Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,174,164 members, 7,890,938 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 02:15 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (63) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (378875 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (60) (61) (62) (63) (64) (65) (66) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 3:52pm On Jun 21, 2007
Iyawo mi,

grin Mo wapa daadaa, o de ti to ojometa kan bayi na ooo smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 3:53pm On Jun 21, 2007
O daa be, o le ba baale soro wipe ki won je ki a sun ojo ayeye na sunmo iwaju die nitori strike yi nitori opolopo awon ti won ma wa fun ayeye na ko ni le jaade ni ojo na, emi na a lo so fun awon ore mi wipe a ti sun ojo na si iwaju.

Aa maa fi deti tuntun ti a ba mu to won leti.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 5:54pm On Jun 21, 2007
@ g nature- oníjèkujé nì ehindero ye. Ole buruku.
Awon nkan ta ma fi si lê layè ni won le kaakiri
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 6:18pm On Jun 21, 2007
Sista Ikamefa, ekan san!! mo gbo pe e feran Jerk Chicken, se emo se? abi efe kin fi bi ti e ti le ko won yin?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 6:27pm On Jun 21, 2007
Al Raheem:

Sista Ikamefa, ekan san!!

broda Alraheem e kaa san oh , se daadaa la ba yin oh?


Al Raheem:

mo gbo pe e feran Jerk Chicken,

tani so fun e wipe mo feran jerk chicken?

anyways its true mo like e tongue grin grin grin


Al Raheem:

se emo se? abi efe kin fi bi ti e ti le ko won yin?

mo ni ways ti mo maa fin se temi oh tongue grin

yes oh o le fi han mi oh boya maa le improve recipe titemi

oya link me up jare cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 6:31pm On Jun 21, 2007
Ore mi Raheem,

I nu mi dun si oro re yen, ni bayi ti a n su ojo Iwuye mi siwaju, jowo se ole salaye fun Iyawo mi ibi ti mo ti a tile ri kinni Jark yen? grin ani the meat grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 6:35pm On Jun 21, 2007
yahoozee , yahoo ooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 6:43pm On Jun 21, 2007
Ewo nkan ti mo ri ka lati ori alantaku nigeria. HA! eyi o da ra ra ra, ko bo ju mu oooo.
As the nationwide strike declared by labour unions and the civil society coalition entered the second day today, public hospitals in the country have started discharging their patients due to the absence of doctors and nurses. Investigations at some of the public hospitals in Lagos, Oyo and Delta states, this morning revealed that the authorities had asked families and relatives of patients to come and remove them as a result of the absence of critical duty personnel in the hospital.

Si Kateflow,

yahoozee , yahoo ooo
What is this supposed to mean? Se ko n se pe won ba e ja ooo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 6:48pm On Jun 21, 2007
kini mo se
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 6:57pm On Jun 21, 2007
ikedepataki fun eyin temi

mofiwe pe gbogboyin lokunrin, lobinrin, lomode ati ni agbalagba, mo fe joye ni ilu mi. oba fabunmi ti okemsi fe fimi je oye otunba fun awon odo in ilu okemsi iyen ni ipinle ekiti,
ayeye na mawaye ni ojo keje, osu keje odun 2007(7th of july, 2007). papajulo awon , awon temi ni nairaland ti momo bi eni to mowo. richylaw, segoye2, ika6, nana, ati eyin ti mo ranti orukoyin, eyin ti e wa ni okeokun mafi nkan ti yin ranse, fun awon ti won wa ni naijiria jije, mumu ati igbadun lopolopo yio wa, ese oo

OTUNBA ADEMOLA ISRAEL
A.K.A ISRAELITE
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 7:02pm On Jun 21, 2007
kate, ibo longbe ni ikoyi naa, mofe wa kie, lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:02pm On Jun 21, 2007
Ma binu simi, sugbon mo kan ni kin sare bere lowo ire ni, ti ire ba mo oun ti ire n so lowolowo yi. Ati wipe, se oti ri iyawo mi ni osan yi? oda bi enipe a fe sun ojo iwuye wa si waju ooo, bo ti le jepe a ma sofun baale lati bawa ba Oba agba ni pa fi fi ase si isun si waju na. grin

Bawo lo ko tire, tabi ire ne n wa hook up ni hin yi  
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 7:03pm On Jun 21, 2007
@israelite
mo gbe ni glover road
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:07pm On Jun 21, 2007
Oloye titun segoye ,e ku akitiyan o . Gbogbo bi yio se da na la n ba ka, bi a o se  alejo awon lobaloba ati awon eekan ilu ti o bo fun oye re yi na ni a n se o. Nipa ti sisun ojo oye siwaju , nitori iyanse lodi awon osise je ohun kan ti o se pataki. Maa fe ki iwo ati iyawo re ro daadaa ki e si je ki n mo ki ile ola to mo o. Ki a le mo bi a o se se eto.Boya o fe ki a sun siwaju ni tabi beeko.

Mo se akiyesi  iwe ifi pe eniyan ti o te, ko si oruko baale nibe o, ki lode de. Ha ha bi o tile je wipe Oba Seun ni oluaye (oba apapo), Sebi oba Richylaw lo sa n fi o joye abi o ti gbagbe wipe Abobajiroro ni o je ni , le ti yoruba  fun nairaland. E jowo e se atunse o.

Gbogbo ile , eku ikale o. Se enu n gbe yangan?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:13pm On Jun 21, 2007
Isrealite, eniti a ko fe nile re n jina. Atemi ati gbogbo awon lobaloba toku ti o je ore mi ni a jo de okemesi wa ba o keye o. oye a mori o ase.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 7:14pm On Jun 21, 2007
Isrealite, ni agbara olorun gbogbo wa , awon lobaloba ati awon ijoye yio ba o keye de imesi lojo oye re na. Oye a mori o ase
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:27pm On Jun 21, 2007
Si Isrealite,
ikedepataki  fun eyin temi

mofiwe pe gbogboyin lokunrin, lobinrin, lomode ati ni agbalagba, mo fe joye ni ilu mi. oba fabunmi ti okemsi fe fimi je oye otunba fun awon odo in ilu okemsi iyen ni ipinle ekiti,
 ayeye na mawaye ni ojo keje, osu keje odun 2007(7th of july, 2007). papajulo awon , awon temi ni nairaland ti momo bi eni to mowo.   richylaw, segoye2, ika6, nana, ati eyin ti mo ranti orukoyin, eyin ti e wa ni okeokun mafi nkan ti yin ranse, fun awon ti won wa ni naijiria jije, mumu ati igbadun lopolopo yio wa, ese oo
     
                                                                                        OTUNBA ADEMOLA ISRAEL
                                                                                                A.K.A  ISRAELITE
Huummmm Ma ba Iyawo mi soro boya ole wa si ibi ayeye na LIVE!, mo de fe fi ye yin wipe, Sir, mon gbadun yin gan ni oooo. Inu mi de dun wipe, egba ati emi ati Iyawo mi Desorlah gege bi ore Idile yin (famili friendi), ayo na yio kari gbogbo wa oooo, Amin.

SI Baale,

Ori Ido bale ni mo wa. Ema binu si mi lori oro iwe yen, ko da, igbagbe gba lo se mi. Oda bi enipe aya mi fe isun siwaju Iwuye owun nitoripe opolopo awon eyan ti ape lati nigeria oni le wa nitori oro Visa ati bee bee lo. Ati pelu pelu, Strike owun je ti Oni gbe le e, (Indoor), ko da yio pa wa lara gan ni. Ma sare te Iyawo mi ni ago, ma de pada fun yin ni abo, nitori mi o fe se tinu mi nikan, ati wipe, oro ajoso wa nikan ni mo le dimu wipe o se koko nitoripe, owun ne pe awon eyan e fun iwuye owun, a de n wa ohun kan pato lati dimu sinsin ti o je ki a sun ojo na si waju.

Baale, ti a ba fi abo si tan, ejowo e bawa ke si Alagogo ilu wa yi, lati kede re ka kiri ori threadi eyi to ku ooooo,  grin

Eseun baba wa.

Emi ni omo yin,

Segoye2
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 7:36pm On Jun 21, 2007
Bawo ni Segoye, era!  mo lo si store ni. 
Ikamefa, mo learn wi pe o like jerk chicke ni yara post the "pic of the food u like"."LoL"   quest? on je wo lo mo se, ma be wa bi won she se?  Ada la ti mo
http://www.jamaicans.com/cooking/chicken/jerkchicken.htm
http://www.youtube.com/results?search_query=Jerk+Chicken&search=Search
http://www.jamaicatravelandculture.com/the_arts/dancehall_queen.htm  the best 2me
http://www.youtube.com/results?search_query=Chinese+food asian food
http://www.folklife.si.edu/africa/recipes.htm  onje ele ile!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 7:42pm On Jun 21, 2007
Segoye, on ye ma pa mi re rin!! "ani di meat"" Broda mi gba ni yin
Gnature, said ma pe mi ni aburo, mo n she aburo e yan kan!! LOL
goodmens
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 7:45pm On Jun 21, 2007
Ikamefa, iya elewa ati iya agege bread a de fit e?? She mo le ron awon eyan si e? Ki wo n wa si skool e
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:49pm On Jun 21, 2007
Mode mode ni ti ewe ade
mobo mobo ni ti aboye
ewure ile to ni aoni de ni ao ni deba
aguntan ile to ni ao ni bo ni yio nu

eku ile oo
segoye baba bawo ni ose wa?
se arale??
baale nko? o to ijo meta ti mo ti wa si ori okun yi.
inu mi dun pupo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 7:56pm On Jun 21, 2007
Mode mode ni ti ewe ade
mobo mobo ni ti aboye
ewure ile to ni aoni de ni ao ni deba
aguntan ile to ni ao ni bo ni yio nu

eku ile oo
segoye baba bawo ni ose wa?
se arale??
baale nko? o to ijo meta ti mo ti wa si ori okun yi.
inu mi dun pupo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:40pm On Jun 21, 2007
MiShoo mo wapa, bawo ni? ni bo lo wa? Ile abi ni ibi ise grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 12:43am On Jun 22, 2007
Segoye , ti o ba ti fi ohun sokan pelu iyawo re tan ni ki o je kii n gbo o. mo n duro laafin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 2:51am On Jun 22, 2007
ewa = yaamaa sad
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 4:56am On Jun 22, 2007
ta ni o wa ni ile ooooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 4:59am On Jun 22, 2007
e ka ro
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:00am On Jun 22, 2007
its aro ooo, ba wo ni, omo dada, wa da gba, wa da rugbo, iyen ti oba se isekuse
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:02am On Jun 22, 2007
amin , o se
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:03am On Jun 22, 2007
omogenaija:

amin , o se


next time,, E SE, so ba wo ni
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 5:04am On Jun 22, 2007
ko bad , iwo nko ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 5:06am On Jun 22, 2007
alright ooo, awon oloribuku ti won ba ilu mi je SOUTH AFRICA, MA PA WON DA MU, U GO SEE

(1) (2) (3) ... (60) (61) (62) (63) (64) (65) (66) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 41
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.