Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,171,815 members, 7,882,828 topics. Date: Sunday, 07 July 2024 at 04:17 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (91) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (199391 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 12:14pm On Sep 29, 2009
chamotex:

Ese modupe o
Jeje mi ni mo wa o ti omo kan ni ohun fe fi oko sere
Mo de so fun wipe mo wa on strike as per ASUU level.

Mo lo si ibi moto mi nisin yi, taya moto mi ti jo but mo wa sure pe omo oloyan nla yen ni o se ise na.
~Mo ma deal pelu e.  angry angry angry angry

hahahahaha  grin grin, Igba ti ooni jawo lati ma le obirin kiri . . . . . . . . balogun leyin obirin take it in stride tongue


FBS:

Tubabie, ki lon se le? how are you re?

Mo wa alright, ose wink Mi o gbagbe Young Chelsea goon wa o wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:21pm On Sep 29, 2009
@Chamo, VW Polo naa o bad now, so sho sure pe o tii ba ile je tele, as pee ko ti mu omo naa ni pa, instead of dee dee,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 12:27pm On Sep 29, 2009
tubabie:

Mo wa alright, ose wink Mi o gbagbe Young Chelsea goon wa o wink
O ni wipe ki n ki gbogbo yin. Don't worry very soon he will start posting too. grin

chamotex:

Mejeji sad angry

VW POLO. . . . mo fe ta gan sef.
O mean wi pe o fe ta oyan ati taya moto or what? grin grin grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 12:28pm On Sep 29, 2009
gba be!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by chamotex(m): 12:38pm On Sep 29, 2009
M
Orilee9ice:

@Chamo, VW Polo naa o bad now, so sho sure pe o tii ba ile je tele, as pee ko ti mu omo naa ni pa, instead of dee dee,

Mi o ti naa rara, mo kan ma n fi idi e sere ni

FBS:

O mean wi pe o fe ta oyan ati taya moto or what? grin grin grin

Ti o ba possible, ma ta gbogbo e po.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 12:40pm On Sep 29, 2009
shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked shocked

what is going on hia??!   Oon fi idi babe na shere, shofe fe ni ?



abi shey asewo ni girl na ni   lipsrsealed lipsrsealed lipsrsealed
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by KennyG6(m): 12:48pm On Sep 29, 2009
mo ki yin ooooooooo, ago oni ile oooo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:51pm On Sep 29, 2009
Mi o ti naa rara, mo kan ma n fi idi e sere ni

cHAMO, now i am confused, sebi o ni o waa on strike nigba ti omo naa so pe oun fe fi oko  e sere, ki lo de ti ofe fi'di e sere nisinyi  

ogbeni dee dee o, there is more there ti o so fun waa o, wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:52pm On Sep 29, 2009
wink Kenny G (oloruko mi) baa woo ni o? so waa pa leni ki lon sele jare
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 12:54pm On Sep 29, 2009
ki lon sele?
Orile
padi mi, ma binu simi, ise po gan fun mi lana ni o je kin da e lo'un, bawo ni? awon ti agege n saaro e gan ni oo, o fe pada wa je ewa aganyin yen abi?  wink

FBS,
Daada ni mo wa joo padi mi, bawo ni? se alaafia lo wa? abobo(our baby) wa nko? se o n toju e daada?

Posa,
Ki aro, sosan? ma binu pe mo tete lo lana, ore mi di e ni. . . wink
Kamooteesi
O tun ti de abi? awa naa ti saaro e gan  grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by KennyG6(m): 12:55pm On Sep 29, 2009
orile, mo wa pa o, se dada ni mo ba ile ooo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 12:57pm On Sep 29, 2009
Orilee9ice:


cHAMO, now i am confused, sebi o ni o waa on strike nigba ti omo naa so pe oun fe fi oko e sere, ki lo de ti ofe fi'di e sere nisinyi

ogbeni dee dee o, there is more there ti o so fun waa o, wink

O se ti o be re because emi na wonder. grin

IFELEKE:

FBS,
Daada ni mo wa joo padi mi, bawo ni? se alaafia lo wa? abobo(our baby) wa nko? se o n toju e daada?

O se ore mi. Alaafia ni mo wa, iwo nko? Adupe ni owo Olorun, baby is doing fine.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:58pm On Sep 29, 2009
@ Ifeleke, ba wo lo see mo jare. mo fe je'wa aginyin yen again ni jare, maa yoo si yin laipe jojo, se ile n'to? awon ara ilesha nko? e raa se awon ni mo mi a talking to ooh!!, wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:03pm On Sep 29, 2009
@FBS abi o, as The chief gboromiro of amuludun land, mo surmoun Chamo si Bigz boyz court" ATI WAA DAHUN AWON IBERE KAN in ago waa, o da mi loju pe oro poo ninu iwe kobo, abi se mi o rii so eyin boyz and galz, wink grin cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 1:07pm On Sep 29, 2009
O rii so Orilee9ice.
Hereby the People of NL vs Chamotes: Oro Oyan nla ati taya moto VW Polo. cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:10pm On Sep 29, 2009
FBS:


O se ore mi. Alaafia ni mo wa, iwo nko? Adupe ni owo Olorun, baby is doing fine.
alaafia naa ni mo wa oo, o kan je 'pe inu mi o dun pelu nkan ti awon omo siasia yen gba lana pataki julo pelu nkan ti ref. yen se.

Orilee9ice:

@ Ifeleke, ba wo lo see mo jare. mo fe je'wa aginyin yen again ni jare, maa yoo si yin laipe jojo, se ile n'to? awon ara ilesha nko? e raa se awon ni mo mi a talking to ooh!!, wink
nitooto?
awon ara ulesa wa daada, a n je iyan ati eran igbe loore koore
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:13pm On Sep 29, 2009
Ok, by the powers confired on me, wink A fun Chamo ni 24hours lati fi ara han ni ago wa fun ipade kekere, failure 2 do dat o je wipe a maa so fun awon olopa obirin oloyan n'la meji pe ki won loo kaa mo'le ki won gbee waa lodindi wa si ago waa, (i know he will like that one, rascal boy, ) wink omo yen ti ya pookii!! sha!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:16pm On Sep 29, 2009
@ Ife, Gbaaaaa bee o, bo see waa ni yen o, e ku eran jije o loore koo ree, temi daa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:17pm On Sep 29, 2009
Kenny G, MAA BINU mi o paa e ti jare, se everyting wa alrite? sha! kaa boo sori afefe amuludun yi, o maa gbadun re gan ni, wink cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 1:23pm On Sep 29, 2009
IFELEKE:

alaafia naa ni mo wa oo, o kan je 'pe inu mi o dun pelu nkan ti awon omo siasia yen gba lana pataki julo pelu nkan ti ref. yen se.
Awon boys yen wa annoying gan. I mean won ni to up to 20 chances amon boolu ko, ko fe wo inu net.
We all expected a better performance from Siasia and his boys. Mo hope wi pe a si le qualify.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by KennyG6(m): 1:26pm On Sep 29, 2009
asiko naija ti lo, eyin boys african teams ti advance ko ja naija
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:26pm On Sep 29, 2009
Orile,
Fi kamoteesi sile joo pelu isokuso e, ko si iyato laarin oun dayo ati pafati.
Iru eran ewo lo fe?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:27pm On Sep 29, 2009
@ FBS and Ife, nipa siasia and his men, my sentiments exactly, cry angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 1:30pm On Sep 29, 2009
FBS,
Mo ti so lana 'pe o ye ki a paaro awon alase t'o wa nidi boolu wa(NFF).
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 1:39pm On Sep 29, 2009
ni 9ja. ti won ba ti pe lori oye, won a ti yoo, ise o ni see see fun won mo, won need eje tun tun ninu egbe yen, angry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deetosh(f): 3:12pm On Sep 29, 2009
Kin she awon alashe nikan, awon boys yen gangan ti yoo, so won really mu ni okun kundun mo. gbogbo won loni club ti won ti gba owo to joju,so dey don't av anytn 2 lose. ogota ogo ota owo alaru o pe

ko de da, bi awon agbabolu Brazil she n gba owo to ni club won, won je fi ilu won shere, dey r still leading.


Ema binu wipe mi oki yin jare, kiss inu awon boys yen bimi gan ni embarassed

bawo ni? she ise nlo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 3:19pm On Sep 29, 2009
abi o deetosh, i feel u jare, i am soo annoyed 2,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:51am On Sep 30, 2009
Kamoru abi Kamoteesi,

O je sora ki o ma kan idin ninu iyo
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 8:13am On Sep 30, 2009
E ku ojumo eyin eeyan mi, se daada mo ba yin? Ojumo ire fun gbogbo wa loni o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 8:51am On Sep 30, 2009
Amin o! Ifeleke, bawo ni?

Mo ki gbogbo ile oo!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 10:06am On Sep 30, 2009
Ekaaro o gbogbo ile wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 10:21am On Sep 30, 2009
E nle nbehun ooo.

(Egba mi lowo jet lag ooo, I am awake at night and sleep thru classes, ojo meta ti koja bayi, lol)

(1) (2) (3) ... (88) (89) (90) (91) (92) (93) (94) ... (100)

Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 65
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.