Welcome, Guest: Register On Nairaland / LOGIN! / Trending / Recent / New
Stats: 3,183,620 members, 7,921,321 topics. Date: Wednesday, 14 August 2024 at 11:00 PM

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! - Culture (49) - Nairaland

Nairaland Forum / Nairaland / General / Culture / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! (380066 Views)

If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here. Everybody Is Invited! / If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! / Do You Speak Yoruba? (2) (3) (4)

(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (167) (Go Down)

Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mukina2: 11:15pm On Jun 11, 2007
bawoni

ki lo seen ika around? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by nana(f): 12:12pm On Jun 12, 2007
hello
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:37pm On Jun 12, 2007
e ku ile ooo, @nana et al
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 12:42pm On Jun 12, 2007
Talo wa ninu ogba nna??
Awon omo kekere kan ni
se nwa wo won
mon wa wo won --------------
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 3:11pm On Jun 12, 2007
Ewo lewo, E kwele oo, Anything to Fenu Gbe? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 3:13pm On Jun 12, 2007
Si Mushoo,

Bawo ni, se iwo na ti ni interest si Aunty Nana ni?, Jo o So fun wa ooo, eje ka ri gbo, emi fe sare lo se road walk, ma pada wa in 1 hours time,

Baalee wa, bawo ni, abi e ti rin rin ajo lo si ilu akatapritari tabitabi ni? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:49pm On Jun 12, 2007
E ku atotonu o gbogbo eyin mutumuwa. Iyalenu nla nla lo je fun mi lati ka orisirisi ohun ti eyin ilu nso nipa baale o. E jowo ta ni o waye adagba ma labe na. Gbogbo eyin ilu n yotomi laarin ara yin , e wa ni ki baale kan ma se eto ilu lasan , to, oti da o.

Iyalode Ikamefa, ti a ba so wipe omi lo ma se eja jinna a o ni iro ni, o si tun n ji baale lese. Sebi o wa ninu aafin  nigba ti ifa so wipe arabinrin ti ko ba ti gbo ede ni ki baale fi se iyawo kekere. Ki wa lode ti o fi wa fe ma se olori alatako si mi. Oodua o fe be o. Won tile so fun mi wipe ohun fi oju di ogun baale. Kai mo danwo. Bi omode ba dari so apa, apa  a pa o!

Debosky, nigba wo lajo sapero lori oro nana, baale eleyi ki i se "agbalowomeri" o, nitori oruko Ilu yi kii se "Jontolo", Nairaland ni a mo si. Emi o gbese le Nana o. Nigba ti asiko ba pe, ti o ba wu awon alale, funra ara re ni yio fi ese rin wa si aafin o. Nitorina ma puro mo baale o, a i jebe awon igbimo le e le o kuro nilu o. Iwo ati Ayefele ni e jo n seto Nana , emi o si binu si. Sugbon emi ko ni fe ki e ti owo ala yin bepo o

Segoye, ranti wipe o ti ba ifa mule o, ma se daba lati da a ifa. Se o mo wipe iwo ni oye idile yin kan laafin mi, "Abobajiro Yoruba  of Nairaland". Emi ko ni fe ki o wu iwa ti ko ni je ki a ja ewe oye le o lori o. Oro re ati akitiyan lati gbeja mi han si mi, sugbon nibo lo ti ri 'JIGA' won so wipe o ni wa so jiga lu ese baale ti o ba gbe ese le Mukina2 Agbedo, iwo o mo idi ti won fi n pe sango lorisa ti bu ra re san woinwoin ni? Se o ro wipe ota ibon nikan ni ayeta wa fun ni? abi oro wipe ada ati obe nikan ni a n lo okigbe fun. Dakun o, bi o se n se daadaa ni ki o ma se o.

Desorlah, kini baale se fun yin o. Ti e  ba fe mo idi oro ti e ba nile lori bii ifa se so wipe ki baale gbe ese le Mukina2, ma ran awon akoda mi wa si ile yin ni owo tanmo oko pelu oko bobinibolojo ayokele ti e mo si 'stretch Limo' ki won o gbe yin wa si afin fun ipade ranpe. ki o to di igba na e tu gbogbo eru iyawo ti e ti di kiakia o grin

Ni akotan e je alagbara ninu oluwa.
Oro mi ko lopin

Baale of Yoruba Thread.
Ire
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 3:52pm On Jun 12, 2007
mishoo:

Talo wa ninu ogba nna??
Awon omo kekere kan ni
se nwa wo won
mon wa wo won --------------

Mishoo temi ni kan soso, jowo ma wo nkan kan ninu ogba o, awon apayan ati gbomogbomo lowa nibe . Mo si ti so fun awon ode ati fijilante ilu ki won ma so inu ogba na. Enikeni ti a ba si mu ni a o fi imu re danrin. Emi ko ni fe ki ore baale tooto je iya ti ko mowo mese o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:51pm On Jun 12, 2007
richylaw:

Mishoo temi ni kan soso, jowo ma wo nkan kan ninu ogba o, awon apayan ati gbomogbomo lowa nibe . Mo si ti so fun awon ode ati fijilante ilu ki won ma so inu ogba na. Enikeni ti a ba si mu ni a o fi imu re danrin. Emi ko ni fe ki ore baale tooto je iya ti ko mowo mese o.
Howu, baale!! enikan o ki je ki ile o fe oo. omode gbon agba si gbon ni a fi da ile ife. Ti e ba nje, e ma fun ore yin ti e pe mi na je diedie sa. Mo kan ni ki n yoju wo inu ogba boya mo le ri nkan mu nibe ni, ki awon segoye,ikomi ati debosky to ma bere sini pe mi ni gbomogbomo.
emi ki gbe omo oo. Agbalagba ni mo ma ngbe. Sugbon mo mon iwa ara mi, mi o je koja aye mi ni ibi ti baale ba wa.
Ire oooo.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by mishoo(m): 4:55pm On Jun 12, 2007
segoye2:

Si Mushoo,

Bawo ni, se iwo na ti ni interest si Aunty Nana ni?, Jo o So fun wa ooo, eje ka ri gbo, emi fe sare lo se road walk, ma pada wa in 1 hours time,


Ogbeni segoye, eewo ti ni tiyin gaan na?? Won o sa ti fun yin ni nana patapata. E maa nbe saa. ksi eni to mo oko iyawo oju ona ooo. Ki e lo fi edo le ori orooro!!
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 5:18pm On Jun 12, 2007
Eku ile o, e si ku dede asiko yi, se daada ni mo ba onikuluku yin.

Baale mo kiyin o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:38pm On Jun 12, 2007
baale omidan desorlah yii o dara gaan fun igbesele oun gan ti fara mo. ko si idi kan kan lati gbese le mukinatu mo, nitori desorlah yii o da mo gaan, Baale wa yio si gbadun re daa daa. nkan ti iyewo wa so fun wa ni yen oh. grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 5:44pm On Jun 12, 2007
Ikemefa bawo ni? A de gburo ee mo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 5:49pm On Jun 12, 2007
si Desorlah,

Kabo, se daada lo de, mo tin reti re ooo, oti e le bere mi tabi ki otile kimi, odaa ooo.

Si Baale,

E seun fun oye yen ti e bu fun mi ooo (Abobajiro Yoruba  of Nairaland), I nu mi dun lopo lopo, ko da, e ni lati se eto fun mi lati se ayeye and ajodun oye owun. Atiwipe, se emi na le ma gbese le awon babes ti o wa ni ihayi.

Baalee ooo, eyin na e ranti wipe e ti ba ifa mule o, ma se daba lati da a ifa.  So e jo, e ja  ewe oye le mi lori o.

Bawo ni ese ri iyawo mi tuntun? grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 5:50pm On Jun 12, 2007
richylaw:


Iyalode Ikamefa, ti a ba so wipe omi lo ma se eja jinna a o ni iro ni, o si tun n ji baale lese. Sebi o wa ninu aafin nigba ti ifa so wipe arabinrin ti ko ba ti gbo ede ni ki baale fi se iyawo kekere. Ki wa lode ti o fi wa fe ma se olori alatako si mi. Oodua o fe be o. Won tile so fun mi wipe ohun fi oju di ogun baale. Kai mo danwo. Bi omode ba dari so apa, apa a pa o!





mo sebi baale ti ni awon iyawo to kun afin? undecided ki ni baale tun se ojukokoro si arabinrin mukinatu si?
o yee ki awofa yin tun ifa e da oh, o da mi loju wipe o ti si ifa yen da cheesy
oruko muki ko yo ninu odu ifa yen lojo naa lohun grin
Baale emi kii se alatako yin oh grin sugbon e fe maa be bii oya, mo ba ni kin fa yin wale ni oh
cheesy
aigbedo a kii rii baale fin oh grin but ti baale ba lo n gbemun grin awa de maa n fo imun oh
grin


baale arabinrin desolarh naa dara pupo e le gbese le oun naa se e gbo?
cheesy e fi owo wonu oh cheesy



Ikomi:

Ikemefa bawo ni? A de gburo ee mo?

ikomi ewo lo se? cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 5:52pm On Jun 12, 2007
@ Ikamefa

Tiee ni mo shee oooh. Se ka jade la leii?

@ Segoye

Baba sego kilo n happen.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 5:53pm On Jun 12, 2007
oloye segeoye oye a mori o!

bawo ni oro eto ajodun se nlo/ a gbodo pa maalu meje ati ewure mesan lati se ayeye yii bio se ye tongue

aunti Ika si mo iyan gun daa daa ati sise efo riro ati elegusi. mo si mo aboki kan ti on ta maalu ni orile oma fun wa ni discount lori maalu yen

e ba Baale soro ki won gbe owo jade oh
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 5:55pm On Jun 12, 2007
debosky:

oloye segeoye oye a mori o!

bawo ni oro eto ajodun se nlo/ a gbodo pa maalu meje ati ewure mesan lati se ayeye yii bio se ye tongue

aunti Ika si mo iyan gun daa daa ati sise efo riro ati elegusi. mo si mo aboki kan ti on ta maalu ni orile oma fun wa ni discount lori maalu yen

e ba Baale soro ki won gbe owo jade oh

Wa de ma kpe everybody ni aunti elegbe man yio. Sego abo so fun ni?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 5:56pm On Jun 12, 2007
eku rubbish
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 5:59pm On Jun 12, 2007
Ikomi:

@ Ikamefa

Tiee ni mo shee oooh. Se ka jade la leii?

@ Segoye

Baba sego kilo n happen.

ha ha cheesy jade lo si ibo? undecided tongue heaven? grin


debosky:

oloye segeoye oye a mori o!

bawo ni oro eto ajodun se nlo/ a gbodo pa maalu meje ati ewure mesan lati se ayeye yii bio se ye tongue

aunti Ika si mo iyan gun daa daa ati sise efo riro ati elegusi. mo si mo aboki kan ti on ta maalu ni orile oma fun wa ni discount lori maalu yen

e ba Baale soro ki won gbe owo jade oh

bawo ni ti ika6 ninu ounje sise? undecided nigbati oloye titun ti ni iyawo

ewo ni ti temi nibe? undecided o ye kii iyawo titun se ounje ki awa si gbe enu wa ,wa jeun ni grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 6:01pm On Jun 12, 2007
ikamefa:

ha ha cheesy jade lo si ibo? undecided tongue heaven? grin

To ba ma jade wa soo, to ba de ni jade wa dee so, ma mu mi sere. Ka kon sere looo. lol
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by debosky(m): 6:02pm On Jun 12, 2007
ooto ni e so anti mi, sugbon ounje ti eyin ba se omaan dun gaaan, mo fe ki iyawo oloye titun wa kose lowo yin ni

kio ma lo fi ebi pa oloye ni le cheesy

omo ibo fi anti mi sile oh, lo wa awon omo ibo iru e ni ibo mii so gbo?
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by kateflow(f): 6:17pm On Jun 12, 2007
wat dey shele
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 6:22pm On Jun 12, 2007
kateflow:

what dey shele

Kate bawo lowo eeee. Maje ki Ikamefa mo wipe mo ba eeee soro ooohhh. Cos alueee kpa
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by ikamefa(f): 6:24pm On Jun 12, 2007
Ikomi:

Kate bawo lowo eeee. Maje ki Ikamefa mo wipe mo ba eeee soro ooohhh. Cos alueee kpa



" grin " funny! cheesy
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by Ikomi(m): 6:27pm On Jun 12, 2007
Ikamefa ma fi mi rerin ooh. mio fe arifin.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 6:45pm On Jun 12, 2007
segoye2:

si Desorlah,

Kabo, se daada lo de, mo tin reti re ooo, oti e le bere mi tabi ki otile kimi, odaa ooo.

Si Baale,

E seun fun oye yen ti e bu fun mi ooo (Abobajiro Yoruba of Nairaland), I nu mi dun lopo lopo, ko da, e ni lati se eto fun mi lati se ayeye and ajodun oye owun. Atiwipe, se emi na le ma gbese le awon babes ti o wa ni ihayi.

Baalee ooo, eyin na e ranti wipe e ti ba ifa mule o, ma se daba lati da a ifa. So e jo, e ja ewe oye le mi lori o.

Bawo ni ese ri iyawo mi tuntun? grin

Ma binu simi o, a de ku ti oye yi o, oye a mori o.

ikamefa:


baale arabinrin desolarh naa dara pupo e le gbese le oun naa se e gbo?
cheesy e fi owo wonu oh cheesy



Eewo ni temi, ki baale wa iyawo tire si iwaju o.
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 7:10pm On Jun 12, 2007
Iyawo mi, o seun ooo, oku ito ju mi ooo, je ka jo soro base ma se se ayeye owun ati wipe, eyin eyan wa, a o fun yin ni abo ipade idile ti a ba se ooo,

E seun oooo,

Emi ni ore yin ati oloye,

Abobajiro Yoruba of Nairaland
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by desorlah(f): 7:19pm On Jun 12, 2007
Eyin eyan wa, e ku oju lona ayeye na o. Ao ni fi enikeni se awati ninu wa o, Aatun ma soro later, odabo niyen
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by marthafor2: 9:05pm On Jun 12, 2007
Iyawo elese bata grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by segoye2(m): 9:19pm On Jun 12, 2007
Iyawo mi, joo bami soro lori segoye2@itsabove.com

Eyin Eyan mi, a de ma soro ti oba ya, Baale e seun wa ooo, Iyawo mi ti soro tan, ti a ba soro wa tan, a o kan si yin, eku ojulona ojo ayeye na, a o fi to yin leti ojo ti a mu, a o ni fi enikeni wa se awati ooo, Ire na a kari wa ooooo, ife ti eni si mi ati iyawo mi ko ni tan oooo,

Nigbati baale yio gbesele gbogbo awon obirin ti o wa ni bi, yio se oju emi wa ooo, Amin! grin
Re: If You Can Speak Yoruba, Talk It In Here! by richylaw(m): 10:02pm On Jun 12, 2007
Gege bi e ti mo wipe baale kii se olojukokoro. Emi ki gbese le eniti ko ba ye ki n gbese le o. eyi ti o fe sele yi, ifa lo wibe o. iyawo kii po ju fun baba laafin o
lekan si mo ki gbgbo wa ku oju lona iwuye segoye , oloye mi titun o. Bi ojo oye yii ba se ri ni a o se mo boya o ye ki a fun iyawo re desorlah na loye o.
ire o

(1) (2) (3) ... (46) (47) (48) (49) (50) (51) (52) ... (167)

Pictures Of Nigeria Traditional Attire / Igbo Names & Their Meanings / Igbo Kwenu ! Kwenu Kwezo Nu ! Join Us If You Proud To Be An Igbo Guy/lady

(Go Up)

Sections: politics (1) business autos (1) jobs (1) career education (1) romance computers phones travel sports fashion health
religion celebs tv-movies music-radio literature webmasters programming techmarket

Links: (1) (2) (3) (4) (5) (6) (7) (8) (9) (10)

Nairaland - Copyright © 2005 - 2024 Oluwaseun Osewa. All rights reserved. See How To Advertise. 47
Disclaimer: Every Nairaland member is solely responsible for anything that he/she posts or uploads on Nairaland.