Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,168,909 members, 7,872,948 topics. Date: Thursday, 27 June 2024 at 05:07 AM

Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! - Politics - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! (1800 Views)

How-to-stop-honourable-kosi-nkankan-syndrome-i / Obiano Likely To Decamp To APC If He Wins & After Swearing In - Aye Dee / Aye Dee: Nigerians Being Lied To, Buhari & Governors Didn't Meet At Abuja House (2) (3) (4)

(1) (Reply) (Go Down)

Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by oyinkinola: 10:15pm On Apr 28, 2016
...Gbogbo oro nigeria pata, toun ogun, oun rogbodiyan, se te ba s'oloriologun ta fi se ogun ran, lo ba ndari ilu nko,nkan iba ma ti see!
too, Olorun eleda nigerian, ori talaka, oyun 'nu oun asee idi, ni yoo ko nigeria yo lowo awon otafa so ke yido bori, ti won nro peleda o ra won!
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ajepako(f): 10:54pm On Apr 28, 2016
Olorun eleda a ko wa yo ninu gbogbo sibasibo yii

Sugbon sha ogbeni Oyin... buhari la maa pariwo e..

Nitoripe oun ni olori...

Bi ori ba shey mo ni fila re a shey mo..

lree oh...

1 Like 1 Share

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by oyinkinola: 12:21am On Apr 29, 2016
ajepako:
Olorun eleda a ko wa yo ninu gbogbo sibasibo yii

Sugbon sha ogbeni Oyin... buhari la maa pariwo e..

Nitoripe oun ni olori...

Bi ori ba shey mo ni fila re a shey mo..

lree oh...
koko oro kn le tun so yi , nje ko a si to ka fise yin onse bi?
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by iamrealdeji(m): 12:34am On Apr 29, 2016
Afi ki amaa fun Ogagun Buhari ni adura,nnkan to nilo lowo lowo bayii niyen,o ti gbiyanju gaan lenu igba ti ode ibi,ko kan pariwo ni
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by porka: 6:42am On Apr 29, 2016
Toooo, nje kinni kati se ti oro awon Fulani ti won dubu omo eniyan bi eni dubu rago bayi?

Bee won ni elede kan nan ni won pelu Buhari.

Nje kilode ti kole bawon wi?

Se odara bi awon Fulani yi sen pa awon eleya miran ni ipakupa bi eni pa ewure lasan ki Aare orile ede o dake lai bikita?

Se eje omo eniyan ko jamo nkankan mon ni?
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Histrings08(m): 7:07am On Apr 29, 2016
porka:
Toooo, nje kinni kati se ti oro awon Fulani ti won dubu omo eniyan bi eni dubu rago bayi?

Bee won ni elede kan nan ni won pelu Buhari.

Nje kilode ti kole bawon wi?

Se odara bi awon Fulani yi sen pa awon eleya miran ni ipakupa bi eni pa ewure lasan ki Aare orile ede o dake lai bikita?

Se eje omo eniyan ko jamo nkankan mon ni?

ooto oro ni o so ore, amo, kilo de ti awon gomina ipinle naa dake ti won o se nkankan si oro yi ko to dipe o di rannto bayi?
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by smsshola(m): 7:25am On Apr 29, 2016
I wish I understand ds write up....
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by trailblaiza(m): 7:26am On Apr 29, 2016
Inu mi dun lopolopo pelu topiki yi. E o ri pe awon omo iran kiran yen o ni le so isokuso ti won ma n so nitori ede abinibi wa la fi n jiroro l'ori tredi yi.

L'ori oro Aare orile ede wa, e ma je ki a tan ara wa, ogagun na n gbiyanju gidi gan, o si n gbiyanju l'osan l'oru lati ri pe aye de gbogbo eniyan l'orun, ati olowo o, ati mekunu. Gege bi eyin na ti mo, nkan ti baje gidi gan l'abe Aare to wa ni be tele.

Gbogbo irin ajo ti Aare orile ede wa n rin kiri, emi ni igbagbo pe gbogbo re ni yio ja is daada. Mo si tun ni igbabo pe logan ti Aare ba ti bu owo lu bojeti ti odun yi, ogun gbogbo yio bere si ni lojutu die die.

Eyin omo iya mi, e dakun e je ki a ma fi adura ran Aare l'owo. Epe o ran nkankan. E ma se je ka da bi awon omo ale ti won ma n fi owo osi juwe ile baba won, awon omo ti won ma n fi ipa ji baba won.
Ohun ti o dara n fe adura, eyi to is ku die kato na n fe adura. Ire ooo!

5 Likes

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by lebienconnu: 8:20am On Apr 29, 2016
Gegebi enikan ti so tele, tireedi yi dara pupopupo o si dun momi ninu gidi gan. Nitipaapa julo, awon omo ajeiutamamumi ki yoo ni anfani lati so isokuso gegebi won ti ma n'so.

Eyin ara , adura ni ki ejeki afi maa ran aare lowo.
Nipati oro awon fulani adaranje ti won so ara won di agbesumomi ti won pa awon eniyan bi eni n p'eran odami mi loju wipe aare yoo wa nkan se si laipe yoo si di afisehin ti eegun n fiso.

Lakotan,awon oniroyin ni ipa pupo lati ko nipa itesiwaju orile ede yii. Oye ki won maa fi opolo pipe ko iroyin won.
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by clinchers(f): 8:33am On Apr 29, 2016
Erin pami lopolopo,,eleyi ga gan
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Nobody: 8:37am On Apr 29, 2016
LMAO
All this long Yoruba grammar grin grin grin
Don't worry, "change ti de"

1 Like

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by princemillla(m): 9:23am On Apr 29, 2016
Oyikin Opolo re pe pere pere. Bi oti fi ede abinibi gbe iji roro yi kale. Ko ba ti da ju ti abani ipekun kan lori nairaland fun iji roro lede oodua
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ArmedRobber: 10:45am On Apr 29, 2016
Afi ki gbogbo omo ile karo o jire mura sile ,dugbe dugbe to u n fi loke yii o gbodo ja le wa lori..

Oro awon fulani ti won dubu awon eyan yii, o ni lo ka mu ra sile ntori ojo idagiri..

1 Like

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by biafransoul: 10:57am On Apr 29, 2016
E je ki ama tan ara wa je. Awon Omo Fulani pelu olori ede wa mo nkan ti won nse. Awon aiye, eri pe Buhari gan o let soro so ke mo bi ti se tele ri. Eje ki amura dada, a si gbodo gba ki won gba ile wa fun grazing reserve won ni tori ibi ti gbogbo oro yi nlo niyen. Ese eyin ara

1 Like

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ArmedRobber: 11:07am On Apr 29, 2016
biafransoul:
E je ki ama tan ara wa je. Awon Omo Fulani pelu olori ede wa mo nkan ti won nse. Awon aiye, eri pe Buhari gan o let soro so ke mo bi ti se tele ri. Eje ki amura dada, a si gbodo gba ki won gba ile wa fun grazing reserve won ni tori ibi ti gbogbo oro yi nlo niyen. Ese eyin ara

Ogbeni mi o ro pe awon mujemuje won je awon ti daeranko looto, won ko n fi oruko na boju nii, janduku ni won je won kii se aderan

Oro billi girazing yii to to nkan ti a n yo ada sii, awon gomino wa ti je ko ye ile igbimo asofin pe ko le e bosi rara..enikeni ti o ba ni ilo ile ki wo kan is gomino ile Na.
Koju be lo
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by oyinkinola: 9:30am On Aug 05, 2016
ArmedRobber:


Ogbeni mi o ro pe awon mujemuje won je awon ti daeranko looto, won ko n fi oruko na boju nii, janduku ni won je won kii se aderan

Oro billi girazing yii to to nkan ti a n yo ada sii, awon gomino wa ti je ko ye ile igbimo asofin pe ko le e bosi rara..enikeni ti o ba ni ilo ile ki wo kan is gomino ile Na.
Koju be lo
o seun omoluabi
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by buharisbae(f): 9:50am On Aug 05, 2016
Afonjas village meeting grin grin kikiki what are this ofe people saying na? cheesy

1 Like

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by buharisbae(f): 9:51am On Aug 05, 2016
eyin afonjas elogbon rarara grin
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ajebuter(f): 10:22am On Aug 05, 2016
buharisbae:
Afonjas village meeting grin grin kikiki what are this ofe people saying na? cheesy

E maa WO kobokobo alainiran to nfi ipa ji awon obi e Lori beedi..

Alaileko omo inaki...

3 Likes 1 Share

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by buharisbae(f): 10:32am On Aug 05, 2016
ajebuter:


E maa WO kobokobo alainiran to nfi ipa ji awon obi e Lori beedi..

Alaileko omo inaki...

undecided what's this ewedu guy saying?

Abeg carry your ngbatingba.ti gerraoutta my site!

3 Likes

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by janvier27(m): 10:41am On Aug 05, 2016
Won ti de o..pelu isokuso. Ewo anti loke.
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ajebuter(f): 10:47am On Aug 05, 2016
buharisbae:


undecided what's this ewedu guy saying?

Abeg carry your ngbatingba.ti gerraoutta my site!

Alafishe.. why did you enter our Yoruba n gbati thread?

lf you are so pained, you could have just opened a thread in your mother tongue...l( lf you have any) instead of constituting a nuisance on mature people's discussion..

Aburo ogunfe..

2 Likes 2 Shares

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by ajebuter(f): 10:49am On Aug 05, 2016
janvier27:
Won ti de o..pelu isokuso. Ewo anti loke.

Ma shey iyonu omo Iya...mo ti ki iponri iyalaya e fun

1 Like 1 Share

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Theultimate(m): 11:14am On Aug 05, 2016
@ trailblaiza, trailblaiza, lebienconnu, ajebuter.
Inu mi naa dun lopo-lopo nigbati mo ri ona ti e fi gbe ede abinibi wa kale. E ku ise opolo.
Amo oo, mo se akiyesi awon ohun kan ti a lee ko ni ede Yoruba pelu.
Fun apere:
Tiredi: Akori tabi Akole.(Ko da a tun le pe ni "Oro T'ohun Lo"wink
Topiki: Akole tabi Akori ba kan naa.
Bojetii: Eto Isuna
Beedi: Ibusun.

N ko ta ko yin oo, mo kan ko won jade fun itesiwaju ede wa ni. E se pupo!

1 Like

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Badtman(m): 11:18am On Aug 05, 2016
Awon Omo irankiran, Awon Omo Olojukokoro, Eru Yoruba le sheyku
buharisbae:
eyin afonjas elogbon rarara grin
Awon Omo irankiran, Awon Omo Olojukokoro, Eru Yoruba le sheyku
Eleribu Omo

1 Like 1 Share

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Nobody: 11:18am On Aug 05, 2016
buharisbae:


undecided what's this ewedu guy saying?

Abeg carry your ngbatingba.ti gerraoutta my site!
Abi ipabe omo, ofo bi omi efo, nibo lo ti jawa?

1 Like 1 Share

Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by Nobody: 11:40am On Aug 05, 2016
Forum
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by banni2000: 12:09pm On Aug 05, 2016
PMB nikan lofe dada fun ilu yii, ole ni awon tokun
Re: Gbogbo Aye Si Ntun Npariwo Pe Buhari O Se Nkankan! by OkoNDOoBo: 12:38pm On Aug 05, 2016
Eyin omo iyami.

Mo kiyin lopolopo, eku iforo jomitoro oro,oro ilu da bi owe awon gba to sowipe , ikoko ti o ba ma je ata idi re a gbona dada.
Ifowo sowopo wa ni ijoba apapo nilo lasiko yi, ijoba buhari ni ero dada fun Ilu wa,adura ti a ma gba nipe ki eledumare fun se.
Kii awon madaru ati obayeje ma ba ijoba e je.

(1) (Reply)

Herdsmen: We Are Being Suffocated In Benue, Gov Cries Out / Official !! Fuel To Sell At 130 / Litre From Today!! / To Have Stable Electricity, Vote Out PDP - Fashola

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 30
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.