Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,201,455 members, 7,978,467 topics. Date: Friday, 18 October 2024 at 08:57 AM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (69) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (382105 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (66) (67) (68) (69) (70) (71) (72) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by abiodunade(m): 6:23pm On Jun 29, 2007
mishoo:

Anje ekuru ko tan lawo, o tun ngbon owo si.
Tomiwa o ti to oo.
se oya ni e ni? nitori oun be, ko to lo fi idi gun iso. Rora se ooo.
Aabo oro laa nso fun omluabi, to ba de inu re adi odindin.
SUKU SUKU BAM BAM,ENI TO BA WU KO BE grin
desorlah:

E kaaro o dede eyin omo kaaro ojiire ile Naira yi, se daada laa ji?

Baale oko ilu, se gbogbo e ndun, awon olori na nko nbe, se ko si iyonu rara?

Segoye2, bawo ni ololufe mi, emi na n miss e gidigidi gan ni o.

Eje ki a kiilo fun ogbeni olutomiwa yii gan o, Baale e je ki a tete wa nkan se si oro arakunrin na ki o to ti wipe apa oo ni ka mo o.
desorlah:

E kaaro o dede eyin omo kaaro ojiire ile Naira yi, se daada laa ji?

Baale oko ilu, se gbogbo e ndun, awon olori na nko nbe, se ko si iyonu rara?

Segoye2, bawo ni ololufe mi, emi na n miss e gidigidi gan ni o.

Eje ki a kiilo fun ogbeni olutomiwa yii gan o, Baale e je ki a tete wa nkan se si oro arakunrin na ki o to ti wipe apa oo ni ka mo o.
wot do u DISAYA wot do u av UNDA,[[/b]b] SWEET BANANA,SWEET BANANA
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 6:31pm On Jun 29, 2007
abiodunade:

SUKU SUKU BAM BAM,ENI TO BA WU KO BE ;Dwot do u DISAYA wot do u av UNDA,[[/b]b] SWEET BANANA,SWEET BANANA

Eeyan bii olutomiwa ni arakunrin yii o. *do you know that pornography is not allowed in this land?*
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:17pm On Jun 29, 2007
Iyawo mi Desorlah,

Thank you for your comment. Bawo ni, se o wa pa? Emi tile missi re gan ni oooo, ni bo lowa bayi, se o ti kuro ni nigeria tabi o wa ni afin ni? ope die ti mo ri baale mo, se alafia ni won wa oooo? baba wa ooo, ejowo eba wa be awe oni aworan rada rada yen ki o gbe kuro lori ile wa oooo, ti a ba ti le ba n soro IYAMA, ko to si aworan lati yoju, ati wipe, Oba Seun ko we simi, wo n de fi ye mi pe inu n bi won si awon aworan yen, ejowo, e ba wa ba awe wa Sqanderi soro wipe eyi ti o se to ooo, Inu awon oloye o dun si, inu emi ati aya mi odun si, inu oba seun o dun si, inu awon eyan nlan lan bi Ikomi, Ayefele, Nana, Ikam, , Angeli ale, Mushoo, Al Raheem, Dis_Guy ati be be lo o dun si bi Rada rada yi se wa n tan sii.

Desorlah Baby, my PC just came up after some tough time of crashing.

Mo ni ife re lopo lopo oooo,

Cheers,

Segoye2
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:24pm On Jun 29, 2007
wot do u DISAYA wot do u av UNDA,[b] SWEET BANANA,SWEET BANANA[/b]

Nje Ire mo wipe arabirin ti ire n bere ohun ti o di saya ni aya mi bi? Nje ire ko mo wipe aya oloye ni bi? Nje ire ko mo wipe ese nla ni ilu ile-ife lati bere ibere basha basha bayi ni owo obirin ti oti ni oko bi? Nje ire ko ni owo fun baale ile wa bi? Nje ire ko mo wipe emi mo wipe eyan daa daa ni ire sugbon aworan ti ire wo ti da agbari Tire run bi? Nje ire ko le ko enu re ni ijanu daadaa mo bi?

Nje u no dey fear, fear? cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 8:26pm On Jun 29, 2007
angry shocked tongue embarassed lipsrsealed undecided kiss smiley wink cheesy grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 8:43pm On Jun 29, 2007
Nana mi Owon,

Bawo ni, se o wa pa, erin pa ire na?

Well, mo ni kin fi to e lati wipe Iyawo mi Desorlah ma come over to the U.K latest by Jan. 08, bo tile je pe, ko i ti gba finally, sugbon arrangement is on lati effect movementi e lati nigeria.

Bawo ni oko e? Ki ni oru ko re na? emi o fe se oju isa ju ra ra ra ooo, nitori na ni mo se ni wipe ki ele olori fi enu ara re so oruko oko re  grin  grin

Am happy for my WIFE DESORLAH
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 8:49pm On Jun 29, 2007
segoye2:

Nana mi Owon,

Bawo ni, se o wa pa, erin pa ire na?

Well, mo ni kin fi to e lati wipe Iyawo mi Desorlah ma come over to the UK latest by Jan. 08, bo tile je pe, ko i ti gba finally, sugbon arrangement is on lati effect movementi e lati nigeria.

Bawo ni oko e? Ki ni oru ko re na? emi o fe se oju isa ju ra ra ra ooo, nitori na ni mo se ni wipe ki ele olori fi enu ara re so oruko oko re grin grin

Am happy for my WIFE DESORLAH
Hmm, Segoye so wa pa? Oko mi ko si on Nl. Mo hope nipe on prepare dada fun bi Desorlah se ma wa si CLAPHAM COMMON?
Nigbawo ni Desorlah di Olori?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 11:16pm On Jun 29, 2007
Mo wa ooo, Nana sebi ore re ni Desorlah, oye ki o so fun e pepe naw grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayefele200(m): 11:21pm On Jun 29, 2007
eka le, eyin, gba ju mo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by queen2(f): 9:58am On Jun 30, 2007
OMG olutomiwa abi kini oruko eh, nibo loti ri awon disgusting pictures yen
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 10:53am On Jun 30, 2007
A o mo o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by queen2(f): 12:35pm On Jun 30, 2007
Who tell u say oyinbo kno no how to speak yuroba, listen 2 this song


https://www.youtube.com/watch?v=kywXb31c2HA
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 1:19pm On Jun 30, 2007
E kaasan o everybody, se daada ni mo ba yin o?

nana:

Hmm, Segoye so wa pa? Oko mi ko si on Nl. Mo hope nipe on prepare dada fun bi Desorlah se ma wa si CLAPHAM COMMON?
Nigbawo ni Desorlah di Olori?

Nana, bawo ni, so wapa? se ire ko mo wipe oloye ni Segoye2 ni nl ni?

segoye2:

Iyawo mi Desorlah,

Thank you for your comment. Bawo ni, se o wa pa? Emi tile missi re gan ni oooo, ni bo lowa bayi, se o ti kuro ni nigeria tabi o wa ni afin ni? ope die ti mo ri baale mo, se alafia ni won wa oooo? baba wa ooo, ejowo eba wa be awe oni aworan rada rada yen ki o gbe kuro lori ile wa oooo, ti a ba ti le ba n soro IYAMA, ko to si aworan lati yoju, ati wipe, Oba Seun ko we simi, wo n de fi ye mi pe inu n bi won si awon aworan yen, ejowo, e ba wa ba awe wa Sqanderi soro wipe eyi ti o se to ooo, Inu awon oloye o dun si, inu emi ati aya mi odun si, inu oba seun o dun si, inu awon eyan nlan lan bi Ikomi, Ayefele, Nana, Ikam, , Angeli ale, Mushoo, Al Raheem, Dis_Guy ati be be lo o dun si bi Rada rada yi se wa n tan sii.

Desorlah Baby, my PC just came up after some tough time of crashing.

Mo ni ife re lopo lopo oooo,

Cheers,

Segoye2

Segoye2, bawo ni, so wapa? emi na miss e gidi gan ni o.

Baale, se ara le o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 2:05pm On Jun 30, 2007
Aya mi,

Emi ne kede wa pa oo, bawo ni ara re ati ara baale, ose die ti a ri won laafin, se ki n se wipe o re ra die?

Jowo bami lo si Villa mi, fun Ore mi, Emma ni parcel ti mo fun e yen ni Igba ti o wa fun visiting yen, mo fe ki o pe mi tale tale oni,

Eyin eyan mi,

Eku ise o ni oooooo, se ara le ooo, weekend in advance!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 2:20pm On Jun 30, 2007
Bale segoye2,mo ki yin e kasan o,e si ku oro ilu,mo yika otun,mo yika osi,KI OKO PE LABE,KI FURO PE NI SOKOTO,ki OKO OBA JE ISU PE O,o se je wipe oro mi ni e wa gbe lori ninu aba wa yi,pelu gbogbo awon wahala to ndoju kowa ni abule wa yi,se ESE NI LATI BERE OHUN TI O NWU,ENIA LOKAN,se o buru fun mi lati bere fun OYAN TUTU MU,eyi to je eto gbogbo omo,SE EYIN TE JE BALE O KI NMUYAN NI?ABI E FE SO FUN MI PE E DAMO,e jowo e fimi lorun sile o,aije be gbogbo ohun te se tile fi jona ni ma so fun gbogbo awon ara ilu wa,papa julo gbogbo bi e se NLA AWON OMO OBIRIN WA MOLE NI MO MO,TI AWON ASIRI YIN WA LOWO MIto ba dabi iro eyin e ni NSA WO. e ma foju dimi o,aworan yin nbe lowo mi,nitorina bale wa E KULU TEMPA LORI ORO MI,KE SI FAMI MORA GEGE BIIKAN NINU AWON OLOYE YIN.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Tonim(f): 2:32pm On Jun 30, 2007
segoye2's postings are so boring and repetitive. All he does is greet baale and iyawo all day long.

Am I the only one who thinks segoye is a bore ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 3:10pm On Jun 30, 2007
Tonim:

segoye2's postings are so boring and repetitive. All he does is greet baale and iyawo all day long.

Am I the only one who thinks segoye is a bore ?
No you is not the only once that are thinkings that segoyse2 posted is bore,me two is thinked so two,i thinks his posted is THREE BORINGS
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 3:14pm On Jun 30, 2007
@Tonim and Tomiwa, na wah for una o!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 4:09pm On Jun 30, 2007
desorlah:

@Tonim and Tomiwa, na wah for una o!!
and u 2 with segoye2 grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by israelite(m): 7:05pm On Jun 30, 2007
eku asale oo, see dada ni ewa, ede ku weekend naa ejo mo need omoge pup kan ti o ma tele me losi club.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 7:19pm On Jun 30, 2007
israelite:

eku asale oo, see dada ni ewa, ede ku weekend naa ejo mo need omoge pup kan ti o ma tele me losi club.
omo abule kilo nwa lo si KULOBU?Sosi abi mosalasi lo ye ko lo o grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:04pm On Jun 30, 2007
Eyin Ogbeni Tonim ati Ogbeni Olutomiwa,

Ki ni itu mo rada rada yi na? Respect is reciprocal cool

Aya mi, Bawo ni, se daada ni o wa, bawo de ni striki ti mo n polongo ni nigeria, se won ti lift e sha?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:23pm On Jun 30, 2007
You guys are not bore with with those naughty pics of naked ladies you got in there, You even got the got to move to Igno thread, representing yoruba there and postin such dirty issues there. I hate what you are doing there, Inu mi o dun si ra ra ra ni, Be de ni, I nu omo yoruba tooto ko gbodo dun si rada rada wonyi ti o pe ni unbored issues, Me no like ham SHIKENA grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 9:56pm On Jun 30, 2007
Ye ko oyinbo si bi bai
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Tonim(f): 10:52pm On Jun 30, 2007
segoye2:


Aya mi, Bawo ni, se daada ni o wa, bawo de ni striki ti mo n polongo ni nigeria, se won ti lift e sha?


Here we go again, can't you find anything else in this world to talk about ?

Same old boring lines. gooooshh undecided
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ThiefOfHearts(f): 1:37am On Jul 01, 2007
eyin people yii sha
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kitaun(m): 2:19am On Jul 01, 2007
@TOH

oro awon eyan yii su emi na o shocked grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omogenaija(f): 2:36am On Jul 01, 2007
ewo le se ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Olufidu(m): 5:06am On Jul 01, 2007
Aaago gbogbo omo ile kaaro oojire! Mo kiyin tomode tagbalagba, mo ki olorioko o, ki nto wole o.

Nje emi Olufidu ni lati ilu odi keji, ni oke odo.

Mo nkoja lo ni ilu Nairalandi ni mo ba ta ju kan, mo ri ododo abemi kan ti owu mi tongue

Yoruba bo won ni, a mo bere lowo oloju ki a to gbaa!

Nje le gbami laaye lati ja ododo naa? wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 9:35am On Jul 01, 2007
Tirédi gbe gaa-an
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Mustay(m): 9:36am On Jul 01, 2007
Tirédi gbe gaa-an
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by olutomiwa(m): 2:38pm On Jul 01, 2007
Tonim:

Here we go again, can't you find anything else in this world to talk about ?

Same old boring lines. gooooshh undecided
o gba oro na so lati enu mi{same old story lines} sad

(1) (2) (3) ... (66) (67) (68) (69) (70) (71) (72) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 45
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.