Stats: 3,171,168 members, 7,880,652 topics. Date: Thursday, 04 July 2024 at 11:46 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (378410 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (98) (99) (100) (101) (102) (103) (104) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 8:18pm On Aug 14, 2007 |
E kale o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:39pm On Aug 14, 2007 |
omoge nana bawo ni o? se ariya nlo. awon oluko ati omo ile iwe nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by satan: 9:25pm On Aug 14, 2007 |
Singing Akon![sup][/sup] Nobody WANNA "C" us together ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 7:58am On Aug 16, 2007 |
LOL.iyen de derin pami. @richylaw---------kin lon pe mi tele? ![]() ![]() ![]() akata kan tio mono ile mo? ogidi omo yoruba ni mio.lol. maje ki gbogbo iyen ya e lenu,mosun mo awon agbalagba daada. fact pe mo wa used mo asha won nibibai o mean pe kin so temi da sigbo now,o get. infact moma fi orokun mejeeji kunle timo ba riyin---iyen te ba fe bee. omo ale eniyan lon fowo osi juwe ile baba e. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 10:11am On Aug 16, 2007 |
Minute Inu mi dun gan ni si oro isiri ti o tun ju si ori afefe yi o. La i si ani ani mo ti ri mo daju wipe iwo kii se akata tabi ajereke rara. Sugbon dakun o ti o ba ri mi, o le ya o lenu wipe eni ti wa di mo ni mo ma je ati wipe kikunle yen, awon agba ti o tun n be niwaju temi ni o wa fun o ![]() Tafari ,olodo oba omo ateni gbore, o ku afiyesi, o si tun ku akiitiyan. sebi bokun o ba gbe okiki re o ni tan! b'osa o ba fa ariwo oruko re ko ni rinle Gudugudu loba awon omele wonsiwonsi loba awon sekere Iyun loba ileke o ti da ju Awoko loloba orin Paapin bayi lolori awon fila Tanganran si ni oga awon awo Ori bayi la o ma je o , a o ni di iru lagbara Aseda aye, omimimile mi 'gi oko karakara, baba mi a dakeje fowo sa gbeji. Awon oke ohun ni ko fe ja ka ri tihin o, sugbon ara le koko ni bi ota. Mo ti pada de si ori igunwa bayi o. Ka jo ma a 'rocky' loku. Aye wa o ni polukurumusu o A o ni jeegun kehin eran. A o kere oko de ile o ASE. Gbogbo ara aba, lokunrin lobinrin, lomode ati lagba mo ki i yin ni tesoteso , mo ki yin ni tologuntologun. Mishoo, Desorlah,Segoye,Nana,Ayanjide, Omoge, Aloib, Disguy, Debosky ati gbogbo oju titun; Akotun la o ma ji siire o lagbara B'ami oke. Agbe a ma gbere pade olokun o Aluko a ma gbere pade olosa Eyin lakeke foro si Eyin ni kuluso n fi se fuja lawujo Bo ti le je wipe iwaju bayi l'oka foro ti e si Oro aye o ni ta wa o ARAN (Velvet) LA O MA DA, A O NI D'ARAN (crime) o IRE. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 2:00pm On Aug 16, 2007 |
@richylaw Oluwa Ohh! ![]() ![]() ![]() Eeyan lo gbo ede abinibi to bayi. ![]() ![]() Aaaah! richylaw mo juba o! Abi ogbon kan wa te n tasi ni? ![]() Oodua a tunbo maa gbe wa oh! Ase!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 2:06pm On Aug 16, 2007 |
iyeen gangan ni mofe ko. kini won pe yen? raara sisun ? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:16pm On Aug 16, 2007 |
Iya oooooooo, Iya ni wura mi o Baba ni dingi o Ololu fe mi Iya oooo, iya Iya ni wura mi oo Baba ni dingi o Ololufemi, ololufemi humming and whistling Iya oooo, iya iya ni wura mi o baba ni dingi oooo ololufemi Eka ro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:19pm On Aug 16, 2007 |
E ku ile ooo!! Ha Omoge Iseju, se alafia ni ile wa?? Bolarge, e kabo si abule wa yio. Baale Richy, e ka alaye, e ku ise opolo. E si tun ku laakaye!! Ibi ti e ti n mu ogbon ko ni sofo oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:21pm On Aug 16, 2007 |
thank you e se o mishoo. dadaa ni mo wa ![]() still humming Iya oooo, iya iya ni wura mi oo baba ni dingi ooo ololufemi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:33pm On Aug 16, 2007 |
omoge: Se ayun iya n yun e ni abi ti ololufe ?? nitori mejeji ni o wa ninu orin re. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:37pm On Aug 16, 2007 |
lol ki le fe mo? still hummying iya oo and making onje aro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:48pm On Aug 16, 2007 |
O da, e je ka jo nigba na. Excuse me dance !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 2:49pm On Aug 16, 2007 |
@ omoge ----she kosi nkan mii nbe sha pelu orin iyaniwura e yii laaro kutukutu.good moring to u. ese ouje ti wa naa moo. @mishoo--adupe. eyin nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:57pm On Aug 16, 2007 |
Mishoo, Omoge, Minute ati Bolarge mo ki yin kaabo si aagbon pataki yio. O se owo olosan ni agbegbe ti mo wa , sugbon mo mo wipe awon kan sese n ji ni, bee si ni ojo n re bi ana lodo awon elomiran :Ise Olodumare awamaridi ni Omo Oduduwa e gbonra jigi e je ka sise ori ran wa. Bolarge:Ola Oluwa ajenjetan. Imo (wisdom) Oluwa abu mu mo fa n'ikoko(water pot) Laakaye Eledumare o ni won gbobgo wa o. Ko si ogbon kan ti o tun yato si wipe mo gbo (understand), mo ka (studied) ,mo gba (accepted and give regards), mo si mu ewa ede abinibi mi lo gege bii iwonba rebete ti Olorun yonda fun mi ninu ogbon. Ore wa Bolarge, ko wa a ti pe ju , bi o ba wu o , o le da bi mi! o si tun le gbo ede yi ju emi na lo. Kiko ni mi mo minute:Eyi ti o ri ti mo ko yen kii see Rara o, aroko oro iwuri lasanlasan ti ko ni amulumola ninu ni a lee kaa si. Jara mo ko ti pe ju, orun to wa loke yio sa aso gbe Iya , iya mi, mo n re ile oko Loni , loni idi mi di idi ileke Olomoge n lo di abileko Oju mi yeso , o kuro ni t'omidan huh huh huh ![]() ![]() ![]() Eleyi ni a le pe ni Rara eyi ti a le lo lati fi sun ekun iyawo. cheers all. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 3:03pm On Aug 16, 2007 |
@ minute if you woke up with a song on your mind, sing it. se o get mi? ![]() ![]() humming kuluso kuluso |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:11pm On Aug 16, 2007 |
Richy, e se o jere!! Se ni omoge kan n da korin ni, Ko ti e fe bami jo. Omoge, ma da nikan jo mo now !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 3:18pm On Aug 16, 2007 |
@ richy--onye mii die die.thanks i'll talk to my grandma to teach me as much as she can when she gets here. @omoge do what u've got to do babe.enitokan lomo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:20pm On Aug 16, 2007 |
omoge jowo iwona ba Mishoo jo now, ara o sa gbodo sa fara! ![]()
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:38pm On Aug 16, 2007 |
Baale, mo n gbadun yin jo !! Ko ma lo be e !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 3:52pm On Aug 16, 2007 |
CALL TO GLORY With gratitude to God for a life Deacon Obowunmi,we love you but God loves you most, continue to rest in the bossom of the Lord He is survived by, Chief mrs obowunmi okogbona okosegun obowunmi okorenle obowunmi okobukola obowunmi okoseni obowunmi okotola obowunmi obonbiwinninu obowunmi okonbiwoninu obowunmi okorenle obowunmi for the family
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:17pm On Aug 16, 2007 |
OMG !! ![]() ![]() ![]() The 'Son of a Gun' is back with another name !!! Shakes Head and temporarilly leaves the thread !!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 4:25pm On Aug 16, 2007 |
so disrespestful. now i have an idea of who seun was talkn about. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 4:27pm On Aug 16, 2007 |
LOL iyen ti ju oju mi lo ![]() mishoo, ![]() richy ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by divanaija1: 4:43pm On Aug 16, 2007 |
YEPAA!! ![]() ![]() Koda rara o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:44pm On Aug 16, 2007 |
Minute,what are u doing here? Tot u were enjoying the fishy thread ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 4:44pm On Aug 16, 2007 |
omoge:Dat one no sweet,abeg check dis one out,it will surely make your day, Peter oluwole babalawo ti won gbojule,o ti sere lo sapele, onisegun ti won feyin ti,o ti sere lo calabar, iwo o logun o,babalawo ma pe e,iwo o logun,o lo lorun oba o, peter o,odofin bello mi omo olola, peter odofin bello o omolola, oluwole mi peter odofin bello ye o e, peter o odofin bello o olola oluwole mi peter odofin bello ye o e, peter o odofin bello o olola, PLAYS INSTRUMENT ayanfe o,mo ba rode,sunny mi shehu o,mo ba rode, ayanfe o moba rode sunny shehu o,mo ba rode, sunny shehu mi atata omo olola, awon to ndite si e,awon to nbinu si e,,oye ka fi to won leti,oye ka fi kan won lara,oye kafi ye won wipe, aso gbere,e ka gbere o, sunny shehu mi atata omo olola,aso gbere e ka gbere o, awo yinka amoje,awo funso mi davies mi, aso gbere,e ka gbere o sunny shehu mi atata omo olola,aso gbere e ka gbere o, PLAYS INSTRUMENT Layiwola amoje mi,amoje mi,baba ni,{2ce} layi amoje,onitemi atata o,akano omo olola, ewure gbo kai,adie ngbo suuuuuuuuuuu,aja ngbo wagba wagba,amoje yi moba rode{2ce} iwa rere leso enia,lofi mujo aguda,lo fi,fi baba joye,won fi baba joye, sir,knight amoje, toba ni mowa mo wi o,toba ni mowa, mi o yaju soba mi o dite soba,toba ni mowa mo wi o,e omo adegbenro,beru ba nba yin ewi o, eru o ba omo balogun o, omo balogun o,eru o bomo balogun, awo funso,eru o bomo balogun beru nba yin ewi o, eru o bomo baloguunnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnnn. I JUST FULFILLED MY PROMISE TO YOU,EVEN THOU SOME EVIL FORCES TRIED TO STOP ME,BUT,THEY CANT STOP THE SUN FROM SHINNING. GOD PASS DEM. SO LOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOOONG,ABI NA SO BIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIIG? ANYHOW SA, ONE ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 4:50pm On Aug 16, 2007 |
mishoo:they can only bark,but they can't bite,don't you know that you can't kill the beatle? minute:who was he no be only naija sofa dey ![]()
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by osereka(m): 5:20pm On Aug 16, 2007 |
IYA AJE, KINDLY ANNONCE THE REMEMBRANCE CEREMONY OF OUR BELOVED KINSMAN 'OPURO' WHO WAS Murdered/killed/terminated/BANNED BY THE ALMIGTHY SEUN SOME MONTHS BACK! remember the late OPURO is survived by an only son OSEREKA |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:28pm On Aug 16, 2007 |
Egbe eye lo n to eye lehin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 5:49pm On Aug 16, 2007 |
richylaw:na dat one dem dey call, karin kapo yiye ni nyeni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:03pm On Aug 16, 2007 |
IRIRI AYE, People talking of themselves and thier future, is painful! |
(1) (2) (3) ... (98) (99) (100) (101) (102) (103) (104) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 45 |