale |
Re: .. by seanjizzyayo: 5:55pm On Dec 17, 2016 |
kadunasouth: baba eyele yi se ale lo eyi ti oti ku tabi aye tabi ti aba ra laye aopa kato lo , atipe ewe aje yen se gbigbe ni tabi tutu, owo (money) ti eso yen se abiya eyele yii lapa otun ati osi la o fisi tabi ninu agbada ijogun lapa otun ati tosi la o fisi ati wipe se ekan ti aba Jo ebu yi ni a o lotan abi OSU melomelo la o malo , se taba lo ebu yii tan se ale matun se kamalo lo, se eni to ko ni ise owo(hand work) ti oje yahoo lonse lelo iseyi ,panbanbari re nipe se ogberi lelo atipe se agbada ti won ti fi joogun ri se mole fi Jo tabi mole Jo lodo elewe omo edakun ESE alaye fun mi Dada Lori ibere mi monreti idahun |
Re: .. by Ayomidegbenga1(m): 6:24pm On Dec 17, 2016 |
Baba ifankaleluya pls kindly give me Odu ifa that works for boldness"ikiya" and how to use it.isese a gbe wa ooooo... |
Re: .. by Lero70: 7:31am On Dec 21, 2016 |
Zenlife: Sir. Am highly disappointed with what you have posted concerning the reply of Baba Ifankaleluya, i think you are a matured man, but it seem as if your mind and your sense of reasoning are not fully matured. Aye oniimuwao, mosife keerantipe INA KOMOJU ENITODAA O. AANIIJEBI. |
Re: .. by Lero70: 8:01am On Dec 21, 2016 |
08101646045atwp: ejowo kilonje ashisu? |
Re: .. by Zenlife: 11:32am On Dec 21, 2016 |
Lero70: You're not appointed. Opinions are like arseholes, everyone has one.
|
Re: .. by Nobody: 8:42am On Dec 26, 2016 |
Ejowo, awure wo lonje "awure dalu te?? ". |
Re: .. by Ifankaleluya: 1:35pm On Dec 29, 2016 |
Ayomidegbenga1: IFA ILAYA OLODI-MEJI 1. Yangi Oju-ona 2. Ikujebu 3. Eresile ewe-idi 4. Yangi esu Ao lo papo, ao wa te ni odu-ifa odi-meji. ifa re; Olukimolaya, ayamudindi kimolaya, ayamu didi ni ti kujebu, ayamu didi ni tesu, yangi oju-ona kiije ji aya ona o ja, ewe-idi ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. odi-meji iwo ni ko di emi lagbaja omo lagbaja laya. eewo ni, aya esu liija nigba kookan. ao ma fi fo eko tutu mu. Aboru, Aboye, Abo-sise. 2 Likes 2 Shares |
Re: .. by ademotech: 6:41pm On Jan 03, 2017 |
baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi |
Re: .. by ademotech: 6:42pm On Jan 03, 2017 |
Ifankaleluya:. baba ejor ebami tunmo ala MI ,,mo LA ala pe mo joko ti owo (money) to PO ni gbangba ti eyan PO ti wan yi MI ka ti wan SI WO mi 1 Like |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 11:29am On Jan 04, 2017 |
ademotech: Bi otile je wipe:- nti okoju si enikan, eyin lokoju si fun elomiran! Sugbon gege bi eti la alayi! Eyi ntumon bai wipe:- tobaje wipe awon Ti oyi yin kayi baje aon Ti edamon eyin tumon si wipe bi iku Ile koba pani tode kii pani Ti osi nsalaye bai wipe olowo kan laarin otosi otosi Ni gbogbo won, Ni odunyi aseyori wa ninu afoju sun yin yen daada! Sugbon enilati se imule ati ebe awon agba Ti ma nje Ki omo'osowo Lai jere! Nitori wipe Oni sowo Ti Ko se ase jere ifa ohere meki wipe eran awon Iya Ni nse! Nitori na esun Mon awon agba daada. Ekoni ri ija kule'o |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 12:09pm On Jan 04, 2017 |
OSOLE=Ti o ma n mun EYAN Mon AWON nlanla nileyi ati okere.(OMO-YAHOO LELO KOSI LABURU) Eiye kannakanna tutu kan,ao fi biscuit okin si labiya otun, ao fi Odidi atare kan si labiya OSI,Ao wa ka iye re mejeji Mon Lara ki awon nkan wonyi maba bole.....ao wa ko eyin ororo meta tele ape tuntun, ao wa GBE eiye kannakanna yen le monle.....ao wa ko ewe ekuya tutu pelu sawerepepe tutu die bo monle....odi jijo.......ao lo kuna Dada,ao wa ma fi 1000naira tuntun kan ko ebu yen sinu oti ST-REMMY....Ao wa GBE si igun yara wa,ao fi 1000naira yen si legbe. Ao wa sope:---------Owo timofi dao loko owo re ooo,kio lo ma bami WO olowo nlanla, olooro,okunrin, obinrin tiowa fun emi l omo l ni owo nlanla wasi odo mi.ADURA.... Ao ma mun diedie laro laro. N/B****** Anfani situn wa fun eyin aworo sasa toje AWO, bii WOLI, ALFA, ati ISESE todarare loju, lati darapo Mon egbe awon ojogbon ti ati ngbe awon ise alagbara jade, ti ape orukore ni MAJEMU LAILAI ON WSP! ele fi orukoyin sile si ori :- https:///6rRqiAC3Y2bHcFdinedWUS :- bere lati Omo ogbon odun losoke. 30 years above! Jowo mafi number re si abe comment'o Whala'oni payin'o Add links yen si odo'e Kede mura sile fun idahun si awon ibere wa Ni ekun rere. Ajuwase o |
Re: .. by Nobody: 12:28pm On Jan 04, 2017 |
Baba ejowo... ose awure wo lonje " awure dalute ". Ejowo kini iwulo re atipe bawo lose ma n sise. Inu mi Ma dun ti e ba dahun ibeere mi. |
Re: .. by 08101646045atwp(m): 7:47am On Jan 05, 2017 |
CallmePROF: Awure Ti won npe Ni dalute Ni awure agbalu Enikan soso Ni ma nlo ninu Ilu kan! Osi a nsise bii apede Ni Ajuwase o 1 Like |
Re: .. by Nobody: 9:17am On Jan 05, 2017 |
08101646045atwp:Baba ejowc...moni lo Ise eyonu nla |
Re: .. by Nobody: 5:38pm On Jan 05, 2017 |
08101646045atwp: Eshe modupe baba, a maa juyin se o. |
Re: .. by Nobody: 5:39pm On Jan 05, 2017 |
08101646045atwp: E seun modupe baba, a maa juyin se o. |
Re: .. by ademotech: 7:52pm On Jan 05, 2017 |
08101646045atwp:ejor imule ati ebe awon agba wo ni mo lese |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:32pm On Jan 05, 2017 |
ademotech: Hnmmmmmmm.........! Baba, emi o mo bi a ti n tan(deceives) ni. Ala ti e la ko dara rara. Iseda yin o ni gba abode pelu ogo-olohun......Amin! N o ni so ju bayen lo.....! |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:42pm On Jan 05, 2017 |
CallmePROF: Baba, e ma je ka tan ara wa je. EMI o gbagbo ninu Awure ti e n toka si yen. Gege bi Apere, ki eniyan kan ni ohun fe ma lo awure dalute ni ilu eko, e dakun nibo ni alujonnu awon to se alujonnu owo ma lo? E dakun, nibo ni alujonnu awon to n lo OSOLE-GBIGBONA ma lo? E ma je ka tan ara wa je, ALUJONNU ju ara won lo. won si ma n da ara won lona gege bi ole ti ma n da eniyan lona! Won da pe fun yin ni, o ni loruko miran, gbogbo n kan to ba je mo bayen gbodo ni owo awon iyami(AJE) ninu, 4 Likes |
Re: .. by Ifankaleluya: 11:56pm On Jan 05, 2017 |
EBE AWON AGBA TO DAJU 1. EPO-OBO TI IGI RE KU FUN RA RE 2. ASO-AGBA MOKANLELOGUN(21) 3. EWE-AJE-OBALE TUTU TO JE TOOJO 4. EPO-IGI NLA 5. EWE-EGELE TUTU TO JE TOOJO ao gun awon eroja yi papo mo ose, lai si aso-agba ati epo-nla yen nibe. ao ko ose yen sinu isasun titun kan to ni ideri, ao wa lo epo-igi nla yen,ao ku si ose yen lori bi elubo, ao wa fi aso-agba yen gun ose yen lori ni eyo kookan. ao de isasun yen pa. ao gbe sinu ora kan, ao so, ao lo bo mole lorita meta fun ojo meje. ao lo wu leyin ojo keje, ao ma fiwe ki a to sun lale. ABORU, ABOYE, ABO-SISE. 1 Like 1 Share |
Re: .. by ademotech: 12:53pm On Jan 06, 2017 |
Ifankaleluya:ejor kini molese |
Re: .. by Ifankaleluya: 1:24pm On Jan 06, 2017 |
ademotech: E lo re wa EWE-AJABO(eku gogoro ni a n pe bayen). e gbo ninu omi ti e le fi we ni e kan soso ni aro kutukutu, ki e wa ju epo igi-nla di e sinu omi yen ki e gba omi yen si ibi ti o tile ri sanmo lati aro yen di ale. ki e wa ra AJAPE eran oruko, ki e ko sinu awo-abokadale, ki e bu epo pupa si lori, ki e wa se adura si wipe Oso lo ba fe bayin ja ni, aje lo ba fe ba yin ja ni gbogbo ajogun kajogun to ba fe koju ija si yin lati de yin mole lona kan tabi lona miran, odidi eran ni e ti pa fun won yi, ki won jowo ki won yonda yin. eo ti wa efun ati osun sile, eo lo papo, eo fi omi di e po, eo wa fi pa ese yin lati orunkun da atelese, eo wa lo gbe ipese yi si orita-meta lale ti gbogbo eniyan ba wole sun tan. pi pada ti e ba pada wo inu ile ni eo wa fi omi ti e ti gbo ewe-ajabo ninu re yen sin gbogbo ara yin ti eo si wole sun. NB; Ti ile ba mo laro ojo-keji, e gbiyanju lati se saara fun afoju meje. Pelu ogo-olohun, eo si ja Ajabo ninu odun yi, e ki yio ri ohun ti yio da yin gunle tabi ogun atimo(do do mi). Ase! 1 Like |
Re: .. by Nobody: 4:41pm On Jan 06, 2017 |
Ifankaleluya: E se pupo, won o dape fun mi rara. Mo ri awure dalute na ninu awon iwe grandpa ko fun mi, sugbon emi ko mo iwulo re... to rire ni mo se bere. Awon eroja ise nah Le lati ri pupo!....sugbon mole dan wo ti mo ba ri awon eroja re pe . Eyin agba leso wipe "Oju orun to eye fo laifi ara kan arawon". danwo lobi iya okere thanks sir. |
Re: .. by belatoxx: 6:40pm On Jan 06, 2017 |
Baba 08101646045atwp(m) ko si akole kan kan lo ri ise yi ejowo e fi akole si Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:02am On Dec 15, 2016 Ni bai ao fi epo obo Tele ape, ao Ko eeru alamon le Lori AO Ko ewe ewuro oojo ati ewe eyeoba le ao bu omi totowe si ao gbe ka ori Ina Ni ago kan osan gerege, ao we Ni ago kan oru nitori Ti ide baja ona asi Ti ona basi arisiki owo awole (Quote) (Report) (Like) (Share) Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:11am On Dec 15, 2016 Bakan na ao lo kafura pelebe merin ati epo obo ao fi omi Idi igbin poo, ao maawe Ni igba kan Ni odun N.B:- ao fi oseyi si ori kan-nkan meta, ao kunle ao we ikan, ao naro ao we ikan, ao joko ao we iketa, ao ju kan'nkan na nu, ao we be Ni ekan Ni ose akoko ose keji ati iketa, eyi Ti otun Ku odi odun miran, abawon kankan koleefo Mon eniyan Ajuwase o (Quote) (Report) (Like) (Share) Re: .. by 08101646045atwp(m): 10:16am On Dec 15, 2016 HMMM eyin pepeiye mewa, eyin adie ibile mewa, a o Jo eyin mejeji sinu awo olomori funfun, ao bu iyo die si, ose lux funfun mewa, ao ha , ao ko sinu re. Ao jeki ore di ojo keji,. A o po po ninu awo yen nibe, ao ma fi we. . N.B:- ( JOWO MASE FUN ENIA LO NINU OSE YIO ). |
(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (99) (Reply)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 88 |