Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,174,157 members, 7,890,920 topics. Date: Tuesday, 16 July 2024 at 01:11 AM

Ade231's Posts

Nairaland Forum / Ade231's Profile / Ade231's Posts

(1) (of 1 pages)

European Football (EPL, UEFA, La Liga) / Re: Barcelona Vs Juventus : UCL (3 - 1) On 6th June 2015 by Ade231(m): 6:15pm On Apr 12, 2016
virginary:
Barca must win
baba ooooo eku koleda o oloru amawa penuyin o.
Health / Re: Alafia Logun Oro Itoju Topeye Ogun Ibile Todaju by Ade231(m): 10:20am On Apr 10, 2016
kadunasouth:
Atude/Asina/Bibo Asiri
Ori ako alangba tapa lojo epo obo die ao gun papo dada ao ra igba olomori kekere ao gun ma ose niwanba ao fi eyin ojo po ose yi ao ko sinu igba kekere yi idire kogbodo kanle month tobati denu igba toba we oseyi ibikibi tobadurosi ore owo yio wa owa sibe lojona odaju
baba ese pupo olodumare yio ma ti yin leyin o,ejo eyin ti e so yi se eyin oojo(new layed egg)ni abi eyin wo ni sir ese pupo hun ma reti esi yin sir.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 1:37pm On Mar 03, 2016
healthFirst:
IKEDE PATAKI:

Ao gbe eto yi lo sori whatsapp group nitori awon opuro ti won n fowo soya lori ayederu ogun lori ikanni yi ki o le seese fun wa lati ma yo won kuro bi a ba ti ri won. Ogun sise ati lilo kii se inkan ti o ye ki a ma pa iro fun awon eeyan. Bi oogun o ba pe tabi o je ayederu, o lewu pupo fun enikeni to ba je iru ogun be. Ao de fe ki awon epo to wa laarin alikama ba oruko wa je.

E dara po mon wa lori whatsapp number yi 08148398067, tabi ki e fi number yin sile nibi, ki a le add yin sinu group na. Iwulo Ewe Ati Egbo ni oruko group na. E dara po mon wa fun ojulowo oogun ati idaabobo lowo awon Oloogun eke.



Baba health ESE pupo polo yin koni daru o dara pupo big ese ni ki ada whatsapp group smile oda pupo koda semi gan nife so number mi niyi 08082819708 tabi 08032537603 ESE gan yio ma ju se fun wa o.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 7:27am On Feb 16, 2016
kadunasouth:

Ogun to wa nisale yi egbiyanju kese gbogbo arun toropo ma nkan osu obinrin kia kia iwosan ati alafia yio de ba ni kia kia koda eni tiko se nkan osuri to ba ni anfani lati lo ogu yi kia kia ni yio bere si se nkan osu, nkan osu yio wa lasiko toye yio si mowo duro lasiko toye

ogun Obinrin ti kori nkan osure Tabi orun tabi onse segesege
Egbo paran pupa ati paran funfun ati bara nla kan ati enu opiye ose dudu bi oni 100 naira tabi 50naira babase fe kiopo si ni ati kanhun bilala epo osan wewe tabi kage osan wewe si meji meji ao jo papo yio month fi omin oronbo wewe mu ogun yi daju saka
Otun sise fun atosi, Aremo ati obinrin ti inu ma nrun lasiko to nse nkan osure odaju odaju
NB ta base ogun yi tan ao bu sibi meji sinu igo oronbo kan yio mamun dede cup toma nwa ninu schinap aimaye eyan lolelo ninu iseyi.


Baba healthfirst ese pupo esi Ku Ojo meji meta otipe ti emi na ti wa ori ikanni yi nipase kan tabi ekeji mo dupe pupo ewe yio ma je o gbogbo adawole yin yio ma yori si rere lagbara eledua ibaje koni to siyin ma lo se ise yi mo si mope yio je bi idan ni e o pe fun wa o Ase edumare

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 1:33pm On Nov 26, 2015
kadunasouth:


Ewe olomuyinrin

Baba kadunasouth eku ise takun takun o,eledua yio ma ran yin se o ase ni tedumare,ejowo mofe oogun ti eeyan le lo fun obinrin ti nkan osu re nle ojo ti o si je pe ki ri be tele,sogbon awon igba kan wa ti oje pe laarin osu merin si marun ole mari rara ti yio ba si ri nigba miran o le je ojo meta sugbon eleyi ti o nse lowo bayi ti nlo bi ojo meje abi mejo bayi,ejowo mofi eledua beyin ni ki e fun mi ni oogun ti a le lo si ti o ba wa,ma ma reti esi yin ojo.ese pupo ao ma ri yin ba ni agbara olorun,ase.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 10:19pm On Oct 07, 2015
tunjiloveth:


---------------------------------------------
Baba Ekaro Ooooo, Se Daada Le Ji Oooo. Eepe Fun Wa Ooo. E Jowo Baba Mo Nilo Ogun Ayoko To Daju Fun Inkan Omo Kunrin To Ba Kere Ju Ojo Ori Eniyan Lo. Ese Baba
tunjiloveth:


---------------------------------------------
Baba Ekaro Ooooo, Se Daada Le Ji Oooo. Eepe Fun Wa Ooo. E Jowo Baba Mo Nilo Ogun Ayoko To Daju Fun Inkan Omo Kunrin To Ba Kere Ju Ojo Ori Eniyan Lo. Ese Baba
tunjiloveth:


---------------------------------------------
Baba Ekaro Ooooo, Se Daada Le Ji Oooo. Eepe Fun Wa Ooo. E Jowo Baba Mo Nilo Ogun Ayoko To Daju Fun Inkan Omo Kunrin To Ba Kere Ju Ojo Ori Eniyan Lo. Ese Baba


Baba health ejowo ogun ti o ma n mu oko tobi daada ti o ba wa edakun e fun wa mo nilo re mofi eledua beyin ese pupo

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 10:08pm On Oct 07, 2015
Davidifa:
Eyi todaju be apo ekan si mi ni email mi.Aleburudavid6@gmail.com


Alagba David mo send mail si address yin o ese gan.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 8:27pm On Sep 30, 2015
kadunasouth:

Ele lo ninu cup asile lo isasun ye na kafilo sugbon akogbodo fi isasun yi jo isemiran ao lore jusi ori akitan nio

Ese gaan baba ao ma ri yin ba lola eleduwa ko si ni pada leyin gbogbo wa,ema binu o se ihoho ni ao wa ti ao fi lo ise yi ni abi ale wo aso sorun se ese gaan.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 8:22pm On Sep 30, 2015
healthFirst:
IWE OWO BURUKU AIYE DANU LARA

Ao gun epo obo kunna dada, ao te gbogbo odu ife si lori, ao gbe kale bi wakati kan, ao wa gbo ewe ewuro topo laifi omi gbo, ao fun omi e sibikan, ao mu die ninu sakiti ewe ye die, ao bu die ninu epo obo tatefa le lori ye, ao pomo ose talewe fun ojo meje, ao wa gbe omi ewuro ye wole, ao du eje penpeye si Pata Pata, ao da epo obo yoku sinure, ao ropo dada, ao wa gbe losile iwe ni dede ago mejila oru, ao fipa gbogbo ara wa latoke dele, ao wa joko sori apoti fun bi wakati kan, lehin wakati kan, ao bu die Totowe nibi ose tagun ye, ao fiwe pelu omi lasan, ao wa fi ose yoku we fun ojo mefa toku pelu omi lasan ni dede ago kan oru ni o. Odaju

Baba health eseun pupo eledua koni fi yin sile nigba kankan gbogbo nkan yin koni dojuru
lola eledua ejowo se ao ni fi kainkain we rara ni abi ao lo kainkain ti aba ma lo titun kankan ni ao ma lo ni ojo kankan ni abi eyokan ni ao fi we iwe na tan ema pe fun wa o...Ase.

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by Ade231(m): 8:10pm On Sep 30, 2015
kadunasouth:
Awure Owo Olosekan
Ao wa oga gbigbe ti irure ka dada ao ra isasun tuntun olomori kekere odidi atare kan ao fi atare kan si legbe ao jo ao lo ra aso funfun opa kan kio te sile ki owa fi miliki olope kan lo lori aso funfun ati koko ati aso yi loju si ori atan. Ona owo yio si fun o kosi aburu kan kan lori iseyi
NB ti yio ba je funo isere koju osekan lo, Ale se ise yi lojo lasan sugbon ojo sunday lodaraju ijo tabajo lagbodo lo


Mojuba eyin agbalagba o ewe a ma je o ejowo se inu isasun titun yi ni ao ti po ebu yen pelu milk ni abi in nkan miran bi cup abi abo eseun gaan ewe o ma je fun wa o.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 9:58pm On Sep 27, 2015
healthFirst:
56

OOGUN ADEESU
Ewe akerejupon ao gun mose ao fi oyin po ao wa fi oga aye kan ti owo ti a ba fe bi 1000 tabi 5000, ao wa je ki o gba awo owo yen, ao wa mu owo yen kuro ao le ose yen mo ori oga na tiko n ifi ku ti yio ni aye ti ko fi ni ku ao wa fi owo na le lori pada ao ma sope ajo temi niyi o, ao ma mu ni ojojumo, elomiran ko gbodo fi oju ri ise yio.

IKILO PATAKI: Oogun yi daju sugbon oni eewo o...O lewu fun ogberi lati se, nitori awon omo eni naa yio ma ku to ba pe to ti n na owo yi...sugbon omo awo to ba mon owo we yio ba agba jeun.


Eku deede asiko yi o baba eku ojo meji o asi ku odun o,ejowo tori eledua kini eewo Adeesu yi eso fun wa mo fi eledua beyin,tori eru ma n ba emi fun irufe awon oogun bayi.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 12:39pm On Sep 08, 2015
sammyjay76:

@healthfirst, ejowo gege bi omo yoruba to mo nipa ewe ati egbo, kini e ri si iwosan nipa lilo ito ara wa?
Urine.

nje o n sise bi? ti o ba nise, iru awon nkan wo la le li fun ati bi a se le lo?
Ejowo gbogbo eyin ojogbon inu ile yi e bawa da si o.
Eseun.
ese pupo baba e ma pe fun wa lola eledua ase,gege bi omo yoruba ito ara wa dara fun iwosan ara,fun apere ale lo fun ti jankariwo ba n ko eyan ni oju ona ti aba fe ji to loru ao fi owo gbe ito wa ao fi boju lemeta ao si iyoku danu ese iba eyin agbalagba o.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 7:41am On Sep 08, 2015
healthFirst:


Eje Adiye na la fe lo. Oruka Ogun yen yio wa bo se wa ni o.
ese pupo baba eledumare yio ma funyin se o ejo mo beere fun ogun omo ekose e o si ti si nipa re rara edakun...
Culture / Re: .. by Ade231(m): 4:07pm On Sep 04, 2015
healthFirst:
18 AGBERO ONI FUNPA:
Egbo akarejupon ati owo osi ikun,ao fibo inu oruka
Ogun, Ao we ni owu dudu ati funfun, ao wa pa akuko adie fun, yio sun ninu
eje yen titi di ojo keji, ao wa ko ni ojo keji yen ao fi awo dudu rann
ni ifunpa. Odaju.

Erore:Apa eni tio ro soke yio wale bi a ba ti kuro ni
sakani eni na o. Aboru aboye!
Baba aboru boye o eku ise eledua yio so imon yin di otun ejo se oruka yen se ao na gbooro ni abi bi o se wa na ni kika ni ao lo ni ati pe se ao pa akuko yen si ile ni abi ao gbe eje re si inu igba kan ese pupo.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 2:25pm On Sep 04, 2015
healthFirst:
E jowo Eyin oluka, E sora nipa awon Oogun lati owo awon ti won n ba wa da si eto yi, awon Oogun ti ko pe ti po losri abala yi lati owo awon ayederu Oloogun. Awon Ayederu Oloogun ti n fi awon Oogun to je ayederu si ori abala yi pupo ju. Ao bere si fi ejo won sun awon to n dari eto abala yi. Ao si ma pa awon ayederu Oogun ti won ba ko re.
Oda bi ese se yi ajinde ara yio ma je yi ewo se oogun na lowa di nkan ti a mu ni yepere be ni oni kaluku sa n so orisi risi ti owu na ni ewo baba mo ti send msg si yin ni e.mail address ejowo mo n reti esi yin sir and again ejo mo ma n fe ogun ti eyan fi ma ni omo ekose pupo pupo ese gan ewe yio ma je fun wa o,ase edumare...
Culture / Re: .. by Ade231(m): 1:58pm On Sep 04, 2015
kadunasouth:
Ogun eyonu
Eyin ororo kan ewe ewuro 100 ao fi tele koko ao fi eyin ororo le ao tun ko ewe ewuro 100 le lori ao fi atare kan si ao ma jo to bati jotan dada ao sokale ao wa sadua si ewe ewuro eyokan ao waju si leyin tati sokale ao lo ao pin si ona meje ao bere lilore lojo sunday fun ojo meje
Nb ojo sunday nikan lale jo ise yi odaju
Yio je funyin o+++++++++++++++++++!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!
Ese pupo baba moti ri lilo re ni isale emi ni mio ka lo si isale esehun,ejowo mo ma need ogun ti eyan fi ma ni omo ekose (aprentise)lopolopo ese ma ma reti idahun yin.

1 Like

Culture / Re: .. by Ade231(m): 1:48pm On Sep 04, 2015
kadunasouth:
Ogun eyonu
Eyin ororo kan ewe ewuro 100 ao fi tele koko ao fi eyin ororo le ao tun ko ewe ewuro 100 le lori ao fi atare kan si ao ma jo to bati jotan dada ao sokale ao wa sadua si ewe ewuro eyokan ao waju si leyin tati sokale ao lo ao pin si ona meje ao bere lilore lojo sunday fun ojo meje
Nb ojo sunday nikan lale jo ise yi odaju
Yio je funyin o+++++++++++++++++++!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!!
Mo ki yin lopolopo,eku ise ewe ama je fun yin lagbara eledua,ejo Eyonu ti e fun wa yi kini ao fi ma lo abi ao kan ma la lasan ni ejowo e la yewa ese pupo.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 11:01pm On Aug 25, 2015
Aboru aboye o,ifa agbe wa lase edumare,ejowo mo ogun ti eyan fin ni omo ise lopolopo todaju ese pupo.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 8:47pm On Aug 25, 2015
baba ejo mo fe ogun ti eyan fin ni omo ekose(aprentise) lopo lopo,ejo baba yio ma ju yin se.
Culture / Re: .. by Ade231(m): 8:41pm On Aug 25, 2015
Mo ki gbogbo ile o,mo si tun ki baba pe aboru aboye eledua yio fun yin se gbogbo adawole yin yio ma je fun yin lase edumare,inu mi dun lati dara po mo ikanni yi tori pe mo gbadun e gan ni ti mo sin gbe iba fun ogbon ati oye ti e fi da ikanni yi sile,ao pe fun ara wa o lase edumare,ese gan o...

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 42
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.