Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,193,433 members, 7,950,928 topics. Date: Tuesday, 17 September 2024 at 06:49 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (68) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380808 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (65) (66) (67) (68) (69) (70) (71) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by GNature(m): 8:52pm On Jun 27, 2007
oyan nla bii gorodom to nwa yen, waa ri layo oo

maa ba e fi si adura. wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 9:03pm On Jun 27, 2007
GNature:

oyan nla bii gorodom to nwa yen, waa ri layo oo

maa ba e fi si adura. wink
Ose jare ore mi ire[b] OYAN [/b] a kari [b]GBOGBO [/b]wa o
segoye2:

Well, nigba ti o miss oyan ni kekere e, o se ba MOMSI re soro woya won le fi omi fo omu won Ma, and fun e mu, tabi ko n se oyan daadaa ni? grin

Iya omu oje e mi ooo, mo mu oyan momsi mi fun odun meji (2 years) and was great fun grin
popsie mi o je ki ngbadun oyan momsie mi ni kekere,nise ni won ma nba mi du oyan momsie mi,so mo wa binu fi sile fun won,dats why ti iya oyan fi je mi ni kekere.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 11:14am On Jun 28, 2007
Well Olutomiwa,

Jowo so more fun wa, nigbawo ati bawo lose sele gan? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 2:48pm On Jun 28, 2007
E kaasan o gbogbo ile o, se alafia ni mo ba yin o.

Baale se e wapa? awon olori na nko?

Segoye2, wats up?

U guys need to see how wet i am now
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 3:07pm On Jun 28, 2007
shocked shocked shocked shocked shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:20pm On Jun 28, 2007
Iyalode Ika , ewo ni toju, ki lo n sele, so wa pa?

Desorlah, mo wa ninu olanla ti Oluwa fi fun mi o, o ni ki n gunwa ki n si ma pase.

Je n soke Babe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:24pm On Jun 28, 2007
desorlah:


You guys need to see how wet i am now

Desorlah , oti o, ko tii ye mi daadaa. Se o da ice cream sara ni abi omo oni pure water lo ja ora omi si e lara ni, abi baba olowo fi moto ta omi si e lara. La oro yi kunnakunna o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 4:15pm On Jun 28, 2007
richylaw:

Desorlah , oti o, ko tii ye mi daadaa. Se o da ice cream sara ni abi omo oni pure water lo ja ora omi si e lara ni, abi baba olowo fi moto ta omi si e lara. La oro yi kunnakunna o.

Ojo ti on ro ni ibi yi lowolowo yi, o le wu oku ole!!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 4:17pm On Jun 28, 2007
richylaw:

[b]Iyalode Ika , ewo ni toju, ki lo n sele, so wa pa?[/b]

Desorlah, mo wa ninu olanla ti Oluwa fi fun mi o, o ni ki n gunwa ki n si ma pase.

Je n soke Babe.

Baale Oko ilu mo waa oh! and you?

se e ti ri aworan oyan ragbada yen sha? shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 4:26pm On Jun 28, 2007
Iyalode ika6, so wapa?
se ko si ti e fin shocked shocked
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 4:50pm On Jun 28, 2007
ikamefa:

Baale Oko ilu mo waa oh! and you?

se e ti ri aworan oyan ragbada yen sha? shocked
a ti ri se tie tobi to won abi o TOBI JU AWON YE LO? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:26pm On Jun 28, 2007
ikamefa:

Baale Oko ilu mo waa oh! and you?

se e ti ri aworan oyan ragbada yen sha? shocked

I'm fine,
Oju abore kii ri ibi o, mo sare fi "sun shade" si oju ni bi mo se ko firi awon aworan afoniloju yen o. Ki Olorun ma ke de gba wa ke lowo bobo Olutomiwa yi ke!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:29pm On Jun 28, 2007
richylaw:

I'm fine,
Oju abore kii ri ibi o, mo sare fi "sun shade" si oju ni bi mo se ko firi awon aworan afoniloju yen o. Ki Olorun ma ke de gba wa ke lowo bobo Olutomiwa yi ke!
Ore mi Baale, koda eyin ni mo sapamo si. Ki oju ma ri ibi, gbogbo ara logun re. A fi bi eni wipe kobekobe baloon fe be.

Ha, ao ro eru eleyi ri, - - - - - -
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:32pm On Jun 28, 2007
olutomiwa:

a ti ri se tie tobi to won abi o TOBI JU AWON YE LO? grin
Haba olutomiwa, a nilati pe igbimo lori oro re ooo. Boya ni a o fi jeki o pe ninu ilu wayi. A mo sa, temi ko ni lati dajo oo. Oloye segoye,Gnature, Iyalode ikamefa, ikomi, desolar kile riso si oro yi oo??
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 6:38pm On Jun 28, 2007
mishoo:

Haba olutomiwa, a nilati pe igbimo lori oro re ooo. Boya ni a o fi jeki o pe ninu ilu wayi. A mo sa, temi ko ni lati dajo oo. Oloye segoye,Gnature, Iyalode ikamefa, ikomi, desolar kile riso si oro yi oo??

Igi kan kii da igbose, e je ki a pade ni aafin baale lati jiroro lori oro ogbeni olutomiwa yi, ki a gbo ohun ti baale ni lati so si oro na, ao le la oju wa sile ki talubo ko wo o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 7:40pm On Jun 28, 2007
desorlah:

Igi kan kii da igbose, e je ki a pade ni aafin baale lati jiroro lori oro ogbeni olutomiwa yi, ki a gbo ohun ti baale ni lati so si oro na, ao le la oju wa sile ki talubo ko wo o.
[/b]eyin ara aba,kini mose tenikan o se ri,ewo ninu awon odomokunrin aba wa yi ni o muyan ri,ewo ninu awon obirin aba wa yi ni won o muyan re ri?mo ni mo nwa [b]OYAN TUTU,nitoripe[b] IYA OYAN JE MI NIGBA TI MO WA NI [/b] KEKERE,lati le je ki awon eyan mo iru oyan ti mo nwa ni mo se gbe[b] AWON AMAZIN [/b] GRACE BREASTS ye sita faraye ri,ti e ba pe ipade lemi lori ti e da ejo ti o te mi lorun,awon agbejo ro mi GANI FAWEHINMI,FEMI FALANA,WOLE OLANIPEKUN,FESTUS KEYAMO wa nikale lati gbe yin lo ile ejo,ti iye o ba de tun te mi lorun,ma lo si NIGER DELTA lati lo pe awon omo iya mi to wa nibe wa fun yin,ki e ya ro dada o.FUNDAMENTAL HUMAN RIGHT MI NI LATI MU OYAN TUTU.,eyi ti[b] NAFDAC APPROVE[/b] DE NI MO NWA O
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by WesleyanA(f): 7:45pm On Jun 28, 2007
olutomiwa:

FUNDAMENTAL HUMAN RIGHT MI NI LATI MU OYAN TUTU.

iya e gbe.
your mom's in trouble.
lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 7:46pm On Jun 28, 2007
:d
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 7:50pm On Jun 28, 2007
desorlah:

Igi kan kii da igbose, e je ki a pade ni aafin baale lati jiroro lori oro ogbeni olutomiwa yi, ki a gbo ohun ti baale ni lati so si oro na, ao le la oju wa sile ki talubo ko wo o.
[/b]Talubo ko ni mo gbe wa [b]OMU NI MO RU WA ,ko de le wo oju yin abi[b] OJU YI TOBI TO AWON OYAN YI NI?[/b]

<<obscene picture removed; this user has been banned for good>>
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 7:55pm On Jun 28, 2007
WesleyanA:

iya e gbe.
your mom's in trouble.
lol
@Wesley OYAN abi kiloruko e?se o fe FUN MI MU NI?mi mind lati fi ESE RIN WA SILU IBI TO NGBE O after all LOVE IS BLIND
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 8:21pm On Jun 28, 2007
eyi wun mi,ko wun o,lodifa fun omo iya meji ti won fi njeun logbogba.E DAKUN E MU EYI TO WU YIN NIBE
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 9:50pm On Jun 28, 2007
desorlah:

Iyalode ika6, so wapa?
se ko si ti e fin shocked shocked

Ayaba desorlah mo waa oh iwo nko?

awon oyan ti mo n ri lori thread yii lo faa shocked shocked grin

olutomiwa:

a ti ri se tie tobi to won abi o TOBI JU AWON YE LO? grin

Elephant breast man ! " grin "

dude you don't know me so bawo lo se maa mo boya temi naa to bi bii tiyen tabi tobi juu lo? undecided

ka sora oh grin

richylaw:

I'm fine,
Oju abore kii ri ibi o, mo sare fi "sun shade" si oju ni bi mo se ko firi awon aworan afoniloju yen o. Ki Olorun ma ke de gba wa ke lowo bobo Olutomiwa yi ke!

Emi ke de maa se Amin e ke! cheesy

o ke de dabi eni wipe ,mi ke de maa lo sare ra chanel -sunglasses kiakia ke?

mi o ke de fe fo loju ke! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:52pm On Jun 28, 2007
Desorlah mi owon,

Bawo ni, se o wa pa? mo missi re gan ooo,

Baale ooo, Iku ise ilu ooo, eba wa be bobo ayaworan yi ki o fiwa lorun sile ooo, ani ise dale ati asa yoruba ko fi aye gba wa lati ni yala iru oyon ti o gbe si oju iwe eyin yen tabi fi aye gba wa lati fi oju wa woo. ni tori, yoruba is not into pornogr, we hate if, if not totally, but in our land here, ode ye ki a so fun ore wa ki o gbe awo ran oduduwa tabi aworan ti o mu ogbon wa si ibe yen, ati aworan obirin ti o fi aso bo ihoho re daadaa,

Eseun wa ooo, bobo kuruje  cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:54pm On Jun 28, 2007
Si olutomiwa,

THIS IS FILM TRICK, se aworan ni awon eleyi tabi Egyptian Mummies?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by AlRaheem(m): 11:09pm On Jun 28, 2007
ori eyan to post awon pictures yen e o pe.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by DisGuy: 1:08am On Jun 29, 2007
shye ko shey wikpe won shekpe fun bobo yi abi talo sofun e ikpe a fi ri irikuri, angry angry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 5:07am On Jun 29, 2007
Oun amu sokun la ma fi ns'awada yi o. Mi o gbagbo rara. Haba! Omu re abi nkan mi. Omo ti ko ba ko lati mu iru omu bayi le ku iku amuju tabi amu pa l'ori. Ti omu ba ma tobi oye ki ara ba do'gba bi o ba je bakana ati e f'arajo. Eyi le ku o.

E gbo o, se Tomiwa fi Komputa ro omu yi ni abi bo ti ri le se fi han. Mo se bi ka ma fi ihoho han wa ninu ohun ti ofin ilu yi lodi si? T'olomu ba ti ni orun o wo ohun, ewo gaan ni ti gbonran mi d'eleru eyin ara ilu. E ja mi l'ori oro omu yi kaa mu nkan miran so.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:56am On Jun 29, 2007
embarassed embarassed embarassed
hissing with 'Do Re Mi Fa So La Ti Do'
ORISIRISI
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:00am On Jun 29, 2007
Anje ekuru ko tan lawo, o tun ngbon owo si.
Tomiwa o ti to oo.
se oya ni e ni? nitori oun be, ko to lo fi idi gun iso. Rora se ooo.
Aabo oro laa nso fun omluabi, to ba de inu re adi odindin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 9:09am On Jun 29, 2007
E kaaro o dede eyin omo kaaro ojiire ile Naira yi, se daada laa ji?

Baale oko ilu, se gbogbo e ndun, awon olori na nko nbe, se ko si iyonu rara?

Segoye2, bawo ni ololufe mi, emi na n miss e gidigidi gan ni o.

Eje ki a kiilo fun ogbeni olutomiwa yii gan o, Baale e je ki a tete wa nkan se si oro arakunrin na ki o to ti wipe apa oo ni ka mo o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 1:49pm On Jun 29, 2007
Singing
ta lo wa ninu ogba na
omo kekere kan ni
se kin wa wo
ma wa wo
iwo lopa
iwo lo - - - - -----------------------
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 3:32pm On Jun 29, 2007
mishoo:

Singing
ta lo wa ninu ogba na
omo kekere kan ni
se kin wa wo
ma wa wo
iwo lopa
iwo lo - - - - -----------------------


O man da lati ma ranti igba ewe leekankan, bawo ni, so wapa?

(1) (2) (3) ... (65) (66) (67) (68) (69) (70) (71) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 42
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.