Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,172,373 members, 7,884,827 topics. Date: Tuesday, 09 July 2024 at 04:18 PM

Yoruba Commonwealth and Politics - Politics (76) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Politics / Yoruba Commonwealth and Politics (680569 Views)

OPC - Faseun & Adams Unite For Security Of Yoruba Commonwealth / SEUN - Re: Yoruba-commonwealth-politics / Goodluck Jonathan Returns From Commonwealth Assignment (photo) (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (73) (74) (75) (76) (77) (78) (79) ... (384) (Reply) (Go Down)

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:53pm On Oct 28, 2015
Musiwa419:
Kilo'n sele ni ibi bayi ni ale yi o


Kii se pe oni nkan pataki kankan ta fe soro nipa ju wipe kako fi yooba soro fun wakati kan
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:53pm On Oct 28, 2015
PrincessJaneDoe:
Aare, Yoruba mi ku die ka to, amon mon gbiyanju. Mi o gbo ede mi o sad Yoruba Eko nikan ni mo le so.

Kini oruko awon mods section yi? (eforiji Yoruba-English mi cheesy)

alcatraz001, alcatraz002
Se eyin ni Ogbeni alcatraz ? Kilode to je wipe oruko obinrin ni etun je ?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:54pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:


E kaa bo oo
[b][color=#770077]Kilode ti awon yooba se wa feran tiredi awon olori pelebe ba yii.mii ti e ka won kun.alawada lawon olori pelebe yen

Enikan kan o ma kawo kun, yeýè la nfi won see. grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 9:54pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:



Kii se pe oni nkan pataki kankan ta fe soro nipa ju wipe kako fi yooba soro fun wakati kan
iyen na da
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:54pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:



grin grin cheesy Emi naa ti mo wipe gbogbo wan ma sa lo.O dami loju wi pe awon kan wa ni awon tiredi biafra yen ton ro ejo lowo lede geesi grin grin cheesy

Rilwayne001:


grin grin Tiredi awon omo olori pelebe (biafra) ma ndun bii kaasi nkan. Erin le mi ma nfi won rin.


Ti aba ti pada si ni so ede geesi, wan yo da wa sibi.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 9:55pm On Oct 28, 2015
grin gbogbo Ile ni aki oo
Ejowó ejeki asoró li ori itesi waaju awon omó Ile oduaà ati ori ilede oduaá


Ni ekan sii moki gbogbo eyin omo Ile oduaa oo cool
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:57pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:



Boya ka fun alagba shymm3x la ye lati so Yooba pelu geesi papo.


O da beyen
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 9:57pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:


Ilorin o se bee yato si Ogbomoso rara. Kini awon nkan ti efe mo nipa Ilu Ilorin ?


Awon ibeere mi po.mo ti bere lowo ogbeni yemaldo la no


Ta ni e ro wipe oma wun awon ara Ilorin la ti tele ti ilu Naijiriya ba pin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by PrincessJaneDoe: 9:57pm On Oct 28, 2015
Musiwa419:
Se eyin ni Ogbeni alcatraz ? Kilode to je wipe oruko obinrin ni etun je ?

rara o, mi o kin se alcatraz001 sugbon omo 'odua ni owun na

Obinrin ni mi ni toto. Se eyin ni Musiwa kan na grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 9:57pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:


E kaa bo oo





Kilode ti awon yooba se wa feran tiredi awon olori pelebe ba yii.mii ti e ka won kun.alawada lawon olori pelebe yen


Esè jarè

Moo ki yin pelu grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 9:59pm On Oct 28, 2015

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 10:00pm On Oct 28, 2015
shocked shocked shocked
wtf
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:01pm On Oct 28, 2015
9jacrip:



O da beyen

Oma se oo
Alagba sheymmx koole so yooba rarani lai fi geesi si ni? cheesy smiley

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:02pm On Oct 28, 2015
PrincessJaneDoe:


rara o, mi o kin se alcatraz001 sugbon omo 'odua ni owun na

Obinrin ni mi ni toto. Se eyin ni Musiwa kan na grin


Hahahaha

Ye mogbe oo
Jesu!!!

Awaada kerikeri gbaa le yi oo

Hahahah

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by laudate: 10:03pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:
zimoni i hope you already downloaded your Yoruba dictionary for today because no Yorubinglish ooo.I'll mention everyone from 9pm-10 pm

Good!! I'll take this advice you just offered to Zimoni. Am off to look for a Yoruba-English dictionary, myself. cool Just wait for me.... undecided

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:05pm On Oct 28, 2015
totit:


Oma se oo
Alagba sheymmx koole so yooba rarani lai fi geesi si ni? cheesy smiley

O da be o.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 10:05pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:
Maapu ile Oduaa lati ori paaaaji 'Proudly Yoruba' lori itakun facebook. https://m.facebook.com/TheYorubaPeople/timeline/story?ut=69&wstart=0&wend=1446361199&hash=-8486053728010333730&pagefilter=3&ustart=1&_rdr

ko ye ki gbobo ile kwara wa Lara maapu ile oodua.
nitori ara a awon nupe ati Fulani wa ni kwara no. wink
ode ye ki ara ile Delta wa Lara ile oodua o. shey e Mo? grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:05pm On Oct 28, 2015
Hahaha back to English



All of you who ran away,clap for yourselves grin grin cheesy Ilekehd especially

1 Like

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 10:06pm On Oct 28, 2015
PrincessJaneDoe:


rara o, mi o kin se alcatraz001 sugbon omo 'odua ni owun na

Obinrin ni mi ni toto. Se eyin ni Musiwa kan na grin
Ema binu. Mo ro wipe eyin ni alcatraz, oni ohun kan ti mo fe ba so tele. Emi ni Musiwa419 cheesycheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 10:06pm On Oct 28, 2015
Aareonakakanfo:



Awon ibeere mi po.mo ti bere lowo ogbeni yemaldo la no


Ta ni e ro wipe oma wun awon ara Ilorin la ti tele ti ilu Naijiriya ba pin

Ile Yoruba ni dajudaju. Awon ara Ilorin ori ara won ni abala miran yato si ile yooba. Idi ti won fii nse saaki fun Emir Ilorin o ju ti oro ESIN lo. Ko da gan, fulani ati hausa to wan ni ilu ilorin ko to Awon to wa nilu Ibadan nbi. Iba daraa ti eyin na ba le fese kan de Ilu Ilorin keri bi nkan se ri.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Shymm3x: 10:06pm On Oct 28, 2015
Loool.

Nyggahs in Paris speaking in tongues. Nice. grin

I can decipher a few of the things you are saying.

Anyway, the Duke of Ijebuland is training for IPOB youths at the gym looooooool.

#Following

2 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:06pm On Oct 28, 2015
laudate:


Good!! I'll take this advice you just offered to Zimoni. Am off to look for a Yoruba-English dictionary, myself. cool Just wait for me.... undecided


Loool till tommorow again.Its just for one hour,we're done for today tongue
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:08pm On Oct 28, 2015
WIZGUY69:


ko ye ki gbobo ile kwara wa Lara maapu ile oodua.
nitori ara a awon nupe ati Fulani wa ni kwara no. wink
ode ye ki ara ile Delta wa Lara ile oodua o. shey e Mo? grin

Hmm
Oti tò le yi, gege bi ati mo wipè itshekri wa lara awon omó Ile oduaa

sugbon ma gba wa ni imoran kia ma fi ipa munwan grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:09pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:


Ile Yoruba ni dajudaju. Awon ara Ilorin ori ara won ni abala miran yato si ile yooba. Idi ti won fii nse saaki fun Emir Ilorin o ju ti oro ESIN lo. Ko da gan, fulani ati hausa to wan ni ilu ilorin ko to Awon to wa nilu Ibadan nbi. Iba daraa ti eyin na ba le fese kan de Ilu Ilorin keri bi nkan se ri.

One word,Bbeautiful! your proficiency in Yoruba is A+

2 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Musiwa419: 10:09pm On Oct 28, 2015
Are we done writing in Yoruba ?

@ Rilwayne001 are you presntly in Ilorin ? Do you know Mohammed Awual Ali Jabata ?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Nobody: 10:12pm On Oct 28, 2015
How on earth did i forget to mention angiography.Flyoruboy thanks for showing up after the match grin cheesy I can see you viewing.you viewed for the whole hour cheesy

2 Likes

Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 10:12pm On Oct 28, 2015
WIZGUY69:


ko ye ki gbobo ile kwara wa Lara maapu ile oodua.
nitori ara a awon nupe ati Fulani wa ni kwara no. wink
ode ye ki ara ile Delta wa Lara ile oodua o. shey e Mo? grin

Well, you have a point. I think Nupe have their LG, but I don't think Fulani has any, there population is nominal. I hardly find Fulani or even hausa on the street of Ilorin compared to their population in Oyo state.
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 10:14pm On Oct 28, 2015
totit:

Hmm Oti tò le yi, gege bi ati mo wipè itshekri wa lara awon omó Ile oduaa
Ori iginle sugbon ma gba wa ni imoran kia ma fi ipa munwan grin

grin cheesy
ooto ni sha. awon gan o fe tele awon olori pelebe wink shebi e ka ni news aro yi? Awa omo Yoruba! aki she Olé Gbobo ibiti awon omo olori pelebe ba ti te ile si, oti di ile won niye grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Flyoruboy(m): 10:14pm On Oct 28, 2015
I am really gbaduing this thread. Make Una go on soun. cheesy
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by Rilwayne001: 10:17pm On Oct 28, 2015
Musiwa419:
Are we done writing in Yoruba ?

@ Rilwayne001 are you presntly in Ilorin ? Do you know Mohammed Awual Ali Jabata ?

I am currently in Ibadan, was born and brought up in Ib, but I have lived in Ilorin for 4 years. I will be going back next year to continue my Education.

I've once heared the name 'Jabata' he is a muslim scholar (salafist), is he the one you are refering to?
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by totit: 10:18pm On Oct 28, 2015
WIZGUY69:



grin cheesy

ooto ni sha.
awon gan o fe tele awon olori pelebe wink
shebi e ka ni news aro yi?
Awa omo Yoruba! aki she Olé
Gbobo ibiti awon omo olori pelebe ba ti te ile si, oti di ile won niye grin

Kilo'n je News ke?
Iroyin abi beeko?

Hahahahah

smiley smiley grin
Re: Yoruba Commonwealth and Politics by WIZGUY69(m): 10:18pm On Oct 28, 2015
Rilwayne001:


Well, you have a point. I think Nupe have the LG, but I don't think Fulani has any, there population is nominal. I hardly find Fulani or even hausa on the street of Ilorin compared to their population in Oyo state.


like how many LG are the Nupes in charge of?
I don't really understand how kwara was positioned in North Central. if we even study the map very well, it's still part of SW. kwara & Oyo is sharing the same border.

(1) (2) (3) ... (73) (74) (75) (76) (77) (78) (79) ... (384) (Reply)

Kenyans Are Far Behind Nigerians In Every Aspect – Fani-Kayode / Anambra light of the nation, eastern economy power house. / Enugu, The Pride Of The East.

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 36
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.