Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,192,586 members, 7,948,270 topics. Date: Friday, 13 September 2024 at 05:19 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380702 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (91) (92) (93) (94) (95) (96) (97) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 2:47pm On Aug 06, 2007 |
Dis Guy:Ekasan oo. A se eyin na ma n so Ede wa. E kaabo sinu abule yi !! tafari:Tafari okunrin meta !! Se oko o je epo !! alafia ki ile wa bi?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 2:56pm On Aug 06, 2007 |
mishoo, ise, omo, iyawo nko? e de ku miliki ilu wa yi. nje baale wa ni aafin bi? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 2:58pm On Aug 06, 2007 |
Mo tun ki gbogbo wa ku ikale leekan si o. Mo ki awon eekan oro bi Alagba Tafari, Disguy, Mishoo ati Nana o. E ku ko le da. Mishoo, inu mi dun wipe o tu ile kan Ilu Oyotunji o. I got to know about Oyotunji about four years ago. Mo si tun ti ni ohun kan tabi omiran se pelu awon abenugo ti n je ki eye ke bi eye ni Oyotunji. Boya ti awon omo yanmirin ode oni ba tun n ri eleyi won yio le pe aro ati odofin inu won wa ile , lati ri wipe ede ati asa ti o lami laaka julo lori ile agbaye (Yoruba!) ko paarun . Alagba Mishoo , e ku afiyesi . E si tun ku afokantan. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:00pm On Aug 06, 2007 |
Alagba Tafari , mo wa laafin ninu ola nla mi o. Koko la ra ota n le. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 3:02pm On Aug 06, 2007 |
baale, oro wa o. ma wa ri yin ni aafin ni irole |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 3:11pm On Aug 06, 2007 |
tafari:Tafari, ko si ogba ti oro ki i si ni?? Se oo ti jawo loro oye yi na?? Amon a i san wo lo ile baale ooo. Se o mo bee?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:15pm On Aug 06, 2007 |
mishoo: Ile gbogbo ilu ni afin oba je, yara awon olori nikan l'enikan o gbodo be ju wo a fi baba funrare . N o mo reti awon alejo mi bo ba d'ojoro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 3:48pm On Aug 06, 2007 |
Hello! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:00pm On Aug 06, 2007 |
HELLO GAN NA NI . Desorlah , ka a si bi? o pe die ka to ri yin loni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:02pm On Aug 06, 2007 |
richylaw: |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:30pm On Aug 06, 2007 |
Mishoo , se iwo o mo pe enikan ki gbe ina wo oju egun ni, enikan ki gbena woju ebora, a i je be ebora a bo laso. Iwo fi yen sile, je ki enikan wa danwo na. Onitohun o dan tan ni. he he he heh ehe he! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 4:34pm On Aug 06, 2007 |
hm hm |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 4:44pm On Aug 06, 2007 |
nana: beeni mo so! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 5:13pm On Aug 06, 2007 |
nana:Nana, eewo ni hmm?? Se oun mi kanle ni tabi oro ohun o ye oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 1:57am On Aug 07, 2007 |
@ Ob'Wunmi lol i dey kampe paddy mi you are hilarious |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:02am On Aug 07, 2007 |
obowunmi: Ti omo eni ba se daada, oyo ka wi !! Inu mi dun fun ogbeni ***Wunmi pupo pupo. Ti a ba ma tie fi epo, ata ati alubosa si i ki i se igbagbogbo, beeni kiise ni pipoju ki o ma baa ja a. Wunmi, a du e se ooo Wa laale, oo ni lalele |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by satan: 1:50pm On Aug 07, 2007 |
Hello Eyin ole lasan lasan |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 3:01pm On Aug 07, 2007 |
@ DEBOSKY o see pupo fun bi o ti pe akiyesii baale abule yi si oro mi. O dun mi pe o pe die ti mo ti yoju si aafin. Sugbon morii pe lai si n le mi aafin si n dun. Edumare o nii ba ise owoo wa je o. ASE Sugbon nisinyi maa se akitiyan lati fara moo yin daada, ki a le baa fowowewo ni abule yi. @ RICHYLAW ooto ni, un o faramo yin daada nitori abule yi dun. A o nii p'edin, a o si nii te. E see gan ti e ko je ki oruko mi o pare labule yi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 5:02pm On Aug 07, 2007 |
LOL. LOVE MY NAIJA BROS AND SIS HERE. LOL-----erin ni yanturu lol |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 6:46pm On Aug 07, 2007 |
obowunmi oniyeye gidi ni o je o eforious ati ilarious nikan ni? oma to ri gbegiricious ni si yin alagba ayanjide, ekaabo si aafin o, adupe pe ko si jamba lona nigba ti e rin irin ajo wa ni tooto mo mu oro yin lo ba baale wa ni aafin, won si wipe ti e ba bawa fowowewo bi o se ye ninu ilu wa yii, laipe laijina ipo lantulantu ninu aafin ni wo ma fi lo yin. inu mi dun pupo pe e ti pinnu lati fara mo wa patapata ni ilu wa yii, owo yin a ma roke o. Amin Ase Baale wa ki ade pe lori ki bata pe le se o. osi ti to ojomelo kan ti mo ti ba oloye segeoye soro, abi Baale ti ran ni se lo si ilu miran gege bii oju ati eti aafin ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 7:07pm On Aug 07, 2007 |
amin jare 'wunmi bawo ni awon iyawo e? se won o je kio re ara sa? nitori mo mo pe awon omo yen le pa eyan o! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:02pm On Aug 07, 2007 |
obowunmi: Oro iyawo ki i se nkan to buru rara oo se apon ni eyin fe je dojo ale ni?? Bachelor for Life Etete lo wa iyawo oo !! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by minute(f): 8:05pm On Aug 07, 2007 |
LOL |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 8:08pm On Aug 07, 2007 |
abi oju mi ntan mi ni?? obowunmi ti di deacon iru asiko ti mo ma feran ki pastor haywhy yoju ni yii. 'wunmi jowo juwe adugbo ti soosi yii wa kinle wa ri alagba ijo yin. iru oro ti o gba enu yin jade tele ko to si eni tio ba je decon ijo o ko si laburu nipa oro iyawo o, sugbon ema je ki o ju eyo kan lo afi ti ijo yin ba je ti catoliki ti awon priest o gbodo fe iyawo oda o, mo ti kunle, deacon obowunmi e gbadura fun wa egbon mi mishoo, se eyin maa nba eyan wa iyawo ni? ti e ba mo iru ise yen se, ejowo e lo ba obowunmi wa iyawo o emi o nilo iyawo miran sa, emi ti fe omidan nana tipe tipe |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 8:12pm On Aug 07, 2007 |
Ti wunmi ba fe fe ju eyo kan lo, ko si laburu nibe. Sebi "me" lolorun wi !! Ko si ewu ni egberun eko, afi aidun obe. Se o sa ti lowo ati toju won ko mo se pe awon ni won o ma toju e?? ti o ba si ti njeun daradara a ma yo ikun si ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 9:04pm On Aug 07, 2007 |
em em em em eh, ni bi wo ni mo stop sha now, oh mo miss road ni sorry chaps and ladies |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 9:20pm On Aug 07, 2007 |
obowunmi: abalajo, oye ki mo ti mo pe ile ijosin onisekuse nikan ni o le fun iru omo obowunmi ni oye deacon ki Olugbala ko yin yo ninu ese yin o, oo ni se Amin ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ayanjide(m): 6:55am On Aug 08, 2007 |
debosky e see mo dupe gan ni o. E de kuu ilaloye ti e n fun ogbeni debosky afi ki Oluwa ko ko won yoninu oro E PA NA, E PA NA ti won ko raa won si yii. OBOWUNMI. e jowo kinni itumo oruko yin, se OBO bii VIRGI, abi OBO bii MONKEY nitori ko ye mi ni mo se beere o. E ma fi se 'binu rara o. eni beere kii sina. Nigba ti mo wa aso iboraa mi9 ti n korii mo pe nombaa yin 0900007777 wonni ko si lawujo awon nomba lorii gegele isoro alagbekaa mi. Se kii se p e e ko mo nomba yin lori? E MAA GBADUN LABULE YI O |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 9:53am On Aug 08, 2007 |
E kaaro ninu abule yi oo!! Abi ko si enikankan ninu ile ni?? Singing Talo ninu ogba na omo kekere kan ni se ki n wa wo? mo wa wo iwo lo pa iwo lo - - - - - - - - - - |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 12:30pm On Aug 08, 2007 |
alagba mishoo, e mi wa ninu ogba o. se oko o je epo o. awon iyawo ati omo nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 12:43pm On Aug 08, 2007 |
E kasan o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:52pm On Aug 08, 2007 |
tafari: Tafari, okunrin meta !! Gbogbo won ni won wa daada oo!! Adupe, Enu n gbe yangan !! E si ku kokari !! E ku ofinkin yi na!! nana:E kaabo oo !! Surprised you aint Helloing us today Alafia ki ile wa bi?? |
(1) (2) (3) ... (91) (92) (93) (94) (95) (96) (97) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 52 |