Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,192,615 members, 7,948,368 topics. Date: Friday, 13 September 2024 at 07:23 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380707 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 2:02pm On Aug 02, 2007 |
haba, baale!! ki lo nsele ni ilu ti apa yin o ka? se rogbodiyan wa ninu ilu ni? e fi okan yin bale. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:39pm On Aug 02, 2007 |
tafari:Ko si ohun to bo nile ti , ile o gba o, apa oba ka ilu tepontepon. Sugbon nipa ti oye, je ki a mu dani si egbe kan na. Ise wa pa o ( and yours?) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:26pm On Aug 02, 2007 |
richylaw: According to 'HIGH' Demand http://download.yousendit.com/D4428F1E3FB86EE5 |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:30pm On Aug 02, 2007 |
o fi dudu je won bolanle o fi pupa je won bolanle o fi kebe je won bolanle Ibadi aran o bolanle Face of africa, he he Ajoma gbadun ni le yi o Bolanle please don't hold me I want to dance
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:40pm On Aug 02, 2007 |
E pagbo !! E pagbo oooo!! Abeg, Clear ground !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:57pm On Aug 02, 2007 |
Baby baby Bolanle bebebi sisi alakada arewa fi wa sewa omodun bebebi olomoge duro na ire la n bawi danwo lo bi 'ya okere emi gangan ni baba okere o da wo mi ko tun mi wo baby mo dun mo tun re ni tun fi jo gbe mi wo bi jigi jigi jigi jigi baby mo ni ko fe mi wa wa gba p'ori loni fila wa tun gba p'ese lo ni bata baby surulere, o sa mo levels ti mo wa gbami gbami towo tese yi o, olomoge Baale has gone gaga and groovy okay dig it , dig it
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 5:12pm On Aug 02, 2007 |
You only need to really see me dancing. Play the song and watch these guys dig it . Original ijoya level. JUST A PRE-FRIDAY JOLLIFICATION
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:17pm On Aug 02, 2007 |
Ase o wa lara bale to bayi !! Tani yio ba bale jo oo?? Nana, Ikamefa, Desorlah, minute, omoge, omoeko, nibo ni gbogbo yin wa oo?? Dance dey waste !!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:23pm On Aug 02, 2007 |
emi naa fara mo ijo pelu baale jare, oya eyin omidan ilu, e jade kie bere si ni komole! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:31pm On Aug 02, 2007 |
Mo tin komole but no one is spraying money on me.Mo like e o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:36pm On Aug 02, 2007 |
nana: Se loto ni Baale?? But Baale lowo lowo gan now !!! Abi awon kan n sa owo yen nile ni?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:38pm On Aug 02, 2007 |
O da ma na e lowo oo!!!
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:42pm On Aug 02, 2007 |
Mishoo Of all currencies ti Naija ni,awon owo kekeke yen ni on na fun mi.Abi o ti gba |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:48pm On Aug 02, 2007 |
nana:Oun lo ogun ni? Bawo ni o se mo?? Eru re bami oo !!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:53pm On Aug 02, 2007 |
Lol, so mo get e.Mo ko guess ni. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:55pm On Aug 02, 2007 |
Je ki nwa ebun kan fun e !! Ki o ba le ranti ile !! http://www.yousendit.com/download/ZUcyQ3Q5Q1JmVFkwTVE9PQ |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 5:59pm On Aug 02, 2007 |
O se o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:03pm On Aug 02, 2007 |
nana: Ha !!! Ori mi wu ooo !!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 6:16pm On Aug 02, 2007 |
je ki o ma wu o mishoo Nana, iwo ma worry, baale ki na wo loju agbo, cheque e wa nibi yi je ki a jo tan! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 6:23pm On Aug 02, 2007 |
richylaw:Baale !! Bi awon agba ba n yo ile da, ohun abenu a ma yo won se oooo Yoruba proverb Ojoro leleyi ooo!! A o si ni faramo !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:40pm On Aug 02, 2007 |
@borrado LOL ni edee yoruba tumo si ERIN NI YANTURU tabi OPOLOPO ERIN |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 7:44pm On Aug 02, 2007 |
@ola2k Mo gbadun akosile ede yorubaa re gan ni o. Nje o le ko mi bi a ti se n lo ero komputa lati fi aami si ori ati idi oro yoruba. Nitori mo gbadun lati maa yan awon akosilee mi pelu ami ti o ye |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 8:00pm On Aug 02, 2007 |
si bodsibobo aayan ongbufoo re dun ka o yo kululu bi elubo ti a jo daada sugbon O TAKE ADVANTAGE tumo si O LO ANFAANI opolo e o nii ku AMIN |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:15pm On Aug 02, 2007 |
aayan ogbufo gidi ni ogbeni ayanjide nse o! Baale wa oye ki a wa ipo kan fun ogbeni ayanjide ni aafin, iru imoran yii ma wulo gan fun ise eto ilu ti Baale nse, pelu awon omo Londona ati Americana ti won po si ni ilu wa yii Erin lopolopo (aka LOL) |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:06am On Aug 03, 2007 |
Debosky ,O ti da be na nu, sugbon yio dara ki alagba Ayanjide fi ara mo wa dara dara ninu abule yi ki a to le mo iru eni ti won je gan. F'otun we osi, f'osi we otun , ki owo sa ti mo ni Isiwo iporo wo, ohun aba jo wo gigun ni gun Ogidimolaja , Ayanjide ti d'awo ile Ife loni o, kawo mo gbe awo nigbowo loku, k'awo mo ba te , k'awo mo ba ya Mishoo, o da mi loju wipe gege bii baale , n o ti jayo pa lati fun Nana ni iwe sowe dowo.Debosky oko re na o si binu si rara. O sa san ki a na owo fun eni ti o mo iyi re. Abi o ti gbagbe iyawo kekere ti a fe fun baale ni ojo kinni ana (Mukinatu)! awon da loni?Aini suuru ti mu won siyan lai duro gbobe ,owo ti o si ye ki a na fun iru won ni a pa ona re da si odo awon ti o mo iyi wura wonyi o. Se bi iwo na mo wipe ohun ti "agbalagba fi n jeko abe ewe lowa. Eyi ti o si fi ju omode lo, ko ni fihan, bi o ba fihan ko ni fi le lowo, bi o ba file lowo, ko ni ko bi yio se lo, bo ba situn wa ko wayi, ko ni fun lero re, amo sa o bi o ba fun lero re , ko wule ni fi ewe ti a fi n ki han tori ojo t'ewe o ba sun oko." Nitorina na agba t'emi o yo le da o Ko je bo ti je , eje ki a ma rin erin yanturu bi asa Ayanjide |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by aloib(f): 4:21am On Aug 03, 2007 |
ahhhhhhhhhhhhhhhh, yoruba yi le ju temi lo o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 9:37am On Aug 03, 2007 |
Aloib ki lo tii fa ekun ninu oro yi, fi suuru ka yoruba yi daadaa , yi o ye o. Sebi awa omo iya re na ni a ko si le. Ni gba ti iwo ko tire awa na sa ka! Desorlah bawo lariya de se ma ke de ri loni ke? Ojo Eti miran tun leleyi o, je ki n fun e ni 'logo' ti o wa nisale yi ki o fi bere si se ajoyo Friday, emi na fe bo si enu ise ni akoko yi o.
|
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:44am On Aug 03, 2007 |
Baale ati gbogbo mutumuwa, e ku owuro oooo. A a jirebi ?? A ke ojo eti miran oo!!! A o se opolopo laye ati laaye wa !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:24am On Aug 03, 2007 |
Eku Ojumo o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dblock(m): 10:26am On Aug 03, 2007 |
Yay Ojo friday ni Tse mo wipe, mo fe gun enikan ni ogun, ma gun ijoku kin mu ogun mi, kin ni agbara kin gun enikan ti mofe gun ni ogun, to shele nisin sin ni Ogun state. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:34am On Aug 03, 2007 |
La lale friday,Temi o ba sun le o. Orin wale mon gbo o Ti mo fi gbera gege,gbera gege,gbera gege |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:34am On Aug 03, 2007 |
dblock:What? |
(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 29 |