Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,193,372 members, 7,950,780 topics. Date: Monday, 16 September 2024 at 10:00 PM

Janle's Posts

Nairaland Forum / Janle's Profile / Janle's Posts

(1) (of 1 pages)

Culture / Re: .. by janle: 8:26am On Feb 11, 2016
AGBERO ONIFUNPA:- Ao wa akuko adie to ti nko daadaa, ao yo abaweku re, ao fi kudi tio luju kan sinu re, ao wa sa ti yo gbe daadaa, ao wa ra ni awo funfun. Akiyesi pataki. E maje ki nkan kan ibi ise yi tie ba npa lawo o. Pelu ogo olohun ti wo bafe lu wa tabi won fe fi nkan kan luwa apa won koni lo soke bi won ba ti ngbe yo ma ro won ni. Moseba agba ikanni yi.

1 Like 2 Shares

Culture / Re: .. by janle: 8:14am On Feb 11, 2016
OGUN TI WON BA FI MAGUN SI OBINRIN LARA TABI SILE.< Ao wa iruke agbado to dori kole, pelu odidi atare kan, ao jo po. Ao fi singbere yipo ikun wa ao ni je ko de ibi idodo wa o. Moseba ajunilo.

1 Like

Culture / Re: .. by janle: 6:01pm On Feb 05, 2016
[OGUN IFURA] ao se'wo si omo oniguguru ao gbodo pe o. Ao ra iwon ba bi oni [50]naira. Ao gbe kale si ibi ti opo eyan bawa won o bawa je. Ka se be fun igba meta tabi ju bee lo. O daju gidi gan o. Mose iba agba o

2 Likes 1 Share

Culture / Re: .. by janle: 9:35am On Feb 04, 2016
[OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba. [OGUN MAJELE] iboju igbin pelu omo atare eyo mesan ao lo po ao fi singbere yipo orun wa. Pelu ogo olohun bi won ba fun wa ni majele je. Ao po. Aye mo juba.

1 Like 1 Share

Culture / Re: .. by janle: 9:26am On Feb 04, 2016
[FUN ANFANI ENI TON WA AYETA TO DAJU] ewe efirin, osedudu bi oni.[100]naira pelu oju olongbo kopo die. Ao gun ewe yi mo osedudu yi, ao te oju olongbo yi si lara. Ao ma fi we. Pelu kaninkan adayeba. Osi tun sise fun ada. Ao bu die sinu oti schnapes. Sugbon oni eewo o. Aye mo juba o.
Culture / Re: .. by janle: 3:32pm On Feb 03, 2016
E jowo kinin won npe ni omundun ewe ege
Culture / Re: .. by janle: 2:23pm On Feb 03, 2016
Kanbo loni mun, agbo 'sale loni ohuohu bi a ba n soro awon to ni imo nipa esin abinibi wa oga baba healthFirst adura temi si yin niyo. Eo ni feyinti sukun omo, ibanuje koni fi'le yin se'bugbe, gbogbo ohun te ba dawole ni yo ma yori si rere. Kori be ko se be. Ni agbara olodumare
Culture / Re: .. by janle: 2:16pm On Feb 03, 2016
Bawo ni mose le ri number yin tabi email yin
Culture / Re: .. by janle: 2:11pm On Feb 03, 2016
Mo nfe oogun ki nkan omokunrin tobi e fi ran mi lowo. Ifa yo gbe wa o
Culture / Re: .. by janle: 1:18pm On Feb 03, 2016
healthFirst eku ise ajinde ara yoo ma je o. Baba mofe iranlowo yin lori nkan omokunrin mi to kere. Mofe kie funmi ni ogun timo le lo si ni kia_kia. Oju koni tiyin o.

(1) (of 1 pages)

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 12
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.