Stats: 3,174,160 members, 7,890,931 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 01:50 AM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (378869 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (57) (58) (59) (60) (61) (62) (63) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 12:25am On Jun 19, 2007 |
Ose gon ojosi-fun ere Nkem Owoh. Mo ti wo gbo gbo ere e tan ni sin, Baba ye she ere movie pu po gan o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 1:46am On Jun 19, 2007 |
kotope |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 1:56am On Jun 19, 2007 |
Gnature, ma da were gambari Ikomi yen loun. Mii o mo enkan ti mo se fun asinwin yen ton fi binu mii kakiri. O da bi pe won sa si ni. Sha so fun pe ko fi mi si le else ma pe Shoponna mo lori. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 2:00am On Jun 19, 2007 |
Ha ole aya! Emi o mo pè omo yoruba ni ö o. Ki lo n mu awon oga olopa ehindero ati tafa fun yoruba oruko ti o da ni ilu yi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:07am On Jun 19, 2007 |
na wa o. . . ari bi so ede wa finally. Oyinbo ti su mi o. ![]() Oga Mustay, e ti sa lo kuro ni thread yen abi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 2:08am On Jun 19, 2007 |
davidylan: oyinbo o ti su e ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 2:12am On Jun 19, 2007 |
Mustay: shey ko hon(show) te le ni? ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 2:17am On Jun 19, 2007 |
omoge NY bawo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 2:21am On Jun 19, 2007 |
tan je gbe? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:24am On Jun 19, 2007 |
omogenaija: ama nya oro lo leekan kan. ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 2:28am On Jun 19, 2007 |
lol , kilon sele ? davidylan: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:30am On Jun 19, 2007 |
ko si repete. ilu oyinbo ti su mi, e wa gba visa yin pada! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 2:31am On Jun 19, 2007 |
ma lo si naija ti o ba ti su e |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 2:35am On Jun 19, 2007 |
o fe le mi ni? mo ro pe o ma bemi pe ki nmalo. ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 2:43am On Jun 19, 2007 |
ti o ba wa ise to ma fun mi ni $ 7.50/hour ni naija , ma ba e lo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 3:16am On Jun 19, 2007 |
Anu mi sè ë omonaija- o o ni gba salari fun odun méjé |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 3:17am On Jun 19, 2007 |
@ ole aya. Boya oruko e lo je kin ro pe omo geesi ni ö |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 4:15am On Jun 19, 2007 |
Mustay: o ma se o ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 4:22am On Jun 19, 2007 |
hummmmmmmmmmmmmmm ekele di m igbos ebe ah oh! ![]() ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 8:41am On Jun 19, 2007 |
E kaaro o, se alafia ni a ji o. Baale, kara o le o, se alafia ni e wa ati awon olori. Segoye, bawo ni, kaaro o. A de ku ipalemo satide o, mo lero wipe gbogbo wa lati mo wipe ojo satide ni ojo iwuye na, gbogbo ma laa ma peju pese si be o, ao ni fi enikeni ninu wa se awati o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 8:48am On Jun 19, 2007 |
ki lo nsele ni ojo satide? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 9:40am On Jun 19, 2007 |
tafari: Se oi tii ri gbo ni? A ni Segoye fe joye, ma send invitation letter sie lo ni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 10:30am On Jun 19, 2007 |
ikamefa: Omo your the best. Tieee la maaa se ni ojokojo. Ikemefa woooo, infact mo jubaee jare. You know what time it is. Ma da awon abinu eni like Thief********* loun. To lo ngbe ebo si orita meta nitori awa. Ikamefa a song for u. Asiko layé eda kan koò mọ'laaa Ay masiko lo ndamu ẹda(Thief******) Ori apata ti Jesu wi ni a waaa (me and Ika) Ógun aye kan ko le bawa leru mooo. Awa ti mo wipe to oluwa lasẹẹẹẹ Bori ko ti wu lori apataaaa Ola oluwa yio sọọ waa delé ohhh Are erè oja je, Ako ere oko dele My lovely Ika, go on soun jare, Won oki se egbẹẹẹẹ, Ojù won lọ teletele oju ni won nya(Thief*******) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by moondust(m): 2:03pm On Jun 19, 2007 |
bee ni! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 3:16pm On Jun 19, 2007 |
omo ibo ni ikomi o! ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:32pm On Jun 19, 2007 |
Aago onile o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 5:25pm On Jun 19, 2007 |
Ki lon happen? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:39pm On Jun 19, 2007 |
@desolar, mo wapa. oko e nko?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by GNature(m): 7:21pm On Jun 19, 2007 |
@toh, bawoni oo, okuu summer yii. Mo shaa man miss time to bawa online sha. eh, ogbeni ikomi, oda benipe oni ife arabinrin kan lori thread yii, as a matter of fact, awon gbeborun ati gbefila (paparazzi ![]() Awon wooli ton she iwadi so fun mi pe, As soon as ti arabinrin yen ba ti gba fun, iwo ati ikomi, ee get along daadaa. So, jowo, ni suuru di gba yen. ![]() Quote from Mustay Ki lo n mu awon oga olopa ehindero ati tafa fun yoruba oruko ti o da ni ilu yi? o ma she oo eniyan mi. Bi won she she yen, ko je ki inu mi dun rara. Oga olopa meji leralera ton ba oruko awa omo yoruba je ni yen. Ko bo si rara. Sugbon, mo tun gbo wipe ehindero ko lowo si owo ti won ji ni abuja. Mo hope wipe ko ni tun ba oruko wa je bi tafa she she yen. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 8:17pm On Jun 19, 2007 |
mishoo: o seun, o wa, o sare jade lati lo fi ayeye ojo satide to awon eniyan leti, mo lero wipe e ti gbo wipe ojo satide ni a fi ayeye na si. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 8:30pm On Jun 19, 2007 |
![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 8:48pm On Jun 19, 2007 |
ekasan |
(1) (2) (3) ... (57) (58) (59) (60) (61) (62) (63) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 20 |