Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,174,162 members, 7,890,932 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 01:58 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (378872 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (61) (62) (63) (64) (65) (66) (67) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:10am On Jun 22, 2007 |
kini won se si South Africa ? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:10am On Jun 22, 2007 |
won bu mi ati awon eyan mi, ma de kick ass won ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:12am On Jun 22, 2007 |
fi gbo yen le , fi won le Oluwa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:15am On Jun 22, 2007 |
oluwa would soon intervene, sugbon before that, ma pa gbogbo won da mu |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:16am On Jun 22, 2007 |
ki Olorun gbakoso aye wa |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:19am On Jun 22, 2007 |
olorun ti gbakoso oo, na u remain |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:21am On Jun 22, 2007 |
Oluwa tin gba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:22am On Jun 22, 2007 |
great, so wetin dey happen |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:46am On Jun 22, 2007 |
ko si nkan ton shele |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 1:46pm On Jun 22, 2007 |
Baale Ekaro, ema binu pe ope kin to kan si yin. Ki Iyawo mi to de lana? owo irole daada nitoripe osare se awon ise kan ni ibi ise. Ati jo gbe ro, a de ri wipe ati sun ojo na si waju ni pataki. A fi a ra mo Sir. Ejowo, eba wa so fun ala gogo lati kede Isunsiwaju Iwuye owun di igba ti striki yio fi kase ni le. Ati paapa julo, oye ti mo fe je, oye ile ni, eyen ni wipe, eyi ti ile wa ni striki, yio soro fun mi lati se eto owun ko fun na, Mo fe sare jade fun road walki, tin ba pada wa, ma wa kan siyin ni afin. Ki ara o le o baba. Omo yin ni tooto, Desorlah & Segoye2 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 2:40pm On Jun 22, 2007 |
Wa kick ass won, ope gbenu si ass ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Busybee1: 2:49pm On Jun 22, 2007 |
Desorlah ati segoye2,oye kini jero yin je e |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 7:49pm On Jun 22, 2007 |
e kale o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 7:53pm On Jun 22, 2007 |
ekasan ni ibi o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 8:39pm On Jun 22, 2007 |
e ra eyin eyan mi, Eka ati Jibiti, ko da to to, e she la won neighbor mi ji Cable tv mi ni sha, won ro bi pe awon gbon. Mo Catch won Red handed ni, but mo so ko kon fun won, to ri pe mo mo pe American Nepa, o ni pe Ja ena mi. So won wa ja la ana. e nu wa bi mi pe, mo ni ra ye wo Onlinenigeria Movie ati lo Nairaland, ati cocoradio.com. So emi lo wa ji ena won, but awon o mo. Atleast mo ro be, Won de le gbo ena ye ko sha, Ti gbese won batti wa, ma she adura fun won ki Olorun ba won San.!! e le believe Ena lo gbe mi sha in the process le meta. But its worth it 4 mo wa pe lu yin sin!!! Awon oloshi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Busybee1: 9:27pm On Jun 22, 2007 |
Ur yoruba is poor 2/100.infact eyin ro mi bi mo se n ka.Al RAHEEM |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 9:47pm On Jun 22, 2007 |
ok |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Busybee1: 10:49pm On Jun 22, 2007 |
Are u sure u are a man.because men dont curse |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Busybee1: 11:18pm On Jun 22, 2007 |
Ki lonsele no hard feelings we are just having fun.tell me abt urself sometime we could be frds.3 gbosa 4 u.respect |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 11:23pm On Jun 22, 2007 |
lai laye, impossible. if you're a girl thanks 4 di insult. If you're a guy ma je ki mu e ni nu corner sha, ma gba eti e. She e mi egbe ni ko ma ba she ere. If u are funny it would be natural. You are tryin too hard and settin yourself up. Ore ko, we re ni. Ma ba mi so ro mo ni ile aye e!! I 4give u this once Kan ma ba mi so ro mo. I will delete my harsh reply to u shortly! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 12:14am On Jun 23, 2007 |
Si Busy Bee, Desorlah ati segoye2,oye kini jero yin je eMo ka oro ti oso nipa emi ati iyawo mi desorlah, sugbon ooo. emi fe fi ye o pe atemi ati iyawo mi di i di ma fun o ni esi ni, nitoripe, a n wo oju awon agbalagba ati baale, papa julo awon eyan pataki bi Ikamefa, Nana, omonaija, ayefele, Ikomi, Oba Seun Osewa, Al Reheem, hummmm ati be be lo ni a wo oju wo n to fa ti a fi gbe solo je. Sugbon ooo, jowo jowo, se alaye fun ile daa da yi ohun ti o je ki o pe wa ni JERO. Oro re lori threadi yi ko mu ogbon tabi erin wa ra ra ra, nise ni o mu ibinu ati ija dani. Si Baale, Baba oo, ki ara o le oo, ema binu si ogbenni wa yi o, o ye mi wipe nise lo fe soro basha basha, boti leje wipe, eyin ni omo kekere e n fi ogbon bu, mo ko iru oro re, mo de ti baja, e mase binu si, omo ki n ponu ki a le fun ekun pa. Si Al Raheem, Ma binu si ore wa, omo kekere lo de si, ni sin ti o fe je ore re, wo boya e le je ore ke, True friends fight sometimes. Ati wipe, people are not the same, thats the busy bee way of saying hi. mo ni gbagbo pe aggresive lover ni ogbenni re yi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 12:21am On Jun 23, 2007 |
e ra eyin eyan mi, Bawo lo se se, o ra cable ni ? se o bo wire na mo le sha,? nitori ti o ba se be, oma back fire ooooo, jo take note oooo, de je ki awon ara ile e mo wipe oji ina; ibi ni ina na de gba or else, o le bumarang ooo, ti famili e ba de wa mo baji, ojepe won ti di culprit ni yen ooo, Isn't that dame family fun? having a shared stealing experience! Just kidding |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 2:15am On Jun 23, 2007 |
en ina (or Eno or Electricity) ni mo n ji. To ri wi pe awon neighboir mi lo ji Cable Tv mi. En, ena ye did back fire, o gbe mi(Shock mi)3* nko ti nu fi bi mi si aburo wa fun oro e ni ye. Mo gbo yin na pe aburo wa ni busy bee another irritation of Edi. Awon egbe ti mo like ti won so esokuso ko? God Bless, OmogeNaija, Weslyan, Drusilla, Wise and WizGirls under 18 and many mo bi won!!. Awon ti o ni laikayi=Ayefele, Babyosisi, NossyCheek, awon ode!!older than 18 + or - Busy Bee i'll be watching him/her |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 2:26am On Jun 23, 2007 |
Is nice to know you already forgiven him/her. I want to get back to bed before ki Iyawo mi to ba mi lori net, ki n lo ba ni bedroom. Oda aro Al Raheem, Oda aro busy brain, hummm sorry busy bee just kidding |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 3:52am On Jun 23, 2007 |
Suuru ni aye n gba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 3:57am On Jun 23, 2007 |
mustay bawo ni jare |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 11:09am On Jun 23, 2007 |
ThiefofHearts, Bawo ni, se daada lo ji? oko re n ko? Si Mustay, Looto ni oro re, oro aye gba suru gidigidi, nitori la i si suru, a ma mu ni kose. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 11:46am On Jun 23, 2007 |
oloye segoye2, bawo ni o. eku imura. baale nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 2:20pm On Jun 23, 2007 |
Baale wa laba, sugbon won su lowolowo. Mo wa pa ooo, a ti sun ojo Iwuye ohun si waju oooooo, se baale ti fi to yin leti nigba ti e ba won ni afin? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 8:18pm On Jun 23, 2007 |
A BE BE BI BO BO BU,A BA BABA,A BAAAAAAAA,ABEBI ATI OBE NI ORUKO AWON OMODE MEJI YI,ABEBI WE GELE,OBE SI DE FILA,INAKI NKIGBE ALAO NSA LO,ALADE HUWO,O HUWO, A-AJA,B-BATA,D-DOJE,E-EJO,E-EYE,F-FILA,G-GBAGUDA,H-HAUSA,I-IGI,J-JAGUJAGUN,K-KINIUN,L-LABALABA,M-MALU,N-NAGUDU,O-OGONGO,O-OGEDE,P-PEPEYE,R-RAKUNMI,S-SANGO,T-TAFATAFA,U-UKUUKU,W-WAHALA,Y-YANMUYANMU. 2 hell wid A-FOR APPLE,B-FOR BALL,C FOR CAT etc YORUBA PONBELE,YORUBA ATATA,YORUBA TO JINA,TO MUNA DOKO,OGIDI YORUBA,ODUAAA A GBE WA O. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 10:42pm On Jun 23, 2007 |
bawo ni ? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 12:21am On Jun 24, 2007 |
O ga o! |
(1) (2) (3) ... (61) (62) (63) (64) (65) (66) (67) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 34 |