Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,171,831 members, 7,882,915 topics. Date: Sunday, 07 July 2024 at 06:29 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (89) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (199408 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / Do You Speak Yoruba? / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (100) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:48pm On Sep 23, 2009
Detosh,

Ere la wa se a o ba ti ija wa o.

Eku deede iwoyi o
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 8:27am On Sep 24, 2009
Eku Ojumo gbogbo ile,
se daada le wa?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:01am On Sep 24, 2009
Bi emo jiire l'opo ile, agunla emo
Bi afe bojo jiire ni iho re, aguntete afe
Bi eyin temi l'adugbo yi ba ti jiire abuse buse.

Se daadaa la ji o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 12:59pm On Sep 24, 2009
Ekiii aroooo gbogbo ara !!! cheesy cheesy cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 2:15pm On Sep 24, 2009
E yin good people. E ku ile oo!
Ifeleke, Remmi, tubabie, posakosa,ologe, detosh. . .!

Se daa da ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by posakosa(m): 2:20pm On Sep 24, 2009
dara dara la wa,

ewon nko ?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dayokanu(m): 5:44pm On Sep 24, 2009
Ti a ba bi ekun ni igba ojo, ti a ba bi eerin nigba ogbele.

O daju wipe ori erin a tobi ju ti ekun lo.

Eyin eniyan mi, e ma bori gbogbo ota.

1 Like 1 Share

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 8:50pm On Sep 24, 2009
IFELEKE:

sisi ologe bawo ni?se alaafia lo wa? mo ni awon eeyan pupo ni ondo ni oo, mo de ma n lo be won wo loore koore.Pafati ma binu, mo ma fi itan alangba pelu ifun esisi ranse si laipe.t.y, me'e li bi kuo mu mi si oo. . .se ala lu ese? aayun re so mi lopo oo  wink
Awun buruku niwo padi yi sa no wonder ti omo to ma nde bebe ye se yari pe ohun o le fe e,se nkan ti wa fi ma feed iyawo niye?shame on you tongue tongue tongue

As for my question pe talo ti de ondo ri,
eni ba de ondo amo ti ko ti do ondo, ko ti do ondo ri,nitoripe iye gangan leyan fi nmo pe eyin ti de ondo ri tongue tongue tongue tongue tongue

1 Like 1 Share

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by dipo2much(m): 5:36am On Sep 25, 2009
eka aro n bi o. Shey daada laji
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:41am On Sep 25, 2009
IYA NGBALI:

As for my question pe talo ti de ondo ri,
eni ba de ondo amo ti ko ti do ondo, ko ti do ondo ri,nitoripe iye gangan leyan fi nmo pe eyin ti de ondo ri tongue tongue tongue tongue tongue

Olori skempe ni iwo omo yi shocked Onisokuse si ni e pelu grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by topsy25(m): 8:43am On Sep 25, 2009
dipo2much:

eka aro n bi o. Shey daada laji

A wa daadaa jare dipomejimosi grin aa jiire bi
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IFELEKE(m): 10:15am On Sep 25, 2009
Ojumo Ire fun gbogbo wa loni oo. . .Ojumo yi ko mon wa s'owo, ko mon wa s'omo ko mon wa si aiku baale oro.
tope-lobi,dayo,pafati,tubabie,fbs,posa,dipo,remii,detoosh,sisi ologe,bandele. . .a.b.b.l.
e n le oo

IYA NGBALI:

Awun buruku niwo padi yi sa no wonder ti omo to ma nde bebe ye se yari pe ohun o le fe e,se nkan ti wa fi ma feed iyawo niye?shame on you tongue tongue tongue

As for my question pe talo ti de ondo ri,
eni ba de ondo amo ti ko ti do ondo, ko ti do ondo ri,nitoripe iye gangan leyan fi nmo pe eyin ti de ondo ri tongue tongue tongue tongue tongue
Oro iwo omo onisokuso yi ti sun mi, mo ma lo fi ejo e sun l'ekiti.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 2:43pm On Sep 25, 2009
O GAA O, KINI MO TI MISS NIBI BAYI O, SE GBOGBO YIN WAA PAA, se e gbadun sallah hols yin sha?, cry
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 2:51pm On Sep 25, 2009
IFELEKE:

Ojumo Ire fun gbogbo wa loni oo. . .Ojumo yi ko mon wa s'owo, ko mon wa s'omo ko mon wa si aiku baale oro.
tope-lobi,dayo,pafati,tubabie,fbs,posa,dipo,remii,detoosh,sisi ologe,bandele. . .a.b.b.l.
e n le oo
Oro iwo omo onisokuso yi ti sun mi, mo ma lo fi ejo e sun l'ekiti.

@Ifeleke, ma da ara e laamu lori Iyangbali, oun ni Hugh Hafner cum Larry Flint of this trend.
@ Iyangbali, boo see nse naa ni koo maa se lo.
@Orilee9ice, sallah dun gaan ni, imagine I have gained 2kilos back in just days. lol.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 2:58pm On Sep 25, 2009
smileyRemii .bo see waa ni yen o, o daa mo baje, how i wish mo waa le'ko ile, anywayz,
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 11:45pm On Sep 25, 2009
Hello, gbogbo eyin omo yoruba
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by deetosh(f): 4:13pm On Sep 26, 2009
Eku igbadun oo gbogbo ile, ede ku igbadun opin ose.

@dayokanu
eere ni mo man se
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:31pm On Sep 26, 2009
Eku Ile!

Se eyin omo wipe omo yoruba ni mi?

Mo Gbona Feli Feli! E wa da omi TuTu si mi lori!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 4:45pm On Sep 26, 2009
@faakay, ni haa.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 4:53pm On Sep 26, 2009
Remii:

@faakay, ni haa.

lool, ni haa ke?

Ni haa ko ni won pe ooo

Ni hao!!!

Emi ma so wipe: Wo hen hao!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:01pm On Sep 26, 2009
faakay:

lool, ni haa ke?

Ni haa ko ni won pe ooo

Ni hao!!!

Emi ma so wipe: Wo hen hao!

O daa bee, mo tie gbiyanju maa yin ara mi. Wakati meta pere ni mo lo ni papa oko ofurufu ti Hong Kong nigbati mo nkoja lo si KL ni odun melo kan sehin. Bawo ni gbogbo awon chinko ladugbo yen. Awon eniyan won yen po sha, afi bii ki afi okan se eni okan. Ao ko ere oko de ile o, Amin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 5:08pm On Sep 26, 2009
faakay:

Emi ma so wipe: Wo hen hao!
Ki ni itumo "Wo hen hao"? mo fe so si neighbour mi ni ibi yii . . . . . cool
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 5:17pm On Sep 26, 2009
tubabie:

Ki ni itumo "Wo hen hao"? mo fe so si neighbour mi ni ibi yii . . . . . cool

ni hao (chinese) - se daadaa ni (yoruba)

wo hen hao (chinese) - mo wa daadaa (yoruba)
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by tubabie(f): 5:19pm On Sep 26, 2009
oh ok, i thought it was a sort of yab i could say to someone. smiley
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Nobody: 5:20pm On Sep 26, 2009
Remii:

O daa bee, mo tie gbiyanju maa yin ara mi. Wakati meta pere ni mo lo ni papa oko ofurufu ti Hong Kong nigbati mo nkoja lo si KL ni odun melo kan sehin. Bawo ni gbogbo awon chinko ladugbo yen. Awon eniyan won yen po sha, afi bii ki afi okan se eni okan.  Ao ko ere oko de ile o, Amin.

Beni ooo! Won ti pu ju!!! Amin ooo gbogbo wa ni ama ko ere oko de ile o

tubabie:

Ki ni itumo "Wo hen hao"? mo fe so si neighbour mi ni ibi yii . . . . .  cool

Ni hao - Gbolohun lati ki eniyan/Hello, How are you

Wo hen hao - Mo wa pa /I'm fine, I'm okay, I'm very good
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by IYANGBALI: 8:04pm On Sep 26, 2009
topsy25:

Olori skempe ni iwo omo yi shocked Onisokuse si ni e pelu grin
tongue tongue tongue tongue
Remii:

@Ifeleke, ma da ara e laamu lori Iyangbali, oun ni Hugh Hafner cum Larry Flint of this trend.
@ Iyangbali, boo see nse naa ni koo maa se lo.
@Orilee9ice, sallah dun gaan ni, imagine I have gained 2kilos back in just days. lol.
ewo lo nje hugh hafner ati lary flint e jowo e ma somi loruko ti won o so mi o Olorun ni mo fi be yin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Remii(m): 9:26pm On Sep 26, 2009
IYA NGBALI:

ewo lo nje hugh hafner ati lary flint e jowo e ma somi loruko ti won o so mi o Olorun ni mo fi be yin

Iyangbali, ha ha ha ha, a so o ti e le, se bi iwo lon npariwo ado, ifaki ilawe, mo de ni wipe ki won fi e sile o fi jo awon asiwaju e ni. Hugh hafner lo ni playboy, Larry Flint lo ni Hustler, rflmao
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 10:56am On Sep 28, 2009
E kaa roo o gbogbo eyin eniyan mi re re, se alaafia ni mo baa yin o, hope di weekend was goodz.
Server waa o sise nibise leni so mon' gabdura pe ki won maa ri ojutu e titi di ago merun irole kin le maa gbadun ara mi loo lori tiredi yi jare, wink ara fee sin mi lee kan kan, and Laughter is di best medicine for "2 much work, " abi se mi o rii so eyin ara mi? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 11:01am On Sep 28, 2009
Ifeleke.oreeee miiiiii daa-daa, mo rii pe o waa lori line , see o waa paa jare ni tie, bawo ni opin ose e see loo si, mon' bo ni agbe gbe yin lai pee o, mo ni awon "tings" lati se ni adugbo agege yen, (not really agege, but you know, lol) wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Witi(m): 12:06pm On Sep 28, 2009
Orilee9ice:

Server
Yoruba: ero ti un mu ero ayara bi asa lu ja gbogbo aye.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Orilee9ice(m): 12:12pm On Sep 28, 2009
Quote from: Orilee9ice on Today at 10:56:39 AM
Server
Yoruba: ero ti un mu ero ayara bi asa lu ja gbogbo aye.
grin

Witi
E see o, e ku ile kika, olorun a fun yin see o Amin
whateva. that means ni mo mean jare, ero naa o tii sise o, boya ma maa lo'le ni ago kan, lati ago mejo ti mo ti wa nibi, wink
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by FBS: 12:31pm On Sep 28, 2009
Eyin pips! E kaa san oo! cheesy

(1) (2) (3) ... (86) (87) (88) (89) (90) (91) (92) ... (100)

Benin Art And Architecture / 20 Popular Yoruba Charms And Their Uses(With Direct English Translations) / Ònkà Yorùbá: Numbers And Numbering System In Yorùbá

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 36
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.