Stats: 3,178,760 members, 7,905,815 topics. Date: Tuesday, 30 July 2024 at 06:58 PM |
Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (200329 Views)
If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)
(1) (2) (3) ... (85) (86) (87) (88) (89) (90) (91) ... (100) (Go Down)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 4:34pm On Sep 18, 2009 |
Everybodi. ke ni 9ice weekend o, emi n'bubble loo ni yen o, e jeki gongo ko soo ni weekend yo i especially to je itunu awe, iyimoye eran ti won maa ti pa l'eko nisinyi, o je kin' ranti ile o, anyways e kash di vibe o, ire o |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:44pm On Sep 18, 2009 |
Orilee9ice:gbogbo aiye. . . sa ma rora oo, ile n yo oo IYA NGBALI:gbogbo eyin to kundun(feran) ati ma'a j'ogede redi ni mo n bawi oo. Iya egbe mo awon omo egbe, e mo ra yin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:38pm On Sep 18, 2009 |
Ifeleke, Won ni aisoro yan oro lo pa elenpe akoko ti o ni igba wuwo ju awo lo. Ngbo tani iwo n bawi |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 5:41pm On Sep 18, 2009 |
IFELEKE:like say you no dey follow chop o je ma je ka tu asiri e lori ibi bayi dayokanu:ma da lohun jare eru wa lo nba ko je daruko anybody afi to ba fe je iyan nisu loku |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:00pm On Sep 18, 2009 |
dayo, iwo ati oluku e pafati mo n ba wi, eyin mejeeji e rora se oo, ile n yo oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:02pm On Sep 18, 2009 |
IYA NGBALI:gbenu so'un n ti e ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 6:05pm On Sep 18, 2009 |
IFELEKE:oro na dun o fe ke ![]() ![]() ![]() ![]() ![]() E jowo eyin enia mi lokunrin at lobirin,melo ninu wa lo ti de ondo ri? ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 6:28pm On Sep 18, 2009 |
pafati, O tun ti gbe'se e de? Mo ti de ondo ri o, ki lo fe mo? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 7:45pm On Sep 18, 2009 |
Eyin eniyan mi iku imura opin ose ooo, eyin tee wa ni Naija, erora je igbadun opin ose to dapo mo isin ojo meji oo. Odun ayo la o se o. Amin. |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 8:58pm On Sep 18, 2009 |
Remii:e jo sir e ma je ki iku mura opin ose o unless ti e ba fe fun iku lagbara nikan loku,e je ki iku ma lo lona tie ki awa de ma gbadun opin ose lo,meanwhile emi nlo sile lati lo gbadun ara mi lale yi,i am in the mood for ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bandely(m): 8:59pm On Sep 18, 2009 |
Iya Ngali, ile ti su, se eni lo da ina fun oko yin ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:31pm On Sep 18, 2009 |
IYA NGBALI: O see jare padi mi, that was a slip of finger, E ku imura opin ose, |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by bandely(m): 9:20am On Sep 19, 2009 |
Ekaro ooo, se dada la ji? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by sisiologe1: 10:29am On Sep 19, 2009 |
e karo o eyin egbon mi ati eyin padi mi, se e wa pa?a ku weelend o,se o bubble?e je ko ma bubble o IYA NGBALI:say mama,mama o ni gba,mama ti o gbagba kugba,e sa rora,e ma je ki won kan yin lehin o,eyin na e de ma kan won lehin,ori lo ma porun,orun lo ma pa ori,bawo ni se e wa pa ![]() IFELEKE:uncle ife kini e lo se ni ondo?se omo ondo niyin ni abi omo ondo no wifey yin?e ku weekend |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 6:54pm On Sep 19, 2009 |
sisi ologe:sisi ologe howdy?se o wa pa?its been a while,i hope all is well?take kia ara e ![]() IFELEKE:ok let me read from others before i tell you why ![]() ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 6:17pm On Sep 21, 2009 |
Barka da Sallah |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 7:37pm On Sep 21, 2009 |
IYA NGBALI: why to shen bere ? ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 8:10am On Sep 22, 2009 |
Iyangbali, Won ni won ri e ni Ifo, Ki lo wa de Ado? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 11:32am On Sep 22, 2009 |
Mo ki gbo gbo Ile oo! ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:02pm On Sep 22, 2009 |
Se o fe je oye akiniku ni? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 7:50pm On Sep 22, 2009 |
eyin padi mi mo ki gbogbo wa kun odun o,emi wa a se opo odun laye o odun a ya ![]() ![]() Ifeleke{oko gbogbo omoge} o ga fun e o,infact o surprise mi gidi gan ni,almost everybody ninu ilu yi to nse odun itunu awe ni won gbe ounje ranse si mi including awon ti won ma tu bebe but mi ri itan efon to kere ju lati odo re,se be lo lahun to ni abi economy melt down lo fa?padi mi o yami lenu gan ni o,ta ba nja ko dabi ka ku now,anyway sa mi o binu si e,but ma ma wu iwa ahun mo its unyorubalike ![]() ![]() ![]() dayokanu:o ya mi lenu o,boya o de fe ma ja ticket fun wa ni ![]() dayokanu:mo lo si ado lati lo ![]() ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 10:06am On Sep 23, 2009 |
IYA NGBALI: Egin pafaati, kinni wahala ti o ni pelu Ondo ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 11:55am On Sep 23, 2009 |
Ki lo wa se Iya Ngbali pelu Ondo, ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 12:44pm On Sep 23, 2009 |
Where is Ifeleke? ![]() ![]() @Topic Eyin eeyan mi ekasan o, otojo meta ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 1:05pm On Sep 23, 2009 |
dayokanu:Dayo, se ebi npa e ni? What is wrong in saying hello to the house? O je lo ba awon nazi boys e. Mogbo wi pe won ti fe rig another election ni ilu germano. ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deetosh(f): 2:26pm On Sep 23, 2009 |
Eku dede iwo yi ooo, se wapa? eyin ti naija bawo ni isinmi. dayokanu: Eshe eku akesi, emi nan kiyi, eje ko mo ni beyen sha. ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:42pm On Sep 23, 2009 |
sisi ologe:sisi ologe bawo ni?se alaafia lo wa? mo ni awon eeyan pupo ni ondo ni oo, mo de ma n lo be won wo loore koore. IYA NGBALI:Pafati ma binu, mo ma fi itan alangba pelu ifun esisi ranse si laipe. tubabie:t.y, me'e li bi kuo mu mi si oo. . .se ala lu ese? aayun re so mi lopo oo ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 2:47pm On Sep 23, 2009 |
Gbogbo Ile(tubabie,tope-lobi,remii,dayo,pafat,fbs,sisi ologe,detoosh,posa,bandele,orile. . .a.b.b.l.) Eku ojo meta, se alaafia ni gbogbo yin wa? Remii A n reti nkan odun wa oo |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 2:56pm On Sep 23, 2009 |
Ife, mo ma ti miss eh gan Bo ni ? ![]() ![]() |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 3:26pm On Sep 23, 2009 |
Posa, Emi gan ti miss e, ke tiri,sosan? ile iwe e nko? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 3:28pm On Sep 23, 2009 |
IFELEKE: O san. Ile iwe lo daa daa, iwon nko, bawo ni ibi ise ? |
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 4:03pm On Sep 23, 2009 |
posa, ibi ise n lo deede, adupe lowo olorun. . .je ka soro lori yim. |
(1) (2) (3) ... (85) (86) (87) (88) (89) (90) (91) ... (100)
Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá
(Go Up)
Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10) Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 53 |