Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,190,625 members, 7,941,407 topics. Date: Friday, 06 September 2024 at 06:19 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (84) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (201312 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (81) (82) (83) (84) (85) (86) (87) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 10:58am On Sep 16, 2009
smileyCamalot, Rita, Krayola, ati gbiogbo eyin to ku ti mi o daruko, e ku ojumo eni o wink oruko ti poju paapa sugbon iyen lo daa, a ti so ji a ti wake up, Ti oluwa lase,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:31am On Sep 16, 2009
camelot:

mo ki gbogbo yin nibi bayi, se alafia ni ewa, she gbogbo e n gud ?

alafia la wa jere, se awon booda nse aye ibe daadaa grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:33am On Sep 16, 2009
Orilee9ice:

smileyArgenti, maa binu mi o gbagbe e o, so waa paa!!, tete ba mi daa Topsy lohun o, maa jafara rara o. Good things come to those who make haste (and wait at the same time, lol) ati Posa naa. se ile n'dun, wink

Ose jare ore, awon omoge kan ti e ti ndisitoobu mi, sugbon mo so fun won pe mo ti ni eni ti mo nba sere ife, ki aje tete juwo sile ki won to kidinaapu mi mo lowo o grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 11:36am On Sep 16, 2009
[b]Topsy, [/b]Mr De-hin-de, hummmm  dee-dee o, rora o, (ewo ni ti aye bee daa daa o ti o n'bi awon sisi  wa o, wink )
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 11:39am On Sep 16, 2009
Ose jare ore, awon omoge kan ti e ti ndisitoobu mi, sugbon mo so fun won pe mo ti ni eni ti mo nba sere ife, ki aje tete juwo sile ki won to kidinaapu mi mo lowo o


Topsy: yeah right!!.lol, i like ya style though, maa give up o, o kan see lasan ni , o shi maa gba fun e gbehin gbehin, wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:39am On Sep 16, 2009
Orilee9ice:

[b]Topsy, [/b]Mr De-hin-de, hummmm  dee-dee o, rora o, (ewo ni ti aye bee daa daa o ti o n'bi awon sisi  wa o, wink )

eyin naa leni ki ngo-on-sohun  cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 11:42am On Sep 16, 2009
Orilee9ice:



Topsy: yeah right!!.lol, i like ya style though, maa give up o, o kan see lasan ni , o shi maa gba fun e gbehin gbehin, wink

Omo naa o tie ni sohisi, ti o ba gba fun mi ni ero, a gba ni ele. Mo maa lo si abule wa lo fi ejo e sun awon agba, ko si okunrin ti o maa pe ba soro ife ninu tireedi yi ti o ba gba fun mi tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 11:42am On Sep 16, 2009
Quote from: Orilee9ice on Today at 11:36:06 AM
Topsy, Mr De-hin-de, hummmm  dee-dee o, rora o, (ewo ni ti aye bee daa daa o ti o n'bi awon sisi  wa o,  )


eyin naa leni ki ngo-on-sohun  


.ngo-on-sohun  si argenti, kii se so awon omoge ee miii ti won bo si ori tiredi yi, o gaa fun e o awe, wink grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 11:47am On Sep 16, 2009
Omo naa o tie ni sohisi, ti o ba gba fun mi ni ero, a gba ni ele. Mo maa lo si abule wa lo fi ejo e sun awon agba, ko si okunrin ti o maa pe ba soro ife ninu tireedi yi ti o ba gba fun mi 




Haaaa, Topsy.aseju ni yen o, o ti gbagbe gbolohun ti mo ba e soo lana ni, steady and slow wins the race, eni ti won gbe iyawo bo waa baa kii garun o, ile ni apoti tin joko de idi o, mi o lowo si oro abule o sho mo pe omo olorun (born twice) lemi o,  wink grin maa je kin soro danu o, feti si oro agba ki o lee ba agba jeun po,  wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 12:26pm On Sep 16, 2009
topsy25:

iyawo wa, e se ti orin ti e fun wa, emi ngbadun orin yen lowo wink
Orilee9ice:

TU - awon orin yin dun men!, mo ti bornu won si ori CD kin lee maa gboo ninu moto tin ban lo le leni,  wink ose jare bee ni tie ri, Iya amuludun of "whereva u are, " wink

Inu mi dun pe e n gbadun e wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:05pm On Sep 16, 2009
Orilee9ice:



Haaaa, Topsy.aseju ni yen o, o ti gbagbe gbolohun ti mo ba e soo lana ni, steady and slow wins the race, eni ti won gbe iyawo bo waa baa kii garun o, ile ni apoti tin joko de idi o, mi o lowo si oro abule o sho mo pe omo olorun (born twice) lemi o, wink grin maa je kin soro danu o, feti si oro agba ki o lee ba agba jeun po, wink

Mo ti gbo oro yin sa, nitori awon agba ni: "omo onile a tee jeje, ajeji a tee girigiri", lati eni lo, maa ma le aje sitedili cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 1:06pm On Sep 16, 2009
Orilee9ice:

TU - awon orin yin dun men!, mo ti bornu won si ori CD kin lee maa gboo ninu moto tin ban lo le leni, wink ose jare bee ni tie ri, Iya amuludun of "whereva u are, " wink

Iya amuludun ti ilu ifeleke grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:41pm On Sep 16, 2009
Topsy! .Gbamuuuuuuuu!!, gbosaaa! , bo se waa ni yen o, o ri yen soo jare, sha maa tee sitedili, u will surely get there cheesy wink, maa kanju, anywayz! jaasi baje!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 4:37pm On Sep 16, 2009
Gbogbo ebi mi e maa quiet losan yi kee.
Mon gbadun orin yi lowo,  e gba ki e too woo,

Olorun mi mo waa dupe, Olorun mi mo waa so'pe
Eyin lo'ba to se to ni, Eyin lo'ba to se ta'na, Odaju pe e o see to'la
Olorun mi mo waa dupe

Olorun mi mo ka'le-lu yah, ha-le-lu, ha-lel-u, ha-le-lu o
Mo wa gbe'gba ope, Mo wa rababa, baba mi 
Eyin lo'ba to se to ni, Eyin lo'ba to se ta'na, Odaju pe e o see to'la
Olorun mi mo waa dupe

Ti nu ree baa dun fi jo re gbe jesu gaa o, Gbee gaa!!
Gbe gaa o gbe gaa o gbe jesu gaa Gbee gaa!!
Jesu Peperempe, Peperempe
Choco Milo, Sugar honey
Sugar sugar, peperempe,


E ba mi po'ruko re see. emi ni tin'je emi ni oloruko n'la emi ni ma se beru
Oloruko n'la la la la la la n'la, oyigiyigiyi gi yi gi eda bi e osi
Oba to, to,to, to,to,to, to kari aiye, emi ni emi ni emi ni ma se beru,
wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by argent(f): 5:07pm On Sep 16, 2009
Mr Tope lobi, mo ri owo yin o. E jo omo kekere ni mi, mi o le feyin sir tongue
Gbogbo ile se alafia ni mo ba yin?
Mr 9ice, e ma really nice gan, e tu n ba mr tope toast obinrin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:34pm On Sep 16, 2009
ajenti,
omo luabi joo ma se yen oo. . .
O kin se arobo(omo kekere) oro wa de ti ye e koja bi a se so lo, ki lo fe ka'a se lati fi da e loju wipe atotileto ni wa, awa ko si ninu awon eletan ti won n fi bureedi k'omi ebe lo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by sisiologe1: 6:47pm On Sep 16, 2009
Orilee9ice:

smileyE kaa roo gbogbo eyin temi, see waa paa!! e ku dede iwoyi oh, Our hands are blessed, with the blessing of the Lord, Our hands are blessed, with the blessings of God, Anyone we touch, surely will be blessed, anyone we touched surelly will be healed, our hands are blessed, with the blessings of the Lord, Ohun ti olorub fi si mi lokan lati preach fun yin leni ni yen o, God Bless una bokuboku IJN,

Topsy, Ma wa moto pem pem, maa wa moto. Mo wa lehin e bi ike, wink you don hit my car, oyinbo repete!! smiley wink

Ifeleke, Wetin dey happen, ki lon'sele, kini big deal leni jare, se o waa on the winning side? jesu o ni fi waa sile o wink

TU, Se gbogbo en' bubble wink

Remii. wuz up dude?, edumare a soro waa dayo, ka waa sope lo ku.ha ha ha ha ha haleluyahh! grin

Dayo, [/b]so waa ok ni tie jare, waa paa joooo! wink

[b]e gbo naa a maa gburo [b]sisi ologe
lati joo yin, see kosi, abi a ti fi kiki lee salo ni, grin cheesy[/b]Ire o!!
e se gan ni mr nice mo kuku wa,o kan je wipe ise ni o fun mi laye lati ma wa si ibi ni gbogbo igba,but you wont believe it mo ti take time mi lati read post everybody lori thread yi and mo ti get to know who is who ni ibi bayi,mo ti mo awon good guys,bad guys,saints,devil,introverts ati extroverts,mo de ti mo awon to je wipe oba isokuso ni won,but its a free world so mi o mind lati flow plu anyone who is ready and willing,simply put i come here to mingle and have fun.

mo notice pe its bein a while ti godmother iya ngbali wa si ori thread yi,se ko si sa?mo lero pe alafia ni won wa?anyways na try lati check won out sa

uncle dayo how far?se e wa pa?e ku ojo meta o,awon ara ile nko?e bami ki awon iyawo yin o grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Pweety4me(f): 8:54pm On Sep 16, 2009
*Walk In Singing Iju Fuji La Rin Rin*
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:31pm On Sep 16, 2009
Sisi Ologe eeeeeeeeeeeeeee, Iyangbalife kii ise obinrin o, shine your eyes, mo wi temi oo. Ki oro e ma dabi eniti ode lowo ale to so wipe oun je abibu, lol.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:04am On Sep 17, 2009
uncle dayo how far?se e wa pa?e ku ojo meta o,awon ara ile nko?e bami ki awon iyawo yin o


Ko si iyawo o a an wo oju olorun ni o. ati tubabie
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:49am On Sep 17, 2009
dayokanu:



Ko si iyawo o a an wo oju olorun ni o. ati tubabie

Ngbo tubabie, woo se fun dayokanu oo, rflamao.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 7:26am On Sep 17, 2009
^^^ Hehehehe rara o , Nkan ti Dayo mean nipe emi naa n baa gbadura fun Iyawo rere.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:58am On Sep 17, 2009
tubabie:

^^^ Hehehehe rara o , Nkan ti Dayo mean nipe emi naa n baa gbadura fun Iyawo rere.

Ko yaa je be o, bi bee ko, mo maa ji dayo gbe ni angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 9:20am On Sep 17, 2009
Eyin eeyan mi, ki lon sele?

dayokanu:



Ko si iyawo o a an wo oju olorun ni o. ati tubabie
Ye'e paro m'olorun, baba ti pese opolopo fun e, iwo sa'a ti dekun ojukokoro e. . .

sisi ologe,
bawo ni,o to jo meta,se alaafia lo wa? ooto oro ni remii n ba e so.
tu,
Me'e ro de oo

Gbogbo ile(Dayo,tope-lobi,remii,tubabie,sis ologe,kamoteesi,orile,posa,ajenti,kamelooti. . .a.b.b.l.)
Eku ojumo, Ire ni loni ooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:45am On Sep 17, 2009
tubabie:

^^^ Hehehehe rara o , Nkan ti Dayo mean nipe emi naa n baa gbadura fun Iyawo rere.

Yoruba mi mehe ko ni yen? O ya, dayokanu soro ponbele ka mo n too wi.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:39am On Sep 17, 2009
Ekaaro ein eyan mi smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:40am On Sep 17, 2009
Remii:

Yoruba mi mehe ko ni yen? O ya, dayokanu soro ponbele ka mo n too wi.

Dayo o le yoju sibi, enu lo ni bi ti ajakara tongue
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:41am On Sep 17, 2009
tubabie:

Ekaaro ein eyan mi smiley

Kaaro o iyawo wa grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 10:44am On Sep 17, 2009
e kuu de de iwoyi eyin ebi mi.se e waa paa loni,

Argenti:
o se jare, mo man 9ice bee lee kan kan!!, sugbon ti won baa to mi ni ja, humm maa soo moo ni o, mo leee baje!!. ka maa rii, cheesy, we would not se fire in di welli o, amen!!  mo ni kin baa Topsy pa enu po baa e soro ni pe ki o woo see funnnnn, maa ro iwa e, think of the blissful years you will have togeda, grin, ki o si roo gbogbo 9iceness temi naa,

Sisi Ologe
wA PAA JARE, e ku ise o, e maa jeki ise gbo mi o e fi suru sii o, God will crown your efforts with success IJN, ALADE OGO, ALADE OGO, o gbe go kari ogo, aladeogo maa wo lee oo

What is dis i am a reading about Iyangbalife jare o, se naa man abi naa woman sef shocked, eyin guys ati guyresses, over to you oh, e laa mi loo'yee o, undecided

Tu
Eyin naa nko o, see  e waa pa, adura yin naa a gba o . amin

Ifeleke
Whats cookin' ma brotha? wuzzzzz up dude??  u ok man??se niposti shin sise le'ko ni?

Gbogbo eyin too ku, Edumare a da yin lohun nibi koko yin loni lagba jesu o.amin!!  that is  di koko of my exhortation 2day, Gbossa!!
Ire o!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:46am On Sep 17, 2009
topsy25:

Kaaro o iyawo wa grin

Eyin wo ni yen? E te slow o cool



@Orile
I see you , bawo ni?

(1) (2) (3) ... (81) (82) (83) (84) (85) (86) (87) ... (100)

Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 49
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.