Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,192,554 members, 7,948,150 topics. Date: Friday, 13 September 2024 at 03:01 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380696 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (94) (95) (96) (97) (98) (99) (100) ... (167) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 6:27pm On Aug 09, 2007 |
egba re yen ! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by omoge(f): 6:30pm On Aug 09, 2007 |
mo wa ooo gegebi mo se wa Ob'wunmi iwo daa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by seunniji(m): 10:48pm On Aug 09, 2007 |
Oga gun ooooo ema wo awon omo karojire bi won se so oro |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by satan: 8:54am On Aug 10, 2007 |
Hello |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dblock(m): 12:13pm On Aug 10, 2007 |
Sup Satani. Ki lo da? Bawo ni Inan. Sho Gbono? Ema Keep it ril Hommie Mi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:49pm On Aug 10, 2007 |
E ku ile oo. Ekaro ninu abule yi. Se ara le?? dblock: Haba, dblock bawo ni ose di ore esu odara |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by jagunlabi(m): 5:43pm On Aug 10, 2007 |
Ko ni da fun gbogbo yin o! Eem,mo mean pe "Mo ki gbogbo yin o!". |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 6:34pm On Aug 10, 2007 |
mishoo, bawo ni o? se gbogbo e ndun? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Amigoz(f): 6:51pm On Aug 10, 2007 |
se gbogbo yin mo ara yin ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by champredd(m): 6:57pm On Aug 10, 2007 |
Emi lo nse |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by satan: 8:58pm On Aug 10, 2007 |
MOWAPA! INU INA NA DE WA PA DAADAA. HELL HERE IS PREPARED FOR YOU. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:10pm On Aug 10, 2007 |
talo wa ninu ilu yio. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 9:11pm On Aug 10, 2007 |
Tafari,bawo ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:35pm On Aug 10, 2007 |
omoge nana , mo wapa. awon family nko? ki lo nsele? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 9:36pm On Aug 10, 2007 |
Yeah,ko si repete jare. I just dey. Awon Family wa dada. Bawo ni ise abi acada? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:42pm On Aug 10, 2007 |
ise nlo daadaa. awon iyawo ati omo naa waa ni alaafia. bawo ni acada? se awon boys o da e lamu. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 9:45pm On Aug 10, 2007 |
Ope ni fun Olorun Oba o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 9:54pm On Aug 10, 2007 |
arewa obinrin ni e o. o si dun woo pelu. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 9:55pm On Aug 10, 2007 |
Ese o.Ola Oluwa ni o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 10:00pm On Aug 10, 2007 |
fun mi ninu ola ati ewa yii naa. je ki ajo ma je ati mu paapoo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:02pm On Aug 10, 2007 |
Hmm. . . Ola ati Ewa Oluwa wa ni ibi gbogbo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 10:06pm On Aug 10, 2007 |
ewa ati ola ti e yii yato. koda mi o ri iru arewa obinrin bi ti e ri. awamaridi ni e o. ko da, o ti npa mi bi oti. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:08pm On Aug 10, 2007 |
Hmm,ese o sugbon ema je ki opa yin bi oti o. E ranti wipe aunty ati aburo mi wa ni ile o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 10:09pm On Aug 10, 2007 |
ma je ko pa e bi oti o ogbeni tafari Nana ti fe oko tipe tipe, o le bere lowo Baale gan, awon ni won se alaga ni ojo igbeyawo naa ni shoki, emi ati Nana je oko ati iyawo, Baale wa si ti so pe lehin iwuye Segeoye ati Desorlah ti emi ati Nana ni o kan. e jo wo ema gbe egun eleegun o, Oluwa yio pese tiyin fun yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 10:14pm On Aug 10, 2007 |
ngbo nana, bawo ni debo se je si e? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 10:18pm On Aug 10, 2007 |
mo ro wipe j-girl ni iyawo re debosky? bawo ni nana tun se je? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 10:20pm On Aug 10, 2007 |
o ga o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by NiteAngel(m): 10:21pm On Aug 10, 2007 |
Enle o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 12:34am On Aug 11, 2007 |
Hello |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 3:19am On Aug 11, 2007 |
tafari oro atijo ni oro j-girl, emi ko se igbeyawo pelu omo yen, asi n'mora lowo (dating) ni nigbati a de ri pe ako ba ara wa mu lehin igba naa ni mo wa foju le omidan Nana omo to larewa julo. mo si n'ife re gaan oun naa si nife mi, mo si lo si le awon obi re lo dobale ki won fun mi ni omo won fun aya mi awon naa si gba. lati igba naa ni emi ati Nana ti je oko ati Iyawo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tafari(m): 3:36am On Aug 11, 2007 |
ko baje rara. carry go! sugbon ranti wipe nana ni iyawo re o. ti owo mi ba te omo mi, mi o ni gba to ba fe claim iyen o. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by iyaaje(m): 2:18pm On Aug 11, 2007 |
talo bami ri oko mi?where is my husband? |
(1) (2) (3) ... (94) (95) (96) (97) (98) (99) (100) ... (167)
Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 18 |