Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,178,827 members, 7,906,039 topics. Date: Wednesday, 31 July 2024 at 12:55 AM

Yoruba Proverbs - Education - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Education / Yoruba Proverbs (706 Views)

This Proverbs Are Bad For You!!! / Pete Edochie's Collections Of Proverbs / Pete Edochie's Collection Of Proverbs (2) (3) (4)

(1) (Reply)

Yoruba Proverbs by joeysunrise(m): 8:39pm On Oct 12, 2015
O rí àgbébọ̀ adìyẹ lọ́jà o sáré si. Ì bá jẹ́ pé ó ńyé ogún tó ńpa ogún ṣé aládìyẹ yóò tàá? / You rushed to buy a full-grown chicken you saw in the market. Had it been top-notch in laying and breeding, would the owner have sold it?

Adìyẹ ńjẹ yangan, ó ńmu omi ó ńgb'ókùúta mì, ó tún ńsunkún àìléyín. Ṣé òbúkọ tó léyín ńjẹ irin ni? / Hens eat corns, drink water & swallow stones, yet lament lacking teeth. Do goats eat pieces of iron with theirs? [Contentment is crucial]

Òkò tí a bá bínú jù kìí pẹyẹ. /A stone thrown at a bird in anger can't kill the bird.[Actions taken in anger seldom achieve desired results]

If a father gets so angry as to throw his child into a raid of army ants, by the time he's appeased the ants may not be.[Don't act in anger]

Ìràwọ̀ ọ̀sán gangan tó ohun tí gbogbo àwọn àgbàlagbà ńpéjọ wò /A star that shows up in the afternoon merits the attention of all the elders.

Àgbẹ̀ tí kòkó ẹ̀ yè, kìí ṣe mímọ̀ọ́ ṣe ẹ̀, bíkòṣe Elédùà / A farmer with a thriving cocoa farm owes this not just to his effort, but to God.

Tí àdúrà bá gbà tán, apá aládúrà ò ní ka. / When a prayer is answered, the person who prayed will be overwhelmed. [Prayers work]

Nínú ìkòkò dúdú ni ẹ̀kọ funfun ti ńjáde. / The pot may be black, yet out of it comes the white corn meal. [Write-off no one]

Ọ̀nà ò ní jìn kó má lóòpin. / A road cannot be so far and not have an end. [Nothing lasts forever; keep hope alive]

Wúrà tó máa dán, á la iná kọjá. / A piece of gold that wants to shine must be passed through fire. [No pains, no gains; don't give up!]

(1) (Reply)

Photo: New Trick Students Disguised To Cheat During Exams / Abraham Lincoln’s Letter To His Son’s Headmaster / Meet Nike Okundaye, A Nigerian With No Formal Education, But Lectures At Harvard

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 7
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.