Stats: 3,233,186 members, 8,093,391 topics. Date: Tuesday, 04 March 2025 at 01:39 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Religion / Ẹṣẹ (603 Views)
(1) (Reply)
Ẹṣẹ by Larrystan(f): 11:15am On Sep 16, 2013 |
Ádari ti o ba fi aye gba ẹṣẹ ati aigbọran nitori ẹni ti ọrọ kan jẹ ẹni ti on nawo si Ṣọọṣi ba dẹṣẹ,a màa sọrọ àanu,sugbọn ti o ba jẹ ẹlomiran, ako patiyẹ bo o. Iru adari naa ti gbagbe pe awọn eniyan,pàapàa awọn aṣẹṣẹ di onigbagbọ n wo wọn. |
Re: Ẹṣẹ by PastorOluT(m): 7:08pm On Sep 16, 2013 |
Larrystan: Ádari ti o ba fi aye gba ẹṣẹ ati aigbọran nitori ẹni ti ọrọ kan jẹ ẹni ti on nawo si Ṣọọṣi ba dẹṣẹ,a màa sọrọ àanu,sugbọn ti o ba jẹ ẹlomiran, ako patiyẹ bo o. Iru adari naa ti gbagbe pe awọn eniyan,pàapàa awọn aṣẹṣẹ di onigbagbọ n wo wọn. ese ma n fa iparun fun enikeni to ba n fi sere! 1 Like |
(1) (Reply)
Is Truth Relative Or Is There Just One Truth? / Are All Nairalanders Humans ? / Strange Message And Image Appear In Brasil,pls Moderator Front Page
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2025 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 18 |