Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,193,405 members, 7,950,900 topics. Date: Tuesday, 17 September 2024 at 05:04 AM

Hamykaz's Posts

Nairaland Forum / Hamykaz's Profile / Hamykaz's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by hamykaz: 3:17pm On Nov 17, 2015
Aku Dede asiko yii ooo, eku ogbon ooo....ejowo e fun wa ni asiri (ogun) ti eniyan fi ri alaanu....eyi ti omo araye fin se eyan laanu gidi....ewe a maa je oooo
Culture / Re: .. by hamykaz: 1:53pm On Nov 04, 2015
ewe a maa he o, ejowo kinni WO n pe ni, awure owo agboojo, nitoriwipe omo ile eko giga ni mi, a si to fe wole sugbon kosi agbara fun a won obi mi lati san owo ile iwe mi, ejowo mo ni lo Ogun ti alaanu fi n was eniyan ri, ipari OSU yii ni a maa wole, owo naa si din die ni egberun lona ogorun,#100,000
Culture / Re: .. by hamykaz: 5:05pm On Oct 28, 2015
eku asiko yii ooo, ejowo iko asthma maa n se mi, ogun wo ni mo le lo....ewe a maa je ooo
Culture / Re: .. by hamykaz: 5:04pm On Oct 28, 2015
ewe a maa je ooooo....ejowo ogun wo ni eyan fi maa san gbese ti eyan ba je

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 4
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.