Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,181,780 members, 7,915,193 topics. Date: Thursday, 08 August 2024 at 05:59 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (379843 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (100) (101) (102) (103) (104) (105) (106) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:49pm On Aug 17, 2007 |
iyalode ikamefa aka orobo onidi nla ekaabo o! ot'ojo meta ti a ri yin ni adugbo yi o ejowo eme fi idi orobo yin ba aga aafin je o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 10:15pm On Aug 17, 2007 |
debo idi yen lo ri abi ( o dabi eni wipe idi yen n da e lorun) bo ba wu mi maa fi baa je bi o si wu mi maa si ma wo nitemi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:51pm On Aug 17, 2007 |
ejo mi ko o! nigbati idi rabata bii ti yin ba wo afin, nise ni gbogbo awon olopa aafin maa n'lanu le bi apere ejoo o, awon aga to wa ninu aafin je aga owo iyebiye o, Olorun ni mo fi be yin, ema fi idi baaje fun wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 10:54pm On Aug 17, 2007 |
hummmmmmmmmm! oga debo e jowo e sanu aje! e gbe idi mi sile oh! idi ti mo fin pa ote mole niyen oh! bi aga ba baje aa si ra imiran n ko le ri idi miran ra loja oh e jowo e gbemi sile oh! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:57pm On Aug 17, 2007 |
kini itumo 'esaanu aje" iyen je pe aje ni yin ni? ejoo oh, ako gba aje laye lati wonu aafin wa o! mo tun gbo titun lose to koja, won so pe awon onisegun ni ilu oba won le se iparo idi fun awon obirin won pe oruko re ni 'brazillian butt lift' ti eba fe idi to tobi sii, tabi 'liposuction' ti idi yen ba ti di orobo ju nitori naa, ti e ba nilo idi titun, maa fun yin ni numba won ki e le pe won lori ago lati paro idi yen |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 11:02pm On Aug 17, 2007 |
ee shanu aje( commerce) not e shaanu aje(witch) abi o o gbo yoruba mo ni? mi o need liposuction (ora idi fifa) or brazillian butt lift( gbigbe idi soke) " " idi mi ti wa pa bi o se wa yii mi o need number kankan |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 11:04pm On Aug 17, 2007 |
ema binu iyalode, mo kan fe mo dajudaju pe eo kin se aje ni o ti e ba mo awon omidan miran ni aafin ti won nilo idi gbigbe soke tabi fifa ora idi, eso fun won ki won pe mi lori ago. numba mi wa lowo awon asona ni aafin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 11:07pm On Aug 17, 2007 |
aight! mo ti gbagbe wi pe onitsha bixnix man ni e tele maa so fun gbogbo awon omoge laafin |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 1:21am On Aug 18, 2007 |
Eku Ojumo oooooooo! Hummm Ko si party party ni end mi yi oooo, ohun ti mon bo ni:- Owuro lojo, Eni ma ri re ooo, Eni ma ri re ooo, A se owo owuro. , , Ati:- Ise logun Ise, Tera mo ise ore mi, Bi ako ba re ni fehin ti, bi ole lan ri, Baale, ejowo eba mi pari re, mo fe mo gbogbo e in word -by-word kin to pada si Clapham Common. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 1:28am On Aug 18, 2007 |
Aya mi wa ni ile ni hayi, Koda oye ki oti wa si ori alantaku yi lati nkan bi ojo meta kan sehin, sugbon awon Shopping ati visiting ti an se ko fi aye gbawa rara ra, lati de ori alan taku ti a wa ti Gba gege bi ile wa. Sugbon ooo, Desorlah ma to de ba wa lori alantaku yi, notoripe, oni owun fe ba Baale soro lori awon nkan die die ti won ma ni fe si, aya mi n ro wipe kin ra awon nkan asa ibile wa so wo si baale, bo tile jepe Baba yioo gba gbogbo ebun yi ti won ba wa bawa ni London, Though Ose kan ni aya mi yio lo ni london ki o to pada wa, ni to ri ibi ise re ni NG. I miss THE HOUSE! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 2:19am On Aug 18, 2007 |
Alo ooooooo Alo ijo kan wa, ijapa lo si odo. ijapa wa re omoge kan to beautiful da da. ijapa wa so fun alangba pe oun fe omoge yen. be ni ijapa te le omoge lo si nibe ki be ti omoge lo. omoge re ijapa nigba omoge wo eyin. well sha, ma continue tales by electric light me. kin lo je carrot mi ni sin yi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:49am On Aug 20, 2007 |
E kaaro oo!! A a jirebi ?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by divanaija1: 9:55am On Aug 20, 2007 |
Moki everybody lokonko o, E ku Monday o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 10:40am On Aug 20, 2007 |
Baale, Segeoye, Mishoo, Debosky, ika6 gbogbo ilu e ku owuro. agogo to nka wakati ojo, a ka wakati wa si rere o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Bolarge(m): 11:06am On Aug 20, 2007 |
Talo ranti orin kan taa ma nko nigba taa ba nsere ni kekere; ". . . Idi ore mi lemi o fi si, . . . idi ore re jalanjolo. . . ." Ki la nfi sidi ore wa nigba naa gaan? Mo kan ranti orin naa mo si nda rerin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 11:08am On Aug 20, 2007 |
Mo ki Onile,Mo ki Alejo,Mo ki ero ona. Se alafia ni gbogbo yin wa o. Bawo ni opin ose se lo? Gbogbo ara ile nko? Ose yin a san wa si ire,omo,owo ati alafia ti nse baale oro o.Amin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 11:14am On Aug 20, 2007 |
Bolarge:Haba, Okan okunrin Bolarge yi Dudu oo !! Isin ti oju re ti ri okun ati osa lo to n bere nkan ti oun fi si idi ore oun. O da oo. Igi kekere ni a ma n fi si ehin ore wa ni igba na @Nana, bawo ni ara re?? @Tafari, okunrin meta !! Bawo ni nkan?? Awon iyawo nko? Se won n jeun ?? Se omode naa n sere pelu ?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by replenish(f): 5:08pm On Aug 20, 2007 |
mo ki eyin ara mi ti le t'oko o. ekun igbadun, esi ku miliki. se dada ni mo bayi, se ewa bi ewa gege bi emi na se wa . e ma gbadun lo ni so , mo wa leyin yin bi ike. ilu nigeria oni baje o (amin) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 9:25pm On Aug 20, 2007 |
Si ibere Bolarge - Ki la nfi sidi ore wa nigba naa gaan? Okuta ni emi ranti wipe a manfi si ehin (kii se idi nitori awon ti nsere na ma n'joko ni). Orin na si ju bi o ti ko lo E ma w'ehin o , (idahun) w'ehin, w'ehin E ma s'ofofo, ofofo o da Idi ore mi lemi o fi si , idi ore re jalanjolo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 9:26pm On Aug 20, 2007 |
Mo ki onile, mo ki alejo. Se ojo oni mu re wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mashaun(m): 7:53am On Aug 21, 2007 |
nana, awon akata yin nko lohun |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MP007(m): 8:28am On Aug 21, 2007 |
ekaaaa le n be un ooo eyin omo odua, omo yin , aburo yin lon kin yin la ti ipinle texas ni orile ede america, se da da la ba yin o, haaa n kna be ooooo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 8:34am On Aug 21, 2007 |
pele aburo mi, shey ko ye ko ti sun ni? MP007: itumo ni oyibo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dblock(m): 8:42am On Aug 21, 2007 |
Wazzap Shele. Shey alafia ni your life. Shey dada ni you. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 8:45am On Aug 21, 2007 |
dblock: tani shele? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dblock(m): 8:48am On Aug 21, 2007 |
Not much lon shele. Tse like fluent yoruba mi. Nibo ni Asia lewa. Mo rope crib tire wa ni 'badan |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 8:49am On Aug 21, 2007 |
olodo ni e, sheybi mo so fun e pe philippines ni mo wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:51am On Aug 21, 2007 |
E kaaro ooo!! Aloib, Dblock se ara yin le?? Nibo ni Baale wa ?? O to ijo meta !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MP007(m): 8:51am On Aug 21, 2007 |
aloib: haaaa n kan beee, ma word ! things are happening |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:54am On Aug 21, 2007 |
MP007, ki lo n sele ni agbegbe re oo?? Gbe si wa leti !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 8:55am On Aug 21, 2007 |
oya e je ka gist, i'm bored, ohh lol mp typo lo shey, mon wonder pe kini yoruba giberish ti bobo yin so mishoo ko si o, mo shey ti clases dey |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by MP007(m): 9:21am On Aug 21, 2007 |
huricane lon sele ni coast texas oo, eru n ba ni seriously , awon boiz tin sa re way dallas ni sha, ta lo fe ku oooo, huricane yi fi la gbara poooo |
(1) (2) (3) ... (100) (101) (102) (103) (104) (105) (106) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 31 |