Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / NewStats: 3,171,815 members, 7,882,828 topics. Date: Sunday, 07 July 2024 at 04:19 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (199392 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:31am On Sep 30, 2009 |
Heheheheh Remii , mo mo feeling yen |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:45am On Sep 30, 2009 |
tubabie: O see jare, Coffee da oran leni sha, mo gbagbe obi si Naija, lol |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:59am On Sep 30, 2009 |
FBS, Alaafia ni mo wa,iwo nko? inu mi ti e dun pelu nkan ti awon boys mi gba ni nou camp lana remii, se ki n fi obi ranse si e ni? tu, okun oo, me'e ro de o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 11:15am On Sep 30, 2009 |
IFELEKE:But ki lo de ti ref se cancel goal Dynamo? or is the ref a racist? Alaafia ni mo wa. Bawo ni gbogbo e? Whats new? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 11:19am On Sep 30, 2009 |
IFELEKE: O se ore mi, that would an expensve kola, maa survive, mo gbiyanju lati ma han oorun pupo ni killasii, ti mo ba de han oorun, won a gba bee naa ni., eni so ewure mo 'le ni yoo fun ni paki, rflmao. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:05pm On Sep 30, 2009 |
eyin guys yi man pa mi lerin shaa all di time, E kaa saan o se e waa al'rite sha! Remii, maa sun ni kilasi o, to ba je pe o mu "zobo pelu agbo die" dani, ni, ko baa helepu re die, Zobo, ni mo man mu tin ban kawe nigbati mo wa ni kilasi, mo ni igo melo kan ninu ero mu'kan tutu mi nibi lati 9ja, ti mo ban wooo loju bayi, lasan, orun o je kun mi, tirayi re woo ti o ba ni, Eyin Boyz mi, IFE, FBS, kOMATSI, POSA, DAYO, ati awon orekelewa waa naa, TU, and co, ki lon sele jare, wetin de happen? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:07pm On Sep 30, 2009 |
FBS: btw,check out this link: http://www.lulu.com/content/paperback-book/ajantala-and-other-yoruba-folk-tales/7251126 remii, Pele ma han oorun ju ki awon omo kilaasi e ma so e ni jona oloorun. Padi mi orile, ki lon sele? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:17pm On Sep 30, 2009 |
@ Ife, mo wa jare, no-ting dey sele o, mo wa ni lunch break, mo ni kin maa bubble si Bracket, Yori-Yori, lori ijuko pelu sandwich mi , orin yen se mi bakan jare, mo laki e baje, iwo nko, so waa, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 1:19pm On Sep 30, 2009 |
Ohhhhhhhhh IFELEKE, that was my favorite story . My Mum could say that story with so much description , hey I loved Ajantala!!!! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:27pm On Sep 30, 2009 |
ooohhhhhhh Ifeleke, u have scored 200per cent, Men!! that brought back memories men!!, igba to change nisinyi, gbogbo nkan ti awon omo waa mo nisinyi ni Computer, DS, Laptop, Nintendo i sat on a mat in NTA those days to listen to Jimmy Solanke TELL those stories then, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:29pm On Sep 30, 2009 |
ooohhhhhhh Ifeleke, u have scored 200per cent, Men!! that brought back memories men!!, igba to change nisinyi, gbogbo nkan ti awon omo waa mo nisinyi ni Computer, DS, Laptop, Nintendo i sat on a mat in NTA those days to listen to Jimmy Solanke TELL those stories then, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:50pm On Sep 30, 2009 |
tubabie: Orilee9ice:Ajantala! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deetosh(f): 6:21pm On Sep 30, 2009 |
Mo ki gbogbo ile ooo. E deku ipalemo odun ominira. Bo tile je wipe there's notin worth celebratn in d country Eeto eko ti doju bole, kosi aabo ati Health care system to ye kooro, kosi oju ona ti oodara, Awon aladari ti ani - ka fi senu kade ke ni oro won.Sugbon, ka shi ma dupe pe kosi ogun, ko si iyan, ade walaye lati ri ojo naa. Adura mi ni wipe olorun yoo fun wa ni awon adari to wulo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 7:17am On Oct 01, 2009 |
Mo tin dagba sha, Mi o ranti itan Ajantala yen mo daada sha, Tubabie wa fi ohun didun re so itan na fun mi. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 7:25am On Oct 01, 2009 |
IFELEKE:Ifeleke! mehnnnnnnn. . .you too much. AJANTALA!!! boy oh boy! Good people of Nigeria, Mo ki yin oo! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 7:48am On Oct 01, 2009 |
Eyin eeyan mi ekaaro dayokanu: Ma worry ti o ba ti ready , ma so itan naa fun e, sugbon £20 per hour ni o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:20am On Oct 01, 2009 |
Eyin eniyan mi a ku odun ominira ooo. A dupe fun anfaani ti Olorun fun wa ti o se oju wa. Olorun yoo ba wa tun ilu naa se oo. Amin. Oju yoo ma ri odun. Asodun modun aso su mo su, odoodun mi peregun ruwe, Ajinde ara yoo ma je, Amin. Gbogbo ojelu ati obayeje to wa ni leyi: Kiisan fun eesan, ki wo fun owo., Afi apoti rori kan kiigbadun oorun, bi aburu ba lo too bo odo won ni yoo dari si. Obo kii jere lehin oko, adanu ni gbogbo won oo ba pada si ile won. Gbogbo awon to je anfaani eko ofe, ti won ko lfe ki awon omo ode iwoyi ni eko gidi, ibiti ti won ko ti ni ireti ni won yoo ti pade ijakule. Pelu ogo Olorun ati eleda awon komo owo komo ese ti nje iya yoo ri bee, Amin. E ku odun ominira ooooooooooo. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 12:59pm On Oct 01, 2009 |
eyin omo Nigeria a ku ile o,se alafia la ba yin "ara" o le bi? bi o le ko le wole Remii:you mean aku odun inira? dayokanu:hmmmmmmmmmm,i hope the story telling will not lead to another "thing" sweeter than the story? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:41pm On Oct 01, 2009 |
happi independence day oh evrybodi, mo fe so pe ki lon dun ninu wa naa jare, sugbon oorun a koo waa moo see daa daa ni ilu yen loruko jesu Amin! Temi ni wipe, Fashola 4 President, a ti rin'kan ton'se le'ko ile, se e o feel wipe o lee see ni federal level ti won ba fun ni chance, abi se mi o rii sooo?? eyin ara? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 1:57pm On Oct 01, 2009 |
Orilee9ice:did u say fashola for president?if na joke make you stop am o,fashola ko fashobo ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:59pm On Oct 01, 2009 |
haba iya ngbalife, wetin e do u?? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by U1(m): 3:00pm On Oct 01, 2009 |
Hin hora nibi o. Ewo wa ni geesi ti gbogbo yin wa n so, e so Yoruba fun mi ojare. Esi ku isimi na. Eyin ti e mo awon |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:02pm On Oct 01, 2009 |
Ma worry ti o ba ti ready , ma so itan naa fun e, sugbon £20 per hour ni o Oya mo ti redi, Mo ma nawo, ma tun na ara pelu. hmmmmmmmmmm,i hope the story telling will not lead to another "thing" sweeter than the story? Se o buru ni? A n wa owo lo, a pade iyi lona, ti a ba lowo na tan sebi iyi ni a fe fi ra. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 5:16pm On Oct 01, 2009 |
E n le o eyin eeyan mi, a ku odun ominira bo ti le je 'pe omi inira ni eyi je fun wa ni naijiria. ogbeni dayo soki soki, o tun ti gbe se e de abi? o to jo meta, se alaafia lo wa? aaaro e so wa gan ni |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 9:17am On Oct 02, 2009 |
Good people of NL- Yoruba Land, mo ki yin oo! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:00pm On Oct 02, 2009 |
Eku Ojumo gbogbo ile (dayo,tope-lobi,fbs,tubabie,posa,pafati,remii,orile,detoosi,u1 a.b.b.l.) A ku popo shin shin opin ose. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by shayoor(f): 12:22pm On Oct 02, 2009 |
kaaro o,se dada loji? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 12:36pm On Oct 02, 2009 |
Eki aroo oooo, daadaa ni mo ji. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:45pm On Oct 02, 2009 |
posa, bawo ni? o to jo meta, se alaafia lo wa? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 12:52pm On Oct 02, 2009 |
alaafia ni mo wa. Iwo nko ? ba wi ibi ise ? hope pe o wa pa sha! |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Abbeycity4(f): 1:08pm On Oct 02, 2009 |
Oga o!! hun kini mo le so na? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Abbeycity4(f): 1:10pm On Oct 02, 2009 |
ok ife mo ti de o |
(1) (2) (3) ... (89) (90) (91) (92) (93) (94) (95) ... (100)
Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá
Viewing this topic: 1 guest(s)
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 40 |